Àdúgbò táwọn akúṣẹ̀ẹ́ nínú Olúìlú Paris (Fránsì).
Favela dentro de Paris (França).
A favela de Ney, nos arredores de Paris ERIC HADJ
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário).
Ghẹto, s. Gueto, subúrbio, favela, periferia, bairro de minorias raciais, bairro de minorias sociais, bairro judeu.
Etílé, s. Periferia de uma cidade, arredores, circunferência, vizinhança, perímetro urbano, contorno.
Agbègbè, s. Arredores, periferia, subúrbio, cercanias.
Ilé akúṣẹ̀ẹ́, ilé ebútú, àwọn ilé àbẹ̀rẹ̀wọ̀ táwọn èèyàn kọ́ síbi tí ìjọba ò fọwọ́ sí, àdúgbò játijàti, àgọ́ àwọn tálákà, àdúgbò táwọn akúṣẹ̀ẹ́, àwọn àdúgbò tí kò bójú mu rárá, ilé jákujàku, s. Favela. Conjunto de moradias populares que, construídas a partir da utilização de materiais diversos, se localizam, normalmente, nas encostas dos morros. Wọ́n ṣírò rẹ̀ pé àwọn tó ń gbé láwọn ilé akúṣẹ̀ẹ́ jákèjádò ayé ju bílíọ̀nù kan lọ - Estima-se que mais de 1 bilhão de pessoas em todo o mundo vivam em favelas.
Àdúgbò táwọn akúṣẹ̀ẹ́, s. Favela. Ọ̀pọ̀ èèyàn ló jẹ́ pé àwọn ilé kẹ́jẹ́bú ni wọ́n ń gbé láwọn àdúgbò táwọn akúṣẹ̀ẹ́ pọ̀ sí táwọn ilé tó wà níbẹ̀ kò sì bójú mu rárá - Muitas têm de se contentar com moradias improvisadas em cortiços ou em favelas urbanas.
Àwọn ilé táwọn èèyàn ti pa tì, s. Casas abandonadas, prédios abandonados.
Nínú, prep. Dentro, no interior de.
Ní, prep. No, na, em.
Parisi, Olúìlú Paris, s. Paris.
Olúìlú, s. Capital.
Ilẹ̀ Faransé Olómìnira, s. República francesa.
Fránsì, s. França.

Nenhum comentário:
Postar um comentário