Ìforúkọsílẹ̀ Àyíká Tó Wà Nínú Oko.
Cadastro Ambiental Rural.
Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Para mais informações:
http://www.mma.gov.br/desenvolvimento-rural/cadastro-ambiental-rural.html
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário).
Ìròyìn kan tó wá látọ̀dọ̀ Ẹ̀ka Tó Ń Bójú Tó Iṣẹ́ Àgbẹ̀, s. Um relatório do Departamento de Agricultura.
Ìròyìn kan tó wá látọ̀dọ̀ Ẹ̀ka Tó Ń Bójú Tó Iṣẹ́ Àgbẹ̀, Ìpèsè Oúnjẹ àti Ìdàgbàsókè Ìgbèríko, s. Um relatório do Departamento de Agricultura, Alimentos e Desenvolvimento Rural.
Àyíká, s. Ambiente.
Ẹ̀kọ́ nípa àyíká, s. Educação ambiental.
Ẹ̀dá, s. Criatura, criação, qualquer criatura viva. Natureza, criação.
Àdánidá, s. Natureza.
Àwọn ìṣòro àyíká, s. Problemas ambientais.
Ìbàyíkájẹ́, s. Poluição.
Ilé Ẹ̀kọ́ Nípa Àyíká, s. Instituto Ambiental.
ILÉ Iṣẹ́ Tó Ń Rí sí Ọ̀ràn Àyíká, s. Ministério do Meio Ambiente.
Ọdún Ìgbógo fún Ibi Rírẹwà Jù Lọ, s. Ano do Paisagismo.
Ìgbèríko, s. Vizinhaça, província, costa. Área rural, zona rural.
Àgbègbè àrọko, s. Zona rural.
Àwọn ìgbèríko, s. Áreas rurais. Nígbà àtijọ́, ìlú Vagnari jẹ́ ìgbèríko èyí tí olú ọba ń ṣàkóso, àwọn lébìrà máa ń yọ́ irin níbẹ̀, wọ́n sì tún ń ṣe àwo ìbolé níbẹ̀ - Nos tempos antigos, Vagnari era uma propriedade imperial rural — uma região controlada pelo imperador — onde os trabalhadores fundiam ferro e produziam telhas de barro.
Tí wọ́n wà láwọn ìgbèríko, adj. Nas zonas rurais.
Ìgbésí ayé oko, s. Vida rural.
Tó wà ní àrọko, tó ń gbé láwọn ìgbèríko, tó wà nínú Ìgbèríko, tó wà nínú oko, ti oko, ti igbó, adj. Rural.
Àrọko, s. Sede de uma fazenda, casa-grande.
Ilẹ̀ títẹ́jú gbalasa, s. Terreno plano e aberto.
Òṣìṣẹ́ tí ń ṣí káàkiri, s. Trabalhador migrante.
Àwọn àgbẹ̀, s. Agricultores.
Àwọn lébìrà ìgbèríko, àwọn lébìrà tó ń ṣiṣẹ́ oko, s. Trabalhadores rurais.
Àwọn tó ń gbé lábúlé, s. Moradores da aldeia, populações rurais.

Àkọsílẹ̀, ìkọsílẹ̀, s. Ato de escrever, registros, escritos.
Ìforúkọsílẹ̀, s. Registro, cadastro.Àyíká, s. Ambiente.
Ẹ̀kọ́ nípa àyíká, s. Educação ambiental.
Ẹ̀dá, s. Criatura, criação, qualquer criatura viva. Natureza, criação.
Àdánidá, s. Natureza.
Àwọn ìṣòro àyíká, s. Problemas ambientais.
Ìbàyíkájẹ́, s. Poluição.
Ilé Ẹ̀kọ́ Nípa Àyíká, s. Instituto Ambiental.
ILÉ Iṣẹ́ Tó Ń Rí sí Ọ̀ràn Àyíká, s. Ministério do Meio Ambiente.
Ọdún Ìgbógo fún Ibi Rírẹwà Jù Lọ, s. Ano do Paisagismo.
Ìgbèríko, s. Vizinhaça, província, costa. Área rural, zona rural.
Àgbègbè àrọko, s. Zona rural.
Àwọn ìgbèríko, s. Áreas rurais. Nígbà àtijọ́, ìlú Vagnari jẹ́ ìgbèríko èyí tí olú ọba ń ṣàkóso, àwọn lébìrà máa ń yọ́ irin níbẹ̀, wọ́n sì tún ń ṣe àwo ìbolé níbẹ̀ - Nos tempos antigos, Vagnari era uma propriedade imperial rural — uma região controlada pelo imperador — onde os trabalhadores fundiam ferro e produziam telhas de barro.
Tí wọ́n wà láwọn ìgbèríko, adj. Nas zonas rurais.
Ìlétò, abúlé, s. Vila, vilarejo.
Iṣẹ́ àgbẹ̀, s. Agricultura. Kí ló mú káwọn àgbẹ̀ máa ṣí kúrò nílẹ̀ náà? - O que provoca o êxodo rural?Ìgbésí ayé oko, s. Vida rural.
Tó wà ní àrọko, tó ń gbé láwọn ìgbèríko, tó wà nínú Ìgbèríko, tó wà nínú oko, ti oko, ti igbó, adj. Rural.
Àrọko, s. Sede de uma fazenda, casa-grande.
Ilẹ̀ títẹ́jú gbalasa, s. Terreno plano e aberto.
Òṣìṣẹ́ tí ń ṣí káàkiri, s. Trabalhador migrante.
Àwọn àgbẹ̀, s. Agricultores.
Àwọn lébìrà ìgbèríko, àwọn lébìrà tó ń ṣiṣẹ́ oko, s. Trabalhadores rurais.
Àwọn tó ń gbé lábúlé, s. Moradores da aldeia, populações rurais.
Àyíká ìgbèríko rírẹwà, s. Belo ambiente rural.
Oko kékeré lábúlé, oko kékeré, oko kéékèèké, oko ìdílé , s. Pequena propriedade rural, sítio. Àwọn oko ìdílé ń parẹ́ - As pequenas propriedades rurais estão acabando.
Oko, s. Orixá da agricultura. Fazenda, roça, plantação.
Oko tí wọ́n ti ń ṣiṣẹ́ ọ̀gbìn, s. Fazenda.
Oko kékeré, s. Fazenda pequena. Àwọn òbí mi ní oko kékeré kan, ohun tí a ń kórè látinú oko la sì fi ń gbọ́ bùkátà - Meus pais tinham uma pequena propriedade rural, de onde tirávamos o sustento.
Ibi jíjìnnà, s. Local distante.
Àwọn olùkórè, s. Trabalhadores para a colheita.