domingo, 8 de janeiro de 2017

Animais

Ẹkùn “Baba Ẹranko” – Tigre "Pai dos Animais"

Ẹkùn “Baba Ẹranko” - Tiger "Father of Animals

Kìnìún ni “Ọlọ́là Ijù -   Leão" O Rei da Floresta ".

Kìnìún ni “Ọlọ́là Iju - Lion "The King of the Forest".

Ọmọ Ẹkùn - Filhotes de tigre

ọmọ Ẹkùn - Tiger's cubs


Ológbò/Ológìní - Gato

Ológbò/Ológìní - Cat



Igún (Abutre)

Igún - Vulture

Corte de energia

Dákú-dáji iná mọ̀nà-mọ́na.
Corte de energia incessante.

Resultado de imagem para corte de energia electrica

Rua

Ọ̀nà ti ó bàjẹ́ (rua ruim)

Resultado de imagem para popozuda em rua esburacada

Gerador de energia

Ẹ̀rọ mọ̀nà-mọ́ná (gerador de energia)

Resultado de imagem para gerador de energia

Independência

Àjọ̀dún òmìnira. 
Celebração da Independência.







2017


Ẹ káàbọ̀ si ọdún Ẹgbàálémẹ́tàdínlógún (Bem-vindo a 2017)


Ẹ kú Ọdún titun! - Feliz ano novo!


Ọdún Ẹgbàálémẹ́tàdínlógún dé –  Ano de 2017 está aqui.

A dúpẹ́ pé ó bá wa láyé - Somos gratos por estar vivo.

Ọlọrun á ṣe ọdún ni ọdún ayọ̀ –  Deus fará ano de alegria.

Ìlú wa yi ó tòrò lágbára Èdùmàrè –  Pelo poder de Deus, nosso país será pacífico. 

Ẹ̀mí wa á ṣe ọ̀pọ̀ ọdún pẹ̀lú ara li leQue você possa viver para comemorar muitos anos de boa saúde


Ẹ káàbọ̀ si ọdún Ẹgbàálémẹ́tàdínlógún – Bem-vindo a 2017.

Cuba

Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Kúbà                                                    República de Cuba    




Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).

Orílẹ̀, s. Nome que denota um grupo de origem ou clã.
Orílẹ̀-èdè, s. Estado, nação.
Èdè, s. Idioma, língua, dialeto.
Olómìnira, adj. Independente.
Ilẹ̀, s. Terra, solo, chão. 
Kúbà, s. Cuba.