Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.
Òmìrán gbá mú ọlọ́pàá ní ọrùn. Gigante pega policial pelo pescoço.
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário) Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Òmìrán, s. Gigante. Àwọn Òmìrán ní Ayé - Gigantes na Terra. Néfílímù, s. Nefilim. Algumas versões da bíblia traduzem nefilim como “gigante. Gòláyátì, s. Golias. O nome Golias significa "grande". Golias era um gigante famoso da cidade filisteia de Gate. So pọ̀, dì lókùn, so lókùn, dè lókùn, so; dì mú, bù so, gbá mú, v. Prender. Gbá mú, v. Agarrar, pegar com firmeza, apreender. Mú, v. Capturar, agarrar. Ser afiado. Ser severo. Tomar, pegar coisas leves e abstratas. Ọlọ́pàá, s. Polícia. Ní, prep. No, na, em. Ọrùn, s. Pescoço.
Rìpóbílììkì Olúìlú Kùrìtíbà. República de Curitiba. 1. Temos provas contra Lula.
2. O DIA QUE LULA ENSINOU AO JUIZ QUE CONTRATO SEM ASSINATURA NÃO VALE NADA
3. Juiz Moro soltou o Youssef e mandou grampear. Devia saber mais do que Lula.
MORO: O sr. Não sabia dos desvios da Petrobrás? LULA: Ninguém sabia dos desvios da Petrobrás. Nem eu, nem a imprensa, nem o senhor, nem o ministério público e nem a PF. Só ficamos sabendo quando grampearam o Youssef. MORO: Mas eu não tinha que saber. Não tenho nada com isso. LULA: Tem sim. Foi o sr. quem soltou o Youssef e mandou grampear. Devia saber mais do que eu.
Moro soltou o Youssef e mandou grampear.
Dois dias depois de prender Eduardo Cunha, que foi o político mais poderoso do Brasil e conduziu o golpe parlamentar de 2016, o juiz Sergio Moro soltou o doleiro Alberto Youssef, que ficará preso em sua residência; Lava Jato começou em março de 2014, quando Youssef e Paulo Roberto Costa, ex-diretor da Petrobras, foram presos pelo juiz paranaense; desde então, dezenas de delações ocorreram e a Lava Jato aproxima-se de seu ápice com as acusações a políticos que teriam se beneficiado dos esquemas na Petrobras Fonte: http://www.brasil247.com/pt/247/parana247/261447/Moro-solta-Youssef-que-ficar%C3%A1-preso-em-casa.htm
4. Lula ataca vazamentos seletivos e relação de Moro com imprensa.
Lula prova ligação de Moro com a imprensa e juiz se cala “Eu Moro com ele”
A página ‘Eu Moro com Ele’ foi criada em março de 2016, na mesma época que Sérgio Moro retirou o sigilo de uma série de interceptações telefônicas do ex-presidente Lula e divulgou o teor das conversas, entre as quais o diálogo de Lula com a ex-presidente Dilma. Em maio do mesmo ano, o ministro do Supremo Tribunal Federal (STF) Teori Zavascki, morto em um acidente aéreo no dia 19 de janeiro de 2017, anulou a validade jurídica da escuta, e considerou que o magistrado não tinha competência para analisar o material. Além disso, o ministro considerou irregular a divulgação das conversas.
5. Lula: “Eu só quero que apresentem uma prova e parem de vazar para a imprensa"
6. Lula a Moro: você me criminalizou no jn!
7. Nem tudo que as mulheres fazem, sabemos!
8 . Relação de Moro com os inimigos de Lula. Fatos sobre Moro que jogam contra sua imparcialidade
Orílẹ̀-èdè Olómìnira, rìpóbílììkì, s. Republica. Olúìlú, s. Capital. Kùrìtíbà, s. Curitiba. Do Tupi Guarani Curi = pinheiro, araucária (pinhão); TIBA = ajuntamento, quantidade (lugar). Nome da capital do Paraná significa, terra dos pinheirais, terra de muito pinhão.
Aláìmọ̀wé tí ó fà jáde ti imí Ilẹ̀ Bràsíl náà. O Analfabeto que tirou o Brasil da bosta.
