Ṣọ́ọ̀ṣì Ńlá ti Pétérù Mímọ́ ní Róòmù.
Basílica de São Pedro, em Roma.
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário).
Ṣọ́ọ̀ṣì, ilé Ọlọ́run, s. Igreja.
Tóbi, ńlá, adj. Grande.
Tóbi, v. Ser grande.
Pọ̀, adj. Cheio, farto, barato, comum, grande.
Gbórín, v. Ser grande, largo, amplo.
Mímọ́, adj. Limpo, puro, íntegro, sagrado.
Róòmù, s. Roma.
Ìsìn Àwọn Afìyàjẹra-ẹni, s. Irmandade dos Flagelantes.
Ilé Ẹ̀kọ́ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìṣàkóso Ọlọ́run, s. Escola do Ministério Teocrático.
Ara ẹgbẹ́ àwọn ará onífẹ̀ẹ́, s. Irmandade amorosa.
Wúńdíá Onílẹ̀kẹ̀ Àdúrà, s. Virgem do Rosário.
Ẹ̀sìn àwọn ará Áfíríkà, s. Religião africana.
Màríà Wúńdíá, s. Virgem Maria.
Abo ọlọ́run òṣùpá, s. Deusa da lua
Ọlọ́run oòrùn, s. Deus do sol.
Ayé ìgbà Kọnsitatáìnì, s. O mundo de Constantino, era constantiniana.
Ọ̀nà tí wọ́n gbà ń kọ́ àwọn ṣọ́ọ̀ṣì ńláńlá, s. Arquitetura da basílica.
Ṣọ́ọ̀ṣì ńlá tó wà ní Ìlú Mẹ́síkò, s. Basílica na Cidade do México
Ilé ìjọsìn ràgàjìràgàjì, ṣọ́ọ̀ṣì ńláńlá, ṣọ́ọ̀ṣì ńlá, s. Basílica.
Táò, ìsìn Táò, s. Tao, taoísmo.
Ìṣe Búdà, s. Budismo.
Ìṣe kọnfukiọsi, s. Confucionismo.
Híńdù, Ìṣehíndù, ẹ̀sìn-ìn Híndù, s. Hinduísmo
Ìsìláàmù, ìmàle, s. Islamismo.
Ìṣekèfèrí titun, s. Neopaganismo, wicca.
Jaini, s. Jainismo.
Ìsìn àwọn Júù, s. Judaísmo
Ìsìn Sikh, s. Siquismo.
Ṣintó, ẹ̀sìn ìbílẹ̀ Jèpánù, s. Xintoísmo.
Ṣọ́ọ̀ṣì ti pẹ́ńtíkọ́sì, ìjọ ti pẹ́ńtíkọ́sì, ilé Ọlọ́run ti pẹ́ńtíkọ́sì, s. Igreja pentecostal.
Ìjọ Ajíhìnrere, s. Igreja evangélica.
Ìjọ Kátólìkì, Ṣọ́ọ̀ṣì Kátólíìkì, s Igreja católica.
Ẹ̀sìn Kristi, ìsìn Kristi, ẹ̀sìn onígbàgbọ́, kirisẹ́ńdọ̀mù, s. Cristianismo.
Ìṣeìjọánglíkánì, s. Anglicanismo.
Ìjọ ilẹ̀ Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì, s. Igreja anglicana.
Ìṣepurẹsibiteriani, s. Presbiterianismo.
Ṣọ́ọ̀ṣì Mẹ́tọ́díìsì, s Igreja metodista.
Ìjọ onígbàgbọ́, s. Congregação cristã.
Ṣọ́ọ̀ṣì Pùròtẹ́sítáǹtì, s. Igreja protestante.
Ìjọ Jéésù Lótìítọ́, s. Verdadeira Igreja de Jesus.
Ìṣeìjọkríslàm, ìṣekríslàm, ìṣekrísmàle, ìṣeìjọkrísmàle, ẹ̀sìn Krístì-ìmàle, s. Crislamismo. Sincretismo do cristianismo com o islã.
