sábado, 18 de fevereiro de 2012

Aulas de yorùbá com o Olùkó José Benedito

Olùkó Orlandes rosa


Aulas de yorubá com Olùkó José Benedito
Começar a seguir o Olùkọ́ José Benedito
http://profjosebenedito.blogspot.com/

Relacionado



1. Àwọn ọ̀rọ̀ míì tí ìtumọ̀ wọn jọra pẹ̀lú ọ̀rọ̀ ìṣe - Outras palavras que têm um significado semelhante ao verbo.
2. Àwọn ọ̀rọ̀ tó tan mọ́ ọn - Palavras relacionadas.
3. Àwọn ọ̀rọ̀ míì tó ní í ṣe pẹ̀lú ọ̀rọ̀ tó túmọ̀ sí “amọ̀kòkò” - Outras palavras relacionadas com a palavra "oleiro".

Sensação.


Ìmọ̀lára (sensação, emoção, percepção).

Resultado de imagem para sensação

Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).

Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).

Ìmọ̀lára pé nǹkan kanni lára lọ́nà tó gbádùn mọ́ni, s. Sensação tátil de forma agradável,  sensação de prazer. Wọ́n ṣàkíyèsí pé, ohun tó ń fa irú ìmọ̀lára pé nǹkan kanni lára lọ́nà tó gbádùn mọ́ni yìí ni àkójọpọ̀ iṣan oríṣi kejì tó wà nínú awọ ara wa, èyí tí àwọn fọ́nrán iṣan àkànṣe kan wà nínú rẹ̀ - Essa sensação de prazer, segundo eles, era causada por uma segunda rede de nervos na pele, que consiste de fibras de lenta condução chamadas fibras C táteis.
Èrò pé ‘kò sóhun tó lè ṣe mi, s. Sensação de invulnerabilidade. Èrò pé ‘kò sóhun tó lè ṣe mi’ yìí wọ́pọ̀ láàárín àwọn èwe gan-an - Essa sensação de ‘invulnerabilidade’ é muito comum nos adolescentes.
Àròdùn ọ̀hún ò lọ, s. Sensação de mal-estar. Mo wá bẹ̀rẹ̀ sí fi taratara kópa nínú iṣẹ́ ìwàásù, àmọ́ àròdùn ọ̀hún ò lọ - Aumentei meus esforços na pregação, mas a sensação de mal-estar continuou.
Ọkàn mi balẹ̀ ní gbogbo ìgbà, s.  Sensação de segurança. Ìyẹn sì máa ń jẹ́ kí ọkàn mi balẹ̀ ní gbogbo ìgbà - Isso me dava uma sensação de segurança.
Ìbàlẹ̀-ọkàn, Ìbàlẹ̀-àyà, s.  Paz de espírito,  paz da mente, sensação de paz, serenidade.
Ìwà ẹ̀dá mu pé kó o banú jẹ́, kó o sì ní ẹ̀dùn ọkàn, s. Comportamento natural que faz você se sentir magoado e deprimido. Báwọn òbí ẹ bá kọra wọn sílẹ̀ tàbí tí ọ̀kan lára wọn bá ṣàìsí, ó bá ìwà ẹ̀dá mu pé kó o banú jẹ́, kó o sì ní ẹ̀dùn ọkàn - É natural ficar triste ou ter a sensação de perda caso seus pais tenham se divorciado ou um deles tenha morrido.
Àárẹ̀ tẹ̀mí, s. Sensação de fadiga emocional ou espiritual. Bákan náà ni ṣíṣe àwọn ìgbòkègbodò tẹ̀mí déédéé lè ṣèrànwọ́ láti dín àárẹ̀ tẹ̀mí kù -De modo similar, atividades espirituais regulares podem ajudar a reduzir qualquer sensação de fadiga emocional ou espiritual.

Banheiro

Ilétọ̀, ilé ìwẹ̀, balùwẹ̀ (banheiro)

Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).


Àpò tó kó ìgbẹ́, s. Bolsa de fezes, bolsa de colostomia.

Imí, ìgbẹ́, ìgbọ̀nsẹ̀, s. Estrume, excremento, esterco, fezes.
Oògùn apakòkòrò, s. Desinfetante.
Ilé ìgbọ̀nsẹ̀, ibi ìgbọ̀nsẹ̀s. Sanitário.
Ilé ìgbọ̀nsẹ̀, ilé ìyàgbẹ́, inú ilé ìgbọ̀nsẹ̀, ṣáláńgá, s.  Vaso sanitário.
Ṣáláńgá, s. Vaso sanitário, latrina (do hauçá sálgá).
Ṣáláńgá ló yẹ ká máa ṣe ìgbọ̀nsẹ̀ sí, s. Fossa séptica para o excremento humano.
Ibikíbi táwọn èèyàn bá ti ń ṣe ìgbọ̀nsẹ̀, s. Local de defecação.
Kọ́bọ́ọ̀dù ìkó-nǹkan-sí, s. Armário de pia.
Ẹnu ẹ̀rọ, ẹ̀rọ omis. Torneira. Tún ẹnu ẹ̀rọ tó bá ń jò ṣe - Conserte torneiras que estão vazando.
Ọpọ́n ìfọwọ́, s. Pia, lavatório.
Ọ̀ṣọ̀rọ̀, ọ̀ṣọ̀ọ̀rọ̀, s. Cascata, cachoeira, goteiras que caem do telhado, cano colocado no canto do telhado para colher a água da chuva, chuveiro.
Òjò, ọ̀wààrà-òjò, ọwọ́ òjò, s. Chuveiro (chuva súbita, abundante e passageira, pancadas de chuva).
Ilé ìwẹ̀, s. Casa de banho.
Ibi ìwẹ̀, s. Local de banho.
Dígí, àwòjíìji, s. Espelho.
Búrọ́ọ̀ṣì ìfọnu, búrọ́ọ̀ṣì ìfọyín, s. Escova de dente.
Bébà anùdọ̀tí, bébà ìnùdí, s. Papel higiênico.
Ọṣẹ, s. Sabonete.
Omi ọṣẹ, s. Sabão líquido.
Aṣọ ìnura, s. Toalha.
Kóòmù ìyarun, kóòmù, s. Pente.
Ọṣẹ ìfọyín, s. Pasta de dente, creme dental. 
Okùn ìfọyín, s. Fio dental. 
Ìnulẹ̀, s. Rodo.
Egbògi ìdíwọ́ bíbàjẹ́ nkanàpaàgùn ti ẹnu, s. Anti-séptico bucal.
Ààtàn, s. Lixo, pilha de estrume, montão de lixo.
Àkìtàn, àtìtàn, s. Refugo, lixo.
Ìdọ̀tí, s. Sujeira.
Lọ́fínńdà, s. Perfume.
Òórùn dídùn tó máa ń bo àágùn mọ́lẹ̀, s. Desodorante.
Ohun ìṣojúlóge, s. Maquiagem.
Ìfárùngbọ̀n tí ń lo iná mànàmáná, s. Barbeador elétrico.
Ìpara, s. Creme.
Ọpọ́n ìwẹ̀, s. Banheira.