sábado, 15 de julho de 2017

Culinária

Oúnjẹ sísè  (culinária)



Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).

Ṣapala, s. Tortilha.
Ẹ̀wà, s. Feijão.
Oúnjẹ alápòpọ̀, Macarrão.
Ìrẹsì, s. Arroz.
Ata lọ, s. Pimenta-malagueta.
Sọ́sééjì, s. Linguiça.
Ẹran, s. Carne.
Bọ́tà, s. Manteiga.
Wàràkàṣì, s. Queijo.
Bisikíìtì, kúkì, s. Biscoito.
Ìṣùpọ̀ ìyẹ̀fun, s. Massa de farinha
Ìwúkàrà, s. Fermento.
Sàláàdì, s. Salada. 
Ẹjá, s. Peixe.
Ẹran, s. Carne, animal.
Ẹran sísùn, s. Carne assada.
Ẹran-àgùtàn, s. Carne de carneiro.
Ẹran gbígbẹ, s. Carne-seca, carne defumada..
Ẹran ẹlẹ́dẹ̀, s. Carne de porco.
Ẹran-gala, ẹran-àgbọ̀nrín, s. Carne de veado.
Ẹran tútù, s. Carne fresca.
Ẹran díndín, s. Carne frita.
Adìyẹ díndín, s. Frango assado.
Ẹ̀dọ̀ màlúù lọ, s. Bife de fígado.
Ànàmọ́ tó dín, s. Batata frita. 
Omi ẹran omitoro, s. Caldo de carne, molho.
Sàláàdì tí wọ́n fi tòmátì, s. Salada de Tomate.
Ọbẹ̀ àsèpọ̀, s. Sopa.
Omi ọbẹ̀ lásán, s. Molho.
Àpòpọ̀ sàláàdì, s. Salada mista.
Pankéèkì ẹlẹ́gẹ̀ẹ́, s Tapioca.
Ápù,  Maçã.
Ànàmọ́, s. Batata
Àlùbọ́sà, àlùbọ́sà láǹfàànís. Cebola.
Èso ọ̀pọ̀tọ́, s. Figo.
Èso déètì, s. Tâmaras.
Pómégíránétì, s. Romãs
Ẹ̀wà pòpòǹdó, s. Ervilha.
Apálá, s. Pepino.
Ewébẹ̀ letusi, letus, s. Alface.
Irúgbìn dílì, s. Endro.
Kọfí, s. Café.
Tíì, s. Chá preto.
Ohun mímu tí wọ́n fi kòkó ṣe, s. Bebidas achocolatadas.
Ṣokoléètì, s. Chocolate.
Èso góbà, s. Goiaba
Ọtí ẹlẹ́rìndòdò, Refrigerante.
Ṣẹ̀kẹ̀tẹ́, ọtí àgbàdo, ọtí sísè, s. Cerveja.
Ọtí èso àjàrà, wáìnì, s. Vinho. 
Ọtí funfun, s. Vinho branco. 
Ọtí pupa, s. Vinho tinto). 
Ọtí ọkà, s. Vinho feito de milho-da-guiné. 
Ọtí ọ̀dá, s. Vinho velho fermentado.
Wáìnì kíkan, s. Vinho fermentado, vinagre de vinho.
Omi èsokéso, s. Suco de frutas.
Omi àjàrà, . Suco de uva.
Omi ọsàn, s. Caldo de laranja, suco de laranja..
Oúnjẹ oní-pá-pà-pá, s. Lanches rápidos.
Búrẹ́dì tí wọ́n fi ẹran pẹ̀lú ewébẹ̀, s. Pizza.
Búrẹ́dì tí wọ́n fi ẹ̀ran há láàárín, s. Hambúrguer, sanduíche. 
Búrẹ́dì ẹlẹ́ran, s. Pastel. 
Àkàrà, s. Bolinho frito feito de pasta de feijão-fradinho. 
Àkàrà òyìnbóonje̩búrè̩dì, s. Bolacha.
Áásìkiriìmù, s. Sorvete.
Oúnjẹ dídùn, s. Doce.
Ṣingọ́ọ̀mù, s. Chiclete.
Súìtì, s. Bala (doce).
Ìpápánu eléròjà nínú, s. Tortas.
Ọbẹ̀ ẹran lílọ̀, s. Chili com carne. É um guisado picante contendo pimentas , carne (geralmente carne ) e muitas vezes Tomates e feijão . 
Ìpápánu, s. Lanche. 
Fífi oúnjẹ pamọ́ sínú agolo, s. Conservas, alimentos enlatados.
Kéèkì, àkàrà òyìnbó, s. Bolo.
Àkàrà olóyin pẹlẹbẹ, s. Bolo de mel.
Ìṣù èso àjàrà gbígbẹ ti Kiri-hárésétì, s.  Bolos de passas de Quir-Haresete.
Àwọn ohun yíyan, s. Produtos de panificação, produtos de forno, produtos assados, bolos, pães.
Ọkà sísun, s. Grãos torrados.
Pankéèkì, s. Panqueca.









Nenhum comentário:

Postar um comentário