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário) Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Aláìmọ̀wé, s. Analfabeto. Ti, prep. de ( indicando posse). Quando usado entre dois substantivos, usualmente é omitido. Ilé ti bàbá mi = ilé bàbá mi ( A casa do meu pai). Ìwọ, o, pron. pess. Você. Ó, òun, pron. pess. Ele, ela. Fà, fà jáde, v. Tirar, remover, puxar. Atrair, seduzir. Arrastar, esparrar. Abater, reduzir. Orílẹ̀-èdè, s. Nação, país. Orílẹ̀, s. Grupo de origem ou clã. Èdè, s. Língua, idioma, dialeto, linguagem. Olómìnira, adj. Independente. Àpapọ̀, s. Soma, total, combinação, ato de unir, de juntar Aparapọ̀, adj. Federativa. Orílẹ̀-èdè Olómìnira Aparapọ̀ ilẹ̀ Bràsíl, s. República Federativa do Brasil. Ilẹ̀ Bràsíl, Bràsíl, s. Brasil, Pindorama. Ilẹ̀, s. Terra, solo, chão. Nínú, prep. Dentro, no interior de. A vogal é alongada se o nome que lhe segue começar com consoante. Imí, ìgbẹ́, s. Estrume, excremento. Náà, pron. dem. Aquele, aquela, aquilo. Náà, art. O, a, os, as. Náà, adv. e conj. pré-v. Também, o mesmo.
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário). Ìtara aláìmòye, ìfi ori-kuku, aìmoye di nkan mu, s. Fanatismo, intolerância, zelo excessivo, beatice. Àìkò lémí, s. Intolerância. Ìtara, s. Zelo. Aláìmòye, s. Pessoa sem percepção, pessoa abobalhada. Àìmòye, s. Imprudência. Nkan, pron. indef. Algo, alguma coisa. Nkan, s. Coisa, algo. Nkankan, s. Nada. Nkan-kí-nkan, adj. Qualquer coisa. Nkanoṣù, s. Menstruação (lit. coisas do mês). Di, v. Tornar-se, vir a ser. Ir direto. Ensurdecer. Cultivar. Di, prep. Até. Quando indica tempo ou período, é antecedida por títí. Mo ṣiṣẹ́ títí di agogo mẹ́rin - Eu trabalhei até as 16h. Se indica de um período para outro, é antecedida por láti. Mo sùn láti aago kan di aago méjì lójojúmọ́ - Eu durmo de 13 h até as 14 h diariamente. Mu, v. Beber, embeber, ensopar. Sugar, chupar, fumar. Mú, adj. Sonoro, agudo, claro. Mú, v. Tomar, pegar coisas leves e abstratas. Capturar, agarrar. Ser severo. Ser afiado. Oríkunkun, s. Obstinação, teimosia. Kúkú, v. Preferir. Kúkù, s. Mestre-cuca (do inglês cook), cozinheiro. Olùjọ́sìn, s. Adorador, cultuador. Olùfọkànsìn, s. Um devoto. Ẹ̀sìn, ìsìn, s. Culto, religião. Ti, prep. de ( indicando posse). Quando usado entre dois substantivos, usualmente é omitido. Ilé ti bàbá mi = ilé bàbá mi ( A casa do meu pai). Ti, ti...ti, adj. Ambos... e. Ti èmi ti ìyàwó mi - ambos, eu e minha esposa. Ti, v. Ter (verb. aux.). Arranhar. Pular. Ti, v. interrog. Como. Ó ti jẹ́? - Como ele está. Ti, adv. pré-v. Já. Indica uma ação realizada. Ti, àti, conj. E. Ti, part. pré-v. 1. Usada para indicar o tempo passado dos verbos. Èmi ti máa rìn lálé - Eu costumava caminhar à noite. 2. É usada com báwo ni - como - quando se deseja expressar sentimento e posicionada antes do verbo principal. Báwo ni àwọn ti rí? - Como eles estão?.
Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas.. Indicador de plural. Búlọ́ọ̀gì, wẹ́ẹ̀bù aláfikù lémọ́lémọ́, s. Blog, blogue, diário online. blog é uma palavra que resulta da simplificação do termo weblog. Este, por sua vez, é resultante da justaposição das palavras da língua inglesa web e log. Web aparece aqui com o significado de rede (da internet) enquanto que log é utilizado para designar o registro de atividade ou desempenho regular de algo. Numa tradução livre podemos definir blog como um diário online. Wọ inú búlọ́ọ̀gì, v. Blogar. Ter acesso à área reservada de um site ou programa de computador através de um login, com nome de usuário e senha; fazer login, acessar, entrar. Búlọ́ọ̀gì, wẹ́ẹ̀bù aláfikù lémọ́lémọ́, s. Blog (diário online). Akọbúlọ́ọ̀gì, s. Blogueiro. Akọbúlọ́ọ̀gì, s. Bloguista. Ibùdó, s Acampamento, local, lugar, sítio, site na internet. Lórí Ìkànnì, orí íńtánẹ́ẹ̀tì, s On-line, online. Ìkànnì, s. Site. Kí ló wà lórí ìkànnì wa? - O que pode ser encontrado em nosso site? Ojú-òpó-wẹ́ẹ̀bù, ibiìtakùn, s. Site. Ojú-òpó wẹ́ẹ̀bù, s. Site da web. Ní, prep. No, na, em. Usada para indicar o lugar em que alguma coisa está. Indica uma posição estática. Èdè yorùbá, s. Lingua yorubá.
Ìpàdé gbogbogbòò nípa oúnjẹ sí ní ìlera. Conferência sobre Alimentação Saudável.
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário) Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìpàdé gbogbogbòò, s. Conferência. Gbogbo, adj. Todo, toda, todos, todas. Nípa, nípasẹ̀, adv. Sobre, acerca de, concernente a. Lórí, lérí, prep. Sobre, em cima de. Oúnjẹ, ohun-jíjẹ, s. Comida, comestíveis, alimento, iguaria, maná e manjar. Oúnjẹ sí ní ìlera, oúnjẹ ìlera, oúnjẹ aṣaralóore, s. Alimentação saudável. Oúnjẹ aṣaralóore, s. Alimento nutritivo. Sí ní ìlera, ní ìlera, adj. Saudável, alimentoso, esculento, substancial, alimentício. Àwọn, wọ́n, pron. Eles elas. Indicador de plural. Wọn, pron. poss. Deles, delas. Wọn, pron. oblíquo, A eles, a elas. Possui função reflexiva e é posicionado numa frase de pois de verbo ou proposição. Àwo àte oúnjẹ, s. Bandeja de comida. Àwo, s. Prato. Àwo àte, s. Bandeja. Oúnjẹ, ohun-jíjẹ, s. Comida, comestíveis, alimento, iguaria, maná e manjar. Ìlera, s. Saúde. Oúnjẹ aṣaralóore, s. Alimento nutritivo. Re, v. Trocar ou perder as penas. Ser bom, ser gentil. Ṣẹ, v. Preencher, completar, tornar-se realidade. Acontecer, ocorrer. Qúínóà, s. Quinoa. Ògì, s. Amido de milho Ọkà, s. Milho, comida feita com farinha de inhame ou de mandioca, misturada com água fervente, uma espécie de àmàlà. Àgbàdo, s. Milho. Ìrẹ́sì, ìrẹsì, s. Arroz. Ìrẹsì funfun, s. Arroz branco. Súgà, s. Açúcar. Búrédì funfun, s. Pão branco. Irúgbìn wóró, s. Semente de mostarda.
Àwo àte oúnjẹ aṣaralóore la ṣẹ àgbékalè rè láti ọwọ́ àwọ́n onímò ti ilé-ìwé ètò ìlera ọ̀fẹ́ ní Havard tí a sì ṣẹ àgbéjadè rẹ̀ ní ilé-iṣẹ́ àgbéjadè ètò ìlera, èyí tó jẹ́ fún láti pe àkíyèsí wa sì oúnjẹ tó pé – yálà a bùú sínú abó tàbí sínú ike tí a fi ń gbé oúnjẹ pamọ́. Fi àpẹẹrẹ rẹ̀ kan sára fíríìjì láti máa dúró gẹ́gẹ́ bíi ape-àkíyèsí sí ìlera, àti jíjẹ́ oúnjẹ tó pé tó sì sara-lóore.
