Baálẹ̀ Jòhánù Dọ́ríà kéde ìsọditaládàáni káríayé ti Olúìlú Páùlù mimọ́
O Prefeito João Doria anuncia a privatização internacional de São Paulo.
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário).
Baálẹ̀, s. Prefeito.
Baálẹ̀ Jòhánù Dọ́ríà, s. Prefeito João Doria.
Kéde, v. Proclamar, promulgar, anunciar.
Káríayé, ti ìbálò láárín àwọn orílè èdè, adj. Internacional.
Pọ́ọ̀lù, Páùlù, s. Paulo.
Mímọ́, adj. Limpo, puro, íntegro, sagrado.
Pọ́ọ̀lù mimọ́, Páùlù mimọ́, s. São Paulo.
Ti, prep. De (indicando posse). Quando usado entre dois substantivos, usualmente é omitido. Ilé ti bàbá mi = ilé bàbá mi ( A casa do meu pai).
Ìyípadà ǹkàn latí ti ìjoba sí aládàní, ìyípadà ǹkàn latí ti ìpínlẹ̀ sí aládàní, títà-kúrò-lọ́wọ́-ìjọba, ìsọditaládàáni, s. Privatização.
Nenhum comentário:
Postar um comentário