Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.
sexta-feira, 9 de março de 2012
Mão
Kí ni Yorùbá ń pe àwọn ẹ̀ya ọwọ́?
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário).
Àtàǹpàkò, àtàǹpààkò, àtàràǹpààkò, s. Polegar (dedão, positivo, mata-piolho).
Tọ́bẹ̀lá, ìtọ́bẹ̀lá, s. Indicador (apontador, fura-olho, fura-bolo).
Mogajùwọ́nlọ, s. Dedo médio (dedo do meio, maior-de-todos, pai-de-todos).
Òrùkáyẹmí, s. Dedo anelar (anelar, seu-vizinho).
Ọmọńdirín, kúrúbete, s. Dedo mínimo. (dedinho, mindinho, minguinho).
Ilà-ọwọ́, s. Linha da mão.
Àtẹ́lẹ́-ọwọ́, s. Palma da mão.
Ọrùn-ọwọ́, s. Pulso, punho, munheca, carpo.
Postado por Aulas de yorùbá- Olùkó orlandes Rosa Farias às 13
Assinar:
Postagens (Atom)