sábado, 15 de julho de 2017

Religião

Ọjọ́ Ìfàyègba Ẹ̀sìn Mìíràn.
Dia da tolerância religiosa.




Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário). 


Táò,  ìsìn Táò, s. Tao, taoísmo.
Ìṣe Búdà, s. Budismo.
Ìṣe kọnfukiọsi, s. Confucionismo.  
Híńdù, Ìṣehíndù‎, ẹ̀sìn-ìn Híndù, s. Hinduísmo
Ìsìláàmù, ìmàle, s. Islamismo.
Ìṣekèfèrí titun, s. Neopaganismo, wicca. 
Jaini, s. Jainismo.
Ìsìn àwọn Júù, s. Judaísmo
Ìsìn Sikh, s. Siquismo.
Ṣintó, ẹ̀sìn ìbílẹ̀ Jèpánù, s. Xintoísmo.
Ṣọ́ọ̀ṣì ti pẹ́ńtíkọ́sì, ìjọ ti pẹ́ńtíkọ́sì, ilé Ọlọ́run ti pẹ́ńtíkọ́sì, s. Igreja pentecostal.
Ìjọ Ajíhìnrere, s. Igreja evangélica.
Ìjọ Kátólìkì, Ṣọ́ọ̀ṣì Kátólíìkì, s Igreja católica.
Ẹ̀sìn Kristi, ìsìn Kristi, ẹ̀sìn onígbàgbọ́, kirisẹ́ńdọ̀mù, s. Cristianismo. 
Ìṣeìjọánglíkánì, s. Anglicanismo.
Ìjọ ilẹ̀ Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì, s. Igreja anglicana.
Ìṣepurẹsibiteriani, s. Presbiterianismo.
Ṣọ́ọ̀ṣì Mẹ́tọ́díìsì, s Igreja metodista.
Ìjọ onígbàgbọ́, s. Congregação cristã.
Ṣọ́ọ̀ṣì Pùròtẹ́sítáǹtì, s. Igreja protestante. 
Ìjọ Jéésù Lótìítọ́, s. Verdadeira Igreja de Jesus.
Ìṣeìjọkríslàm, ìṣekríslàm, ìṣekrísmàle, ìṣeìjọkrísmàle, ẹ̀sìn Krístì-ìmàle, s. Crislamismo. Sincretismo do cristianismo com o islã.
Ṣọ́ọ̀ṣì Ọ́tọ́dọ́ọ̀sì ti Ìlà Oòrùn , s. Igreja ortodoxa oriental.
Baháí, s. Fé bahá'í
Ẹ̀sìn òrìṣà, s. Religião de orixá. 
Kandomblé, s. Candomblé.
Santería, s. Santeria.
Fúdù, s Vodum, vodun, voodoo ou vodu.
Ìgbàgbọ́ pé ẹ̀mí wà nínú ohun gbogbo, s. Animismo.
Ìjọsìn Sátánì, s. Satanismo.
Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà, s. Testemunhas de Jeová.
Ìjọ Jésù Krístì ti àwọn Ènìyàn Mímọ́ Ọjọ́-ìkẹ́hìn, s. Igreja de Jesus Cristo dos Santos dos Últimos Dias.
Ẹ̀sìn àgbọn, s. Religião do coco.
Àìgbọlọ́rungbọ́, àìgbà-pọ́lọ́run-wà, s. Ateísmo. 
Agbátẹrù ìgbàgbọ́ Ọlọ́run-kò-ṣeé-mọ̀, s. Agnosticismo. 
Iṣẹ́ àjẹ́, iṣẹ́ oṣó, iṣẹ́ òkùnkùn, s. Feitiçaria.
Oògùn, idán pípa, iṣẹ́ àjẹ́, s. Magia.
Ẹ̀sìn ìbílẹ̀, iṣe gba àwọn ẹ̀mí àìrí gbọ́, s. Xamanismo.
Ìbẹmìílò, ìbẹmìílò ká, s. Espiritismo.
UMBANDA, s. Umbanda. Ó ju àádọ́rin mílíọ̀nù ọmọ ilẹ̀ Bràsíl tí wọ́n sọ pé ó ń lọ́wọ́ nínú ẹ̀sìn kandomblé, Umbanda, Ṣàngó, àtàwọn ẹ̀sìn míì táwọn Adúláwọ̀ mú wọ orílẹ̀-èdè náà - Diz-se que mais de 70 milhões de brasileiros, direta ou indiretamente, estão ligados ao candomblé, umbanda, xangô e outras religiões afro-brasileiras.

Nenhum comentário:

Postar um comentário