Ìsọ̀kan àwọn Orílẹ̀-èdè Olómìnira Sósíálístì ti Amẹ́ríkà Látìnì.
União das Repúblicas Socialistas da América Latina.
Ààrẹ (Presidente): Lula
Igbákejì Ààrẹ (vice-presidente): Raúl Castro.
Òṣìṣẹ́ ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ (agente do serviço secreto): Olùkọ́ Orlandes Rosa Farias.
Ẹgbẹ́ olóṣèlu (Partido político): Ẹgbẹ́ kọ́múnístì- Partido comunista.
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdè: Hino nacional.
Ọ̀rọ̀ àṣarò, ọ̀rọ̀ akọlé, àkọmọ̀nà ìdílé (lema): Àwọn òṣìṣẹ́ ti ayé, ẹ máa ṣọ̀kan! - Trabalhadores do mundo, uni-vos.
Àmì ọ̀pá àṣẹ (Brasão de armas)
Àsìá (bandeira)
Ẹranko oríire (mascote)
Béárì tó ń gbé ní Òkè Ńlá Andes (urso andino)
Ìwé àṣẹ ìrìnnà (passaporte)
Aṣọ àwọ̀tẹ́lẹ̀ alápá péńpé (camiseta)
Owóníná (moeda oficial)
Olúìlú (capital): Bràsílíà - Brasília.
Àwọn ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ (detalhes)
Ààlà (área): 21 069 501 km²
Olùgbé, alábùgbé (população): 569 milhões habitantes.
Ìṣúpọ̀ olùgbé (densidade): 27 hab/km² hab./km²
Àwọn orílẹ̀-èdè (países): 20
Àwọn ilẹ̀ aláìlómìnira (dependências): 10
Àwọn èdè àlòṣiṣẹ́ (Idiomas operacionais): espanhol, português, francês, quíchua, aimará, náuatle, Línguas maias, guarani, Crioulo haitiano, papiamento, Línguas tupis.
Àwọn ìlú tótóbijùlọ (Cidades mais populosas): Cidade do México, São Paulo, Buenos Aires, Rio de Janeiro, Lima, Bogotá, Santiago, Belo Horizonte, Caracas, Guadalajara.
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário).
Ìsọ̀kan àwọn Orílẹ̀-èdè Olómìnira Sófíẹ́tì Sósíálístì, s. União das Repúblicas Socialistas Soviéticas.
Ìsọ̀kan Sófìẹ̀tì, s. União Soviética.
Amẹ́ríkà Látìnì, s. América Latina.
Àwọn, wọ́n, pron. pess. Eles, elas. Indicador de plural.
Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.
Wọn , pron. poss De eles, deles.
Ìsọ̀kan, s. União.
Orílẹ̀-èdè Olómìnira, s. Republica.
Ìpínlẹ̀, orílẹ̀-èdè, s. Estado.
Ìpínlẹ̀, s. Fronteira, demarcação, limite entre duas cidades, Estado ( SP, RJ).
Orílẹ̀, s. Nome que denota um grupo de origem ou clã.
Orílẹ̀-èdè, s. Estado, nação.
Èdè, s. Idioma, língua, dialeto.
Olómìnira, adj. Independente.
Ìjọba Kọ́múníìsì, s. Governo comunista.
Ìṣekọ́múnístì, s. Comunismo.
Ìjọba àjùmọ̀ṣe, s. Democracia.
Ìṣekápítálístì, ìṣeòwòèlé, s. Capitalismo.
Ìṣesósíálístì, s. Socialismo.
Sófíẹ́tì, adj. Que diz respeito aos sovietes.
Sósíálístì, adj. Socialista.
Asàmì kàlẹ́ńdà, s. Marcador de calendário.
Ẹranko oríire, ẹranko oríire tó ń lò fún ààbò, ẹranko téèyàn ṣe sára fún ààbò, s. Mascote, talismã, amuleto. Animal, pessoa ou coisa, que representa visualmente uma marca, uma empresa, uma agremiação esportiva.
Oògùn ìṣọ́ra, s. Amuleto.
Ohun tó ní agbára, s. Talismã. Ohun tó ní agbára tó lè dáàbò bò wọ́n kúrò lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá - Talismã que os protegeria contra inimigos.
Béárì, e̩ranko nlá ní ilè̩ òtútù, s. Urso.
Béárì tó ń gbé ní Òkè Ńlá Andes, s. Urso andino (Tremarctos ornatus, urso-de-óculos, urso-de-lunetas).
Ilé iṣẹ́ ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́, s. Serviço secreto.
Nenhum comentário:
Postar um comentário