sexta-feira, 10 de março de 2017

Ecossexualidade

Ìbálòpọ̀ pẹ̀lú yèyé ìṣẹ̀dá tàbí àràmàǹdà obìnrin náà. 
Ecossexualidade (relação sexual com a mãe natureza).


Resultado de imagem para Ecossexual


Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò, àkójọ ọ̀rọ̀ tí ò ń lò lójoojúmọ́, àwọn àkànlò ọ̀rọ̀, àwọn àkànlò èdè, ọ̀rọ̀ tó máa ń sọ, àkànlò èdè lọ́nà tó gún régé (vocabulário).


 Àbáṣe, ìbáṣe (cooperação, apoio, assistência, relação sexual com uma mulher), ìfẹ́ ìbálòpọ̀ sókè (excitação sexual), ẹni tó nífẹ̀ẹ́ sí bíbá ọkùnrin àti obìnrin lò pọ̀ (aquele que tem  atração ou interesse sexual pelos dois sexos), ìbálòpọ̀, ẹ̀yà abo àti akọ, ẹ̀ya obìnrin àti ọkùnrin, ìbádàpọ̀, takọtabo, ìbálòpọ̀ takọtabo (sexo), iṣẹ́ aṣẹ́wó mímọ́ (prostituição sagrada), ìwà bíbá ọmọdé ṣèṣekúṣe (pedofilia), yíyan ọmọdé láàyò fún ìbálòpọ̀ (interesse mórbido pelas crianças), ìgbégbòdì ìbálòpọ̀ nínú èyí tí ó jẹ́ pé àwọn ọmọdé ni a yàn láàyò (perversão sexual em relação às crianças), ìwà bíbá ẹranko ṣèṣekúṣe (zoofilia), ìwà bíbá adìyẹ ṣèṣekúṣe (zoofilia com galinhas), ẹni tó máa ń bá yèyé ìṣẹ̀dá tàbí àràmàǹdà obìnrin náà lò pọ̀ (ecossexual, aquele que faz sexo com a mãe natureza).


Nenhum comentário:

Postar um comentário