Ará ọ̀run (habitantes do espaço, ET, alienígenas, extraterrestres, extraterrenos, espíritos).
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário).
Àtọ́dúnmọ́dún, adv. Muitos anos atrás.
Àtọdúnmọ́dún, s. Anos atrás.
Àtoṣùmóṣù, adv. Meses atrás.
Gàgàgúgú, adj. Muito grande, pesado.
Irinṣẹ́, s. Ferramenta de trabalho.
Àjùlé ọ̀run, s. Abóbada celeste, firmamento. Ìsọfúnni wọ̀nyí ń wá láti Orísun kan tó ga gidigidi ju ibi táwọn èèyàn yìí rò pé ìsọfúnni yóò ti wá lájùlé ọ̀run - Estas vêm duma Fonte muito mais elevada do que de qualquer imaginário extraterrestre.
Ìsọfúnni, s. Informação.
Orísun, s. Fonte,
Onímọ̀ ìjìnlẹ̀, s. Cientista.
Ará ọ̀run, s. Habitante do espaço, espírito, extraterrestre. Àtọdúnmọ́dún, àtoṣùmóṣù làwọn onímọ̀ ìjìnlẹ̀ ti jókòó ti irinṣẹ́ gàgàgúgú yìí, tí wọ́n ń retí àtigbọ́ ohùn àwọn ará ọ̀run - Os cientistas têm esperado por décadas receber mensagens de vida extraterrestre por meio deste enorme instrumento.