Ṣọ́ọ̀ṣì Ọ́tọ́dọ́ọ̀sì ti Ìlà Oòrùn , s. Igreja ortodoxa oriental.
Baháí, s. Fé bahá'í
Ẹ̀sìn òrìṣà, s. Religião de orixá.
Kandomblé, s. Candomblé.
Santería, s. Santeria.
Fúdù, s Vodum, vodun, voodoo ou vodu.
Ìgbàgbọ́ pé ẹ̀mí wà nínú ohun gbogbo, s. Animismo.
Ìjọsìn Sátánì, s. Satanismo.
Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà, s. Testemunhas de Jeová.
Ìjọ Jésù Krístì ti àwọn Ènìyàn Mímọ́ Ọjọ́-ìkẹ́hìn, s. Igreja de Jesus Cristo dos Santos dos Últimos Dias.
Ẹ̀sìn àgbọn, s. Religião do coco.
Àìgbọlọ́rungbọ́, àìgbà-pọ́lọ́run-wà, s. Ateísmo.
Agbátẹrù ìgbàgbọ́ Ọlọ́run-kò-ṣeé-mọ̀, s. Agnosticismo.
Iṣẹ́ àjẹ́, iṣẹ́ oṣó, iṣẹ́ òkùnkùn, s. Feitiçaria.
Oògùn, idán pípa, iṣẹ́ àjẹ́, s. Magia.
Ẹ̀sìn ìbílẹ̀, iṣe gba àwọn ẹ̀mí àìrí gbọ́, s. Xamanismo.
Ìbẹmìílò, ìbẹmìílò ká, s. Espiritismo.
UMBANDA, s. Umbanda. Ó ju àádọ́rin mílíọ̀nù ọmọ ilẹ̀ Bràsíl tí wọ́n sọ pé ó ń lọ́wọ́ nínú ẹ̀sìn kandomblé, Umbanda, Ṣàngó, àtàwọn ẹ̀sìn míì táwọn Adúláwọ̀ mú wọ orílẹ̀-èdè náà - Diz-se que mais de 70 milhões de brasileiros, direta ou indiretamente, estão ligados ao candomblé, umbanda, xangô e outras religiões afro-brasileiras.
Ṣọ́ọ̀ṣì lágbàáyé, ṣọ́ọ̀ṣì pátápátá, s. Igreja Universal.
Ilẹ̀ọba, ìjọba, s. Reino.
Gómìnà, s. Governo.
Ọba, s. Rei.
Tí, pron. rel. Que, o qual, do qual, cujo.
Tí, conj. Se. Enquanto, ao mesmo tempo que.
Tí, prep. Desde que.
Tí, v. Bater com a mão ou com algo na mão, acertar o alvo.
Tí, adv. Onde, quando.
Ti, prep. de ( indicando posse). Quando usado entre dois substantivos, usualmente é omitido. Ilé ti bàbá mi = ilé bàbá mi ( A casa do meu pai).
Ti, ti...ti, adj. Ambos... e. Ti èmi ti ìyàwó mi - ambos, eu e minha esposa.
Ti, v. Ter (verb. aux.). Arranhar. Pular.
Ti, v. interrog. Como. Ó ti jẹ́? - Como ele está.
Ti, adv. pré-v. Já. Indica uma ação realizada.
Ti, àti, conj. E.
Ti, part. pré-v. 1. Usada para indicar o tempo passado dos verbos. Èmi ti máa rìn lálé - Eu costumava caminhar à noite. 2. É usada com báwo ni - como - quando se deseja expressar sentimento e posicionada antes do verbo principal. Báwo ni àwọn ti rí? - Como eles estão?.
Tìti, adv. Tremendamente, violentamente.
Títí, adv. Continuamente, constantemente.
Títí, prep. Até.
Tìtì, adv. Tremulamente, balançadamente.
