Èmi kì í ṣe àlàáfíà
Eu não sou da paz.
Àwọn gbólóhùn (frases)
1. Mi ò ní àlàáfíà - Eu não tenho paz.
2. “Mi ò ń ṣe sùẹ̀gbẹ̀ o!” - “Eu não sou medroso!”
3. N kì í ṣe ọ̀kan lára ẹ̀yin Ẹlẹ́rìí Jèhófà - Eu não sou Testemunha de Jeová.
4. Mi ò kì í ṣe èèyàn burúkú; bẹ́ẹ̀ ni mi ò sì dára ju àwọn èèyàn tó kù lọ - Eu não sou uma pessoa má, tampouco alguém especial.
4."Èmi Jèhófà ha kọ́ ni?” - ”Não sou eu, Jeová?”
5. Ó ṣeé ṣe kó o sọ pé, ‘Àmọ́ èmi kì í ṣe wòlíì!’ - Talvez diga: ‘Mas eu não sou profeta!’
6. Èmi kì í ṣe ẹni tí ń sọ̀rọ̀ lọ́nà tí ó já geere - Eu não sou orador fluente.
7. “Kí ló dé, ó yẹ kẹ́ ẹ ti mọ̀ pé mi ò ní báa yín dá sírú nǹkan bẹ́ẹ̀ yẹn!” - “Vamos lá, você sabe que eu não sou disso!”