Àwọn ìròyìn bíi pípa odindi ẹ̀yà run, ìkórìíra kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà, ìwà ìkà sí ìran ènìyàn àti ìròyìn àwọn apániláyà.
Notícias como limpeza étnica, ódio racial, crime contra a humanidade e terrorismo.
Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações:
https://www.youtube.com/watch?v=wnhg1LbUwmU&t=13s
https://g1.globo.com/rj/rio-de-janeiro/noticia/2022/01/31/morador-jacarezinho-denunciou-tortura-ameaca-pms-bope-reconhecer-autores.ghtml
https://www.metropoles.com/brasil/rj-jovem-denuncia-tortura-e-ameaca-por-pms-no-jacarezinho
Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò, àkójọ ọ̀rọ̀ tí ò ń lò lójoojúmọ́, àwọn àkànlò ọ̀rọ̀, àwọn àkànlò èdè, ọ̀rọ̀ tó máa ń sọ, àkànlò èdè lọ́nà tó gún régé (vocabulário).
Nwọ́n, pron. pess. Eles, elas. Expressa uma ação que não é creditada a nenhuma pessoa em particular.
Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; neste caso, é posicionado antes do substantivo.
Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.
Wọn, pron. poss. Deles, delas.
Ìjọba Násì òun ìjọba Aláṣẹ Oníkùmọ̀ tó jẹ́ òǹrorò, s. Regime nazifascista.
Ìṣìkàpa ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ àwọn aráàlú láti ọwọ́ àwọn ìjọba tiwọn fúnra wọn, s. Genocídio de seus cidadãos praticados pelos governos.
Ìkórìíra kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà, s. Ódio racial.
Ìwà ìkà sí ìran ènìyàn, ẹ̀ṣẹ̀ sí aráyé, s. Crime contra a humanidade.
Ilé-Ẹjọ́ Ìwàọ̀daràn Káríayé, s. Tribunal Penal Internacional
Ìran aláwọ̀ funfun lọ̀gá, s. Supremacia branca.
Àwọn afáríkodoro, s. Skinheads.
Ọmọlẹ́hìn Bolsonaro, s. Bolsomínion, seguidor de Bolsonaro, eleitor de bolsonaro. Sujeito burro, ignorante, mal intencionado, autoritário, extremista, preconceituoso, homofóbico, misógino, racista, xenofóbico e que faz discurso de ódio contra minorias na internet. É apoiador de torturadores, de ditadores e ditaduras militares. A maioria deles acredita que hidroxicloroquina e uso de ozônio pelo ânus pode curar paciente com Covid-19. Também acredita na terra plana, no geocentrismo e no cristonazifascismo.
Ìwé-ìròyìn, s. Jornal.
Ìròyìn, ìròìn, s. Notícias, reportagens.
Ròyìn, v. Noticiar, relatar.
Ìròyìn Orí Tẹlifíṣọ̀n, s. Telejornal.
Pípa ẹ̀yà ìran run, pípa ìran run, pípa odindi ẹ̀yà run, s. Limpeza étnica, genocídio.
Gẹ́gẹ́ bí, conj. De acordo com, assim, exatamente.
Bí, prep. Como, da mesma forma que.
Bí ...bá ti, adv. Tanto tempo quanto, como, quando.
Bí... bá, v. aux. Expressa uma condição indefinida.
Bí, v. Perguntar, indagar de alguém, comunicar. Também usado para formar frases interrogativas; nesse caso, é posicionado no fim da frase. Entregar, distribuir. Gerar, dar nascimento a. Estar zangado, aborrecer.
Bí, conj. v. aux. Se. Indica uma condição
Àti, Conj. E. Usada entre dois nomes, mas não liga verbos.
Sì, ( conj. pré-v.). E, além disso, também. Liga sentenças, porém, não liga substantivos; nesse caso, usar " àti". É posicionado depois do sujeito e antes do verbo.
Ti, àti, conj. E.
Pẹ̀lú, Conj. E.
