ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ
Àṣẹ Eṣù yóò bá ọ gbé làyè.
BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ
Àṣẹ Ogún yóò bá ọ gbé làyè.
BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ
Àṣẹ Ifá yóò bá ọ gbé làyè.
BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ
Àṣẹ Ọbàtálá Ọbàtáriṣà yóò bá ọ gbé làyè.
BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ
Àṣẹ Odùdúwa yóò bá ọ gbé làyè.
BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ
Àṣẹ Ọsányìn yóò bá ọ gbé làyè.
BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ
Àṣẹ Ṣàngó yóò bá ọ gbé làyè.
BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ
Àṣẹ Ọya yóò bá ọ gbé làyè.
BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ
Àṣẹ Ọ̀ṣun yóò bá ọ gbé làyè.
BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ
Àṣẹ Ọ̀bà yóò bá ọ gbé làyè.
BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ
Àṣẹ Yemọja yóò bá ọ gbé làyè.
BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ
Àṣẹ Ọ̀ṣọọsì yóò bá ọ gbé làyè.
BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ
Àṣẹ Ológún-ẹdẹ yóò bá ọ gbé làyè.
BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ
Àṣẹ Òṣùmàrè yóò bá ọ gbé làyè.
BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ
Àṣẹ Ọmọlú yóò bá ọ gbé làyè.
BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ
Àṣẹ Ìbejì yóò bá ọ gbé làyè.
BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ
Àṣẹ Ọbalúwayé yóò bá ọ gbé làyè.
BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ
Àṣẹ Òrìṣà oko yóò bá ọ gbé làyè.
BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ
Àṣẹ Egúngún yóò bá ọ gbé làyè.
BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ
Àṣẹ Gẹ̀lẹ̀dẹ́ yóò bá ọ gbé làyè.
BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ
Àṣẹ Ìrókò yóò bá ọ gbé làyè.
BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ
Àṣẹ Orí rẹ yóò bá ọ gbé làyè.
BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ
Àṣẹ ọ̀kanlénígba imalẹ̀ yóò bá ọ gbé làyè.
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário).
1. Aṣẹ, aṣẹ o.
Assim será, assim será.
Aṣẹ, s. Força, poder, o elemento que estrutura uma sociedade, lei, ordem. Palavra usada para definir o respeito ao poder de Deus, pela crença de que é Ele que tudo permite e dá a devida aprovação.
O, part. adv. Forma frase exclamativa para ênfase. Ó ti dé o! - Ela já chegou!
2. Aṣẹ fún ọ.
Assim será para você.
Égbè, s. Coro, coral. Ajuda, apoio, parcialidade.
Fún, prep. Para, em nome de (indica uma intenção pretendida para alguém).
Ọ, pron. Você. É usado dessa forma depois de verbo ou preposição
3. Àṣẹ ọ̀kanlénígba imalẹ̀ yóò bá ọ gbé làyè.
Axé das duzentas e uma divindades vai acompanhar você por toda vida.
Ọ̀kanlénígba, num. Duzentos e um (201).
Imalẹ̀, s. Embema do culto aos ancestrais, divindade, orixá.
Yóò, adv. pré. v. Indicador de futuro numa frase afirmativa. Em outras palavras, emprega-se o futuro do presente para expressar uma ação que será executada no futuro. Outros indicadores de futuro: yóó, ó, á, máa, fẹ́.
Bá, v. Acompanhar, ajudar. Alcançar, ultrapassar, perseguir. Encontrar., atingir.
Gbé, v. Carregar, levantar, erguer, morar, viver).
Láyè, láàyè, adj. Vivo.
Àyè, s. O fato de estar vivo.
Ìyè, ẹ̀mí, wíwà láàyè: ìgbésí ayé, ayé, s. Vida.
Wíwà. s. Estado de ser , de existir.
4. Àṣẹ Orí rẹ yóò bá ọ gbé làyè.
O axé do seu Orí vai acompanhar você por toda a vida.
Orí, s. Cabeça.
Rẹ, ẹ, pron. poss. Seu, sua, de você. É posicionado depois de substantivo.
Àkójọ àwọn ìwé ti wádìí lẹ́nu (lista de livros pesquisados, bibliografia)
SÀLÁMÌ, Sikiru.
Cânticos dos Orixás na África/ Sikiru Sàlámì King. São Paulo: Oduduwa, 1992.
BENISTE, José.
Dicionário yorubá-português/ José Beniste. - Rio de Janeiro: Bertrand Brasil, 2011.