Ìṣípayá kúántù àti àgbáyé ti àwòrán ẹlẹya mẹ́ta.
O apocalipse quântico e o universo holográfico.
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário).
Físíksì kúántù, s. Física quântica.
Pápá kúántù, s. Campo quântico.
Ọkàn kúántù, s. Consciência quântica.
Àti, conj. E. Usada entre dois nomes, mas não liga verbos.
Àgbáyé, s. Mundo, cosmo, universo.
Ayé, gbogbo ẹ̀dá, àgbáyé, s. Universo.
Ayé, àiyé, s. Mundo, planeta.
Ilẹ̀-ayé, ayé, ilé-ayé, s. Terra (planeta terra).
Plánẹ̀tì ilẹ̀-ayé, s. Planeta terra.
Àdánidá, s. Natureza.
Àwòrán ẹlẹya mẹ́ta, s. Holograma.
Ti àwòrán ẹlẹya mẹ́ta, adj. Holográfico.