Àwọn onímọ̀sáyẹ́nsì ti orílẹ̀ èdè Áfríkà (cientistas africanos).
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário).
Àwọn, wọn, pron. Eles elas. Indicador de plural.
Onímọ̀sáyẹ́nsì, s. Cientista.
Ní ti Áfríkà, ti orílẹ̀ èdè Áfríkà, adj. Africano.
Àwùjọ tonísáyẹ́nsì, s. Comunidade científica.
Ọmọ ilẹ̀ Áfríkà, s. Africano.
Ọmọ kùnrin ilẹ̀ Áfríkà, s. Africano.
Ọmọbìnrin ilẹ̀ Áfríkà, s. Africana.