Mú kí oúnjẹ re kún fún ewébẹ̀ àti èèso – Ìdajì abọ́:
Lọ fún àwò lórísìírísìí, sì rántí pé ọ̀dùnkún kìí ṣẹ ewébè tí a lè kà kún gbíbe ní ìlera nítorí wọ́n ní ipa tí kò dára lórí ìtọ̀-súgà.
Lọ fún oúnjẹ wóóró irúgbìn kan – ó gbọ́dọ̀ jẹ́ ìdá mẹ́rin àbọ̀:
Oúnjẹ oníhóró ẹlẹ́yọ̀ – wíìtì, báálì, èèso wíìtì, qúínóà, ògì, ọkà, ìresì àti oúnjẹ tí a sè pèlú wọn, bíi oúnjẹ tí a fi àgbàdo àti ìrẹsì ṣẹ – wọ́n ní àbáyọrí díè lóri ìtò- súgà àti inslulínì ju búrédì funfun lọ, ìresì funfun àti a àwọ́n oúnjẹ irúgbìn wóró kan yókù tí a tún ṣe.
Oúnjẹ Amúnidàgbà – ó gbọ́dọ̀ jẹ́ ìdá mẹ́rin àbọ̀:
Ẹja, adìye, ẹ̀wà àti èèso ẹlẹ́pà bíi ẹ̀pà sísè, yíyan, kaṣú abbl ló dára, àwọn oúnjẹ ámaradàgbà míì tí a mú láti oríson mìíran tí – a lè dàpọ̀ mọ́ sàláàdì, àti tí a tún lè jẹ pèlú ewébè nínú abọ́. Jẹ ẹran níwọ̀nba, kí o sì sá fún ẹran bíi sọ́sáàjì àti bákóònù.
Oúnjẹ ọlọ́ràá:
Lo òróró ìsebè tó kún fún ìlera tó wà fún ìdágbásókè ara láti mú kí ara wa wà lálàáfíà bíi òróró ólívì, sóyà, àgbàdo abbl. Kí o sì sá fún àwọn òróró tí ó ń mú ní sanra tó ní àwọn ohun tí kò lè ṣara lóore. Rántí pé ọ̀rá ìwọ̀nba kò túnmọ̀ sí pé o wà ní “Ìlera Pípé”.
Mu omi, tíì tàbí kofí:
Sá fún àwọn ohun mímu tó dùn, dín mílíìkì òòjọ́ mímu kù sí èèkan tàbí èèmejì lójúmọ́, kí osì mu ife kékére kan lójoojúmọ́.
Máa wà lákínkanjú ní gbogbo ìgbà:
Àwọn àwòrán ohun pupa/ẹlẹ́jẹ̀ tó ń sáré kiri nínú àwòran àwo ìléra jẹ́ ìrántí láti máa wà ní akínkanjú àti ọ̀nà láti dín ọ̀sùwòn ìwọ̀n kù.
Kókó inú àpèjúwe oúnjẹ aṣaralóore ní láti dúró lé ìwọ̀n oúnjẹ tó pé:
Irúfé oúnjẹ afáralókun tó wà nínú oúnjẹ se pàtàkì ju oye oúnjẹ afáralókun tó wà nínú oúnjẹ lọ, torí àwọn oríson oúnjẹ afáralókun bíi ewébè (àti òdùnkún), èèso, oúnjẹ wóró irúgbìn kan, àti ẹ̀wà jẹ́ èyí tó ní ìlera ju àwọn yókù lọ.
Ó tún gba ni níyànjú pé oníbárà gbọ́dọ̀ yàgò fún àwọn ohun mímu onísúgà, èyí tó jẹ́ orísun tó tóbi jù fún ìsanra – Ó wà lórí díẹ̀ lára àwọn oúnjẹ tó ní ìdíyelé.
Oúnjẹ ìlera yìí náà tún gba oníbárà níyànjú láti lo òróró tó ní ìlera nínú; kò sì ní èyí tí ó pòjù lọ nínú ìwọ̀n ìtóbi tí ènìyàn gbọ́dọ̀ ní lójúmọ́ láti ara oríson ọ̀rá tó mú ìlera dání.