Títì, adj. Trancado, que deve ser empurrado, fechado.
Títì, ọ̀nà, s. Via pública, rua, passagem.
Ti... ti, adj. Ambos... e. Ti èmi ti ìyàwó mi - Ambos, eu e minha esposa.
Títi-àiyé, adv. Eternamente.
Títí dé, prep. Até. (referindo-se a um local ou espaço).
Títí di, prep. Até. (referindo-se a período de tempo).
Títí láé, títí láí, adv. Perpetuamente, para sempre, definitivamente.
Títilọ, adv. Continuadamente, assim por diante.
Ọlọ́run, s. O dono do céu, o ser supremo.
Elédùmarè, Èlédùmàrè, s. Deus, a divindade suprema.
Olódùmarè, Olódùmare, s. Deus, o onipotente.
Èdùmàrè, s. Deus, o ser supremo do universo. Kí ni Ọlọ́run ń fẹ́? - Qual é a vontade de Deus? Ọlọ́run ùn mi Ọba Òkè, ògo ni fún orúkọ Elédùmarè Ọba Adániwáyé mágbàgbé ẹni. Ǹjẹ́ bàbá modúpẹ́ lọ́ọ̀rẹ, ọpẹ́ ìmọ̀, ọgbọ́n, òye tí Ẹ jogún fún mi, modúpẹ́. Modúpẹ́ àǹfààní tí O fún mi láti gbé yobamoodua kalẹ̀, mo sì dúpẹ́ pé ẹ̀mí wà, bí ẹ̀mí bá sì wà, ìrètí ń bẹ. Ọ̀báńjígì gba ọpẹ́ẹ̀ mi, modúpẹ́ - Meu Deus, o Todo-Poderoso, a glória é o teu nome, Aquele que criou humano para viver na Terra. Pai, obrigado, obrigado para o conhecimento, sabedoria e compreensão que você tem dado para mim, eu agradeço. Obrigado pela oportunidade que me deu para criar yobamoodua, também sou grato pela vida, quando há vida, há esperança. Deus Todo-Poderoso aceitar o meu agradecimento.
Òrìṣà obìnrin, s. Deusa. A kì í fipá mú káwọn míì gba ohun tá a gbà gbọ́ lórí Òrìṣà obìnrin - Nós não devemos forçar ninguém a aceitar nossas crenças sobre Deusa.
Àwọn ọlọ́run àjúbàfún, s. Deuses, deidades, divindades.
Ti Ọlọ́run, adj. Divino.
Ẹ̀ṣẹ̀, s. Pecado.

Ẹ̀sìn Ọlọ́runkan, s. Monoteísmo.
Òfin Mẹ́wàá, s. Dez mandamentos.
Ónjẹ Alẹ́ Olúwa, s. Última ceia.
Bíbélì Mímọ́, bíbélì, s. Bíblia sagrada. Ìwé mímọ́ lédè hébérù àti árámáìkì - Escrituras hebraico-aramaicas.
Májẹ̀mú Láéláé, s. Antigo Testamento.
Májẹ̀mú Titun, s. Novo Testamento.

Ti ìhìnrere, adj. Evangélico.
Ti pẹ́ńtíkọ́sì, adj. Pentecostal.
Ẹlẹ́sìn Pùròtẹ́sítáǹtì, s. Protestante.
Alátẹnumọ́, s. Protestante, evangélico.Onígbàgbọ́, s. Crente.
Ẹlẹ́sìn májẹ̀mú titun, s. Neotestamentário.
Ìhìnrere, s. Evangelho.

Íṣímáẹ́lì, s. Ismael.
Kérésìmesì, s. Natal.
Ìlú Fatikan, s. Vaticano.
Pópù, s. Papa.
Biṣọpu, s. Bispo.
Àlùfá, s. Ministro do culto muçulmano, padre.
Páàdì, s. Padre.
Páàdì Kísẹ́rò, s. Padre Cícero.