Òun, on, conj. E. Geralmente usada com nomes de pessoas.
Àwùjọ apániláyà, ẹgbẹ́ àwọn apániláyà, àwùjọ àwọn apániláyà , s. Grupo terrorista, organização terrorista.
Apániláyà, s. Terrorista.
Ìpániláyà, s. Terrorismo.
Ìwà ìpániláyà tó kárí ayé lọ, s. Terrorismo internacional, terrorismo global.
Ìṣòro ìwà ìpániláyà, s. Problema de terrorismo.
Ohun tó gbàfiyèsí nínú ọ̀ràn ìpániláyà jákèjádò ayé, s. Atos espetaculares de terrorismo no mundo inteiro.
Àìráragba-nǹkan-sí, s. Intolerância.
Ìjà ẹ̀yà, s. Violência étnica.
Ìpẹ̀yàrun, ìpakúpa, s. Genocídio, holocausto.
Ìṣẹ̀lẹ̀ ìdánilóró, s. Atentado terrorista.
Ìgbòkègbodò ẹgbẹ́ àwọn aṣòdì sí ìjọba aláṣẹ oníkùmọ̀, s. Antifa. O movimento Antifa é uma conglomeração de grupos de esquerda. A principal característica dos grupos antifa é a sua oposição ao fascismo por quaisquer meios necessários. Eles atuam com táticas de militância em protestos expondo identidades de nazistas e fascistas e realizam manifestações contra a extrema-direita.
Aṣòdì sí ìjọba aláṣẹ oníkùmọ̀, s. Antifascista.
Tó lòdì sí ìjọba aláṣẹ oníkùmọ̀, adj. Antifascista.
Ìmúnisìn tipátipá, ìjọba ìmúnisìn tipátipá, s. Totalitarismo (hitlerismo, fascismo, nazismo, nacional-socialismo).
Ètò ìjọba Násì, s. Nazismo.
Ẹgbẹ́ násì, s. Partido nazista.
Ẹgbẹ́ aláṣẹ bóofẹ́bóokọ̀, s. Partido de extrema direita.
Ẹgbẹ́ àwọn Òṣìṣẹ́ Sósíálístì Tọmọorílẹ̀-èdè Jẹ́mánì, s. Partido Nacional Socialista dos Trabalhadores Alemães.
Ẹgbẹ́ ìmùlẹ̀ Ku Klux Klan, s. Ku Klux Klan.
Onípadà-sẹ́hìn, aládẹ̀hìnbọ̀, olùpadà-sẹ́hìn, konsafetifu, s. Reacionário, conservador.
Ìjọba ológun, s. Governo militar.
Àgọ́ ìṣẹ́niníṣẹ̀ẹ́ Násì, s. Campo de concentração nazista.
Ọ̀dáràn, apànìà, apani, s. Criminoso, assassino, malfeitor, culpado, matador.
Ìkóríra, ìkórìíra, s. Ódio.
Ìṣojúsàájú, s. Parcialidade, favoritismo, xenofobia.
Ìṣẹlẹyàmẹyà, s. Racismo.
Kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà, adj. Racista.
Ajàfẹ́tọ̀ọ́-ọmọnìyàn lórí ọ̀ràn ìṣèlú, s. Ativista político.
Ọ̀rọ̀àbá, s. Ideologia.
Ìjọba, s. Governo, reino.
Elérò ẹ̀yà-tèmi-lọ̀gá, elérò igbagbọ ẹ̀yà-ìran-tèmi-lọ̀gá, aláìfẹ́irúẹ̀dáọmọẹnìkéjì, s. Racista.
Ilẹ̀ àwọn òkú tó ṣókùnkùn biribiri, s. Submundo escuro.
Ayé àwọn òkú wà, níbi tí àwọn òǹrorò abàmì ẹ̀dá lónírúurú ń gbé, òmíràn á rí bí ènìyàn, òmíràn á dà bí ẹranko, s. Submundo aterrorizante, habitado por monstros hediondos em formas humanas ou animais.