Awọn ofin lilo
A gba àwọn ènìyàn láyè láti lo àwọn àwòrán inú àwo oúnjẹ ìlera yìí ní ìbámu pèlú àwọn wọ̀nyí:
O gbọ́dọ̀ lo àwọn ìpè wọ̀nyí: “Copyright 2011 Harvard University. Fún àlàye kíkún nípa àwo oúnjẹ ìlera, jòwó wo oríson oúnjẹ amúnidàgbà, ìpín oúnjẹ amúnidàgbà, ilé-ìwé ìlera ọ̀fé, http://www.thenutritionsource.org ati Harvard Health Publications, health.harvard.edu.’’
Ìlò àwòrán àwo oúnjẹ amúnidàgbà kìí ṣẹ fún títà.
Ìlò àwòrán àwo oúnjẹ amúnidàgbà yìí gbọ́dọ̀ jé èyí tí ó tèlé gbogbo òfin tí a gbé kalẹ̀.
O kò lè sàtúnṣẹ/sàyípadà àwọn àwòrán/akosílẹ̀ rẹ̀ ní ọ̀nà kọnà.
Ilé-ìwé Harvard leè ṣẹ àgbápadà/àpèpadà àṣẹ rẹ̀ nígbàkúùgbà gẹ́gẹ́ bí ó bá ti pinu. Ní àkókò tí a bá ti ṣẹ àpèpadà ìgbàláàye náà, o gbọ́dọ̀ yọ àwòrán náà kúrò nínú ẹ̀rọ álatagbàà tàbí ibi tí gbogbo ènìyàn ti leè rí láàarín ọjọ́ márùn-ún.
Harvard lodi si gbogbo àpẹẹrẹ – yálà èyí tí a gbé jáde tàbí tí a fé lò-èyí tí o rò pé tàbí tó lè fa ká rò pé Harvard, ìpín oúnjẹ amúnidàgbà ti ilé-ìwé ìlera ọ̀fẹ́, tàbí orísun oúnjẹ amúnidàgbà alátagba ti buwọ́ lu ọjà, iṣẹ́, ènìyàn, ẹgbẹ́ tàbí ibi-iṣẹ́ kísé. Nítorí náà, o lè má lo orúkọ “Harvard,” ìpín ti oúnjẹ amunidagba ti ilé-ẹ̀kọ́ ìlera ọ̀fe tàbí “orísun oúnjẹ amúnidàgbà” tàbí ilé-iṣẹ́ kíṣẹ́ tó níí ṣẹ́ pèlú àtẹ ìbuwólù, ní àkọsílẹ̀, yàtọ̀ sí fún àtèjáde àwọn ìpè wọ̀nyí fún àwòrán gẹ́gẹ́ bí a ti kọ sókè yìí.
O lè má lo àte àwo oúnjẹ ìlera ní ọ̀nà-kọnà tó lè tàbùkù bá orúkọ Harvard.
Harvard lòdì sí gbogbo ìyanrantí èyíkéyìí (tí a sọ, kọ, tàbí rò) èyí tó níí ṣẹ pèlú àtẹ àwo oúnjẹ ìlera, láìsí òdiwọ̀n, ìyanranti tó lòdì bíi ti onísòwò/aláróbọ́, èyí tí a ṣẹ fún èrèdí pàtakì kan, tàbí àìnítèlé òfin náà. O gbọ́dọ̀ gbà láti san padà tàbí dìmú ohun tí kò lóró. Harvard University àti àwọn alága ìgbìmọ̀ ọ̀gá ilé-ìwé náà, àwọn aṣojù, ọmọ ẹgbẹ́, akẹ́kọ̀ọ́, òsìṣẹ́ àti agbódegbà láti lòdì sí èrí, ìbàjẹ́, ìsọnù, èyí tí a létòósí láti sanwọ́ rẹ̀, oye àti iye gbogbo nǹkan tó níí ṣẹ pèlú ìlò àwòrán àwo gbígbé ní ìlera.
Translation assistance provided by Dr. Sally N. Adebamowo
Terms of Use
The contents of this website are for educational purposes and are not intended to offer personal medical advice. You should seek the advice of your physician or other qualified health provider with any questions you may have regarding a medical condition. Never disregard professional medical advice or delay in seeking it because of something you have read on this website. The Nutrition Source does not recommend or endorse any products.