Pétérù Mímọ́, s. São Pedro.
Pópù Pius 1k, s. Papa Pio I.
Àpọ́sítélì, s. Apóstolo, evangelista, evangelizador, propagador.
Símónì tàbí Pétérù, s. Simão ou Pedro.
Áńdérù, s. André.
Jákọ́bù, s. Tiago.
Jòhánù, s. João.
Fílípì, s. Filipe.
Batolómíù, s. Bartolomeu.
Mátíù, s. Mateus.
Tọ́másì, s. Tomé.
Áfíọ́sì, s. Alfeu.
Símónì, s. Simão.
Júdásì, s. Judas.
Júdásì Ísíkáríótù, s. Judas Iscariotes.
Jésù Krístì, s. Jesus Cristo.
Krístì alààyè, s. Cristo vivo.
Ọmọ-ẹ̀hìn Kristi, ọmọlẹ́hìn Kristi, s. Seguidor de Cristo, cristão.
Onígbàgbọ́, s. Uma pessoa crente.
Ẹlẹ́sìn Krístì, s. Cristão.
Onígbàgbọ́ titun, onígbàgbọ́ tuntun, ọmọ-ẹ̀hìn Kristi titun, ọmọ-ẹ̀hìn Kristi tuntun, ọmọlẹ́hìn Kristi titun, ọmọlẹ́hìn Kristi tuntun, s. Cristão-novo, converso (convertido).
Mọ̀láíkà, ańgẹ́lì, màlékà, s. Anjo.
Sátánì, s. Satã.
Ohun buburu, S. Coisa ruim.
Ańgẹ́lì lọ sílẹ̀, s. Anjo decaído.
Bìlísì ( do hauçá e do árabe iblis), s. Mal.
Ọ̀run àpáàdì, s. Inferno.
Ṣìọ́ọ̀lù, s. Seol, sheol, hades, mundo dos mortos.
Gẹ̀hẹ́nà, gẹ̀hẹ́nà oníná, s. Geena ardente. Geena refere-se ao vale de Hinom, fora das muralhas de Jerusalém. Este vale era usado como depósito de lixo, onde se lançavam os cadáveres de pessoas que eram consideradas indignas, restos de animais, e toda outra espécie de imundície. Usava-se enxofre para manter o fogo aceso e queimar o lixo. Jesus usou este vale como símbolo da destruição eterna.
Hédíìsì, s. Hádes, mundo dos mortos.
Tátárọ́sì, s. Tártaro. O mais profundo do abismo no Hades; significa encerrar no suplicio eterno.
Àjíndé, s. Ressurreição.
Miṣọ́nnárì, s. Missionário.
Pọ́ọ̀lù, s. Paulo.
Rómù, Róòmù, s. Roma.
Ítálì, Itálíà, s. Itália.
Áńtíókù ti Písídíà, s. Antioquia da Pisídia.
Sísílì, s. Sicília.
Málítà, s. Malta.
Pútéólì, s. Putéoli (atual Pozzuoli). É uma comuna italiana da região da Campania, província de Nápoles.
Ọ̀run, òkè ọ̀run, ọ̀run àlàáfíà, ọ̀run rere, s. Céu.
Màríà, s. Maria.
Jósẹ́fù, s. José.
Hánà, s. Ana.
Pẹ̀nínà, s. Penina.
Jẹ́nẹ́sísì, s. Gênesis.
Ẹ́kísódù, s. Êxodo.
Léfítíkù, s. Levítico.
Númérì, s. Números.
Diutarónómì, s. Deuteronômio.
Jóṣúà, s. Josué.
Àwọn Onídàájọ́, s. Juízes.
Rúùtù, s. Rute.
1 Sámúẹ́lì, s. 1 Samuel.
2 Sámúẹ́lì, s. 2 Samuel.
1 Àwọn Ọba, s. 1 Reis.
2 Àwọn Ọba, 2 Reis.