Àwọn ohun akójìnnìjìnnì-báni, s. Coisas aterrorizantes.
Àwọn alákitiyan násì, s. Nazistas.
Àwọn aláṣẹ násì, s. Autoridades nazistas.
Ẹnì kan tó bá gba ilẹ̀-ayé títẹ́ pẹrẹsẹ gbọ́, ẹnì kan tó máa ń sọ nípa ilẹ̀-ayé títẹ́ pẹrẹsẹ: terraplanista, s. Terraplanista. Pseudointelectual que acredita ou defende que o planeta Terra é plano.
Tó ń gba ilẹ̀-ayé títẹ́ pẹrẹsẹ gbọ́, tó máa ń sọ nípa ilẹ̀-ayé títẹ́ pẹrẹsẹ, adj. Terraplanista.
Ilẹ̀ ayé tẹ́ pẹrẹsẹ, ilẹ̀ ayé títẹ́jú pẹrẹsẹ, ilẹ̀ ayé títẹ́ pẹrẹsẹ, ilẹ̀-ayé títẹ́ pẹrẹsẹ, s. Terra plana.
Ilé-ẹjọ́ Gígajùlọ, s. Supremo Tribunal Federal, corte suprema, suprema corte, supremo tribunal.
Dẹ́rùbà, v. Amedrontar, assustar, apavorar, intimidar, aterrorizar, atemorizar, assombrar, acobardar, aterrar, espavorir, terrificar.
Dẹ́rù, v. Causar medo, alarmar.
Dẹ́rùsílẹ̀, v. Causar pânico, alarmar.
Ìbẹ̀rù, s. Medo, pusilanimidade, fraqueza.
Ẹlẹ́wọ̀n olókìkí, s. Prisioneiro famoso. Wọ́n pe Bárábà ní “ẹlẹ́wọ̀n olókìkí burúkú” àti “ọlọ́ṣà” - Barrabás é descrito como “preso notório” e “salteador”.
Àrúfín, s. Prisioneiro, criminoso, transgressor,
Ọ̀dáràn, apànìà, apani, s. Criminoso, assassino, malfeitor, culpado, matador.
Tàkúté, s. Armadilha de metal para pegar roedores.
Panpẹ́, pawọ́pẹ́, pakuté, s. Algemas.
Okùn-dídẹ, s. Armadilha, cilada, arapuca.
So pọ̀, dì lókùn, so lókùn, dè lókùn, so; dì mú, bù so, gbá mú, v. Prender.
Mú, v. Capturar, agarrar. Ser afiado. Ser severo. Tomar, pegar coisas leves e abstratas.
Ghẹto, s. Gueto, subúrbio, favela, periferia, bairro de minorias raciais, bairro de minorias sociais, bairro judeu.
Etílé, s. Periferia de uma cidade, arredores, circunferência, vizinhança, perímetro urbano, contorno.
Agbègbè, s. Arredores, periferia, subúrbio, cercanias.
Àgọ́ àwọn tálákà, àdúgbò táwọn akúṣẹ̀ẹ́, àwọn àdúgbò tí kò bójú mu rárá, àwọn ilé àbẹ̀rẹ̀wọ̀ táwọn èèyàn kọ́ síbi tí ìjọba ò fọwọ́ sí, àwọn Ilé akúṣẹ̀ẹ́, àdúgbò àwọn akúṣẹ̀ẹ́, s. Favela. Conjunto de moradias populares que, construídas a partir da utilização de materiais diversos, se localizam, normalmente, nas encostas dos morros. Wọ́n ṣírò rẹ̀ pé àwọn tó ń gbé láwọn ilé akúṣẹ̀ẹ́ jákèjádò ayé ju bílíọ̀nù kan lọ - Estima-se que mais de 1 bilhão de pessoas em todo o mundo vivam em favelas.
Àwọn ilé táwọn èèyàn ti pa tì, s. Casas abandonadas, prédios abandonados.