Aláìfẹ́irúẹ̀dáọmọẹnìkéjì láìlógo.
Racista derrotado.
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário).
Ìṣẹlẹyàmẹyà, s. Racismo.
Aláìfẹ́irúẹ̀dáọmọẹnìkéjì, s. Racista.
Àbàtì, s. Fracasso, falha.
Ìkùnà, s. Falha.
Ìṣẹ́nu, ìṣẹ́nú, s. aborto, móvito, falha, fracasso, insucesso, desmancho.
Kùnà, v. Fracassar, perder.
Tí a ti tù-lójú, tí ojú rẹ̀ mọ ilẹ̀, tí a ti mojú, adj. Amansado, dominado.
Lílù, adj. Que é para ser batido.
Gàágbo, adj. Subjugado.
Láìlágbára, adj. Fraco, sem forças, derrotado.
Láìnípa, adj. Sem poder, sem capacidade.
Láìníláárí, adj. Sem importância, insignificante.
Láìlógo, adj. Sem glória.
Láìláṣẹ, adj. Sem autoridade, sem força.