Ìbéèrè tó jẹ mọ́ ìdánwò gbogbogbòò (questão de concurso).
Qual alternativa apresenta apenas um plural?
A) Corrimão (corrimãos, corrimões).
B) Álcool (álcoois, alcoóis).
C) Mel (méis, meles).
D) Cirurgião (cirurgiões, cirurgiães).
E) Sol (sóis). ✔
Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò, àkójọ ọ̀rọ̀ tí ò ń lò lójoojúmọ́, àwọn àkànlò ọ̀rọ̀, àwọn àkànlò èdè, ọ̀rọ̀ tó máa ń sọ, àkànlò èdè lọ́nà tó gún régé (vocabulário).
Nwọ́n, pron. pess. Eles, elas. Expressa uma ação que não é creditada a nenhuma pessoa em particular.
Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; neste caso, é posicionado antes do substantivo.
Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.
Wọn, pron. poss. Deles, delas.
Ìdánwò gbogbogbòò, s. concurso, exame geral.
Àwọn ìbéèrè, s. Questões. Fi àmì ✔ sí èyí tó jẹ́ nísàlẹ̀ yìí - Ponha um ✔ em uma das alternativas abaixo.
Àwọn ìbéèrè amúnironújinlẹ̀, s. Questões de reflexão.
Ìbéèrè, àbèèrè, s. Pergunta, questão, requisição.
Ìbéèrè pàtàkì kan, s. Uma pergunta importante.
Ọ̀ràn tó jẹ mọ́ ẹ̀rí ọkàn, s. Questão de consciência.
Ìbéèrè tó jẹ mọ́ ìdánwò gbogbogbòò, s. Questão de concurso.
Tá a lò fún ẹnì kan àti ẹni púpọ̀, adj. Usado no singular e no plural.
Ọ̀rọ̀ tó ń tọ́ka sí ẹnì kan, s. Palavra que se refere a uma pessoa, singular.
Tó jẹ́ ọ̀rọ̀ atọ́ka ẹnì kan ṣoṣo, adj. Que é um pronome pessoal singular.
Ti ènìyàn púpọ̀, s. De muitas pessoas, plural.
Ọ̀rọ̀ ìsọdipúpọ̀, s. Palavra plural.
Ọ̀rọ̀ kan ṣoṣo, s. Palavra singular.
Ti ènìyàn kan, adj. Singular.
Àìlẹ́gbẹ́, adj. Único, incomparável, exclusivo.
Tó tan mọ́ ọn, adj. Relacionado a ele.
Tó ní í ṣe pẹ̀lú, adj. Relacionado a, relacionado com.
Tó jẹ mọ́, adj. Relacionado a.
Tó ń tọ́ka sí, adj. Referindo-se a.
Nenhum comentário:
Postar um comentário