1 Kíróníkà, s. 1 Crônicas.
2 Kíróníkà, s. 2 Crônicas
Ẹ́sírà, s. Esdras.
Nehemáyà, s. Neemias.
Ẹ́sítérì, s. Ester.
Jóòbù, s. Jó.
Sáàmù, s. Salmos.
Òwe, s. Provérbios
Oníwàásù, s. Eclesiastes
Orin Sólómọ́nì, s. Cântico de Salomão.
Aísáyà, s. Isaías.
Jeremáyà, s. Jeremias
Ìdárò, s. Lamentações
Ìsíkíẹ́lì, s. Ezequiel
Dáníẹ́lì, s. Daniel.
Hóséà, s. Oseias.
Jóẹ́lì, s. Joel.
Ámósì, s. Amós.
Ọbadáyà, s. Obadias.
Jónà, s. Jonas.
Míkà, s. Miqueias
Náhúmù, s. Naum.
Hábákúkù, s. Habacuque.
Sefanáyà, s. Sofonias.
Hágáì, s. Ageu.
Sekaráyà, s. Zacarias.
Málákì, s. Malaquias
Mátíù, s. Mateus.
Máàkù, s. Marcos.
Lúùkù, s. Lucas.
Jòhánù, s. João.
Ìṣe, s. Atos
Róòmù, s. Romanos.
1 Kọ́ríńtì, s. 1 Coríntios.
2 Kọ́ríńtì, s. 2 Coríntios.
Gálátíà, s. Gálatas.
Éfésù, s. Efésios.
Fílípì, s. Filipenses.
Kólósè, s. Colossenses.
1 Tẹsalóníkà, s. 1 Tessalonicenses.
2 Tẹsalóníkà, s. 2 Tessalonicenses
1 Tímótì, s. 1 Timóteo.
2 Tímótì, s. 2 Timóteo.
Títù, s. Tito.
Fílémónì, s. Filêmon.
Hébérù, s. Hebreus.
Jákọ́bù, s. Tiago
1 Pétérù, s. 1 Pedro.
2 Pétérù, s. 2 Pedro.
1 Jòhánù, s. 1 João.
2 Jòhánù, s. 2 Pedro
3 Jòhánù, s. 3 João
Júúdà, s. Judas.
Ìṣípayá, s. Apocalipse.
L', pref. No.
L, pref. Forma modificada da palavra ní quando seguida de palavra iniciada por vogal diferente de i.
Ní, prep. Contração da preposição ní e substantivo. Quando a vogal inicial do substantivo não é i, a consoante n da preposição se transforma em l, e a vogal i toma forma de vogal do substantivo posterior. Mas se a vogal do substantivo é i, ela é eliminada. Ní àná ( l'ánàá ). Ní ilé (ní'lé)
Ní, part. enfática. Usada na construção de frases, quando o verbo tiver dois objetos, o segundo objeto é precedido por " ní".
Ní, prep. No, na, em. Usada para indicar o lugar em que alguma coisa está. Indica uma posição estática. Wọ́n ń wàásù ní ọjà kan ní Jakarta - Pregando em uma feira em Jacarta.
Ní, v. Ter, possuir, dizer.Transportar carga em um barco ou navio. Ocupar, obter, pegar.
Ni, v. Ser, é.
Nì, pron. dem. Aquele, aquela. Requer alongamento da vogal final da palavra que o antecede somente na fala. Ex.: Fìlà ( a ) nì = aquele chapéu.
Kàn án mọ́gi!, v. imper. Crucifica-o!, Para a estaca com ele! Bẹ̀rẹ̀ sí fẹ̀sùn kàn án - Começou a acusá-lo.

Ń, v. Estar. Indicador de gerúndio.
Ń, adv. pré-verbal. O prefixo "ń" no verbo indica não só uma ideia presente como uma ação que esteja ocorrendo, em desenvolvimento (gerúndio). Pela sua função, é equivalente ao verbo auxiliar estar em português.L', pref. No.