1- Àṣà (cultura)
Lítíréṣọ̀ = literatura
Eré-ìdárayá = desportos Fílmù = cinema Orin = música Tíátà = teatro Ìṣeròyìn = jornalismo Tẹlifísàn = televisão Rédíò = rádio
2- Ìlera (saúde)
Ìdárayá = exercício Amáralókun = nutriente Ìtọ́jú ìlera = assistência médica
Àrùn = doença, indisposição.
Ọ̀rọ̀-àjàkálẹ̀àrùn = Epidemiologia
3 - Àwùjọ (Sociedade)
Ẹbí = família
Fàájì = entretenimento
Òfin = direito
Ọ̀rọ̀-òkòwò, ìṣiṣẹ́òkòwò= economia
Ìnáwó = Finança
Ìṣèlú = política
Ọ̀rọ̀-àwùjọ, Ìṣeọ̀rọ̀àwùjọ = sociologia
Ènìyàn = pessoas, povo
Ẹ̀kọ́ = educação
Ìmòye = filosofia
4 - Mathimátíkì (matemática)
Áljẹ́brà = Álgebra
Ìtúwò mathimátíìkì = análise matemática
Ìṣírò = aritmética
Ìṣedọ́gba = equação
Jẹ́ọ́mẹ́trì = geometria
Nọ́mbà = número
Tẹ̀ọ́rẹ́mù = teorema
Ọgbọ́n = Lógica
5 - Ìtàn (história)
Ogun = guerra
Orílẹ̀-èdè tẹ́lẹ̀ = Estado extinto
Ilẹ̀ọbalúayé = império
Ọ̀rọ̀-ayéijọ́un = texto antigo
6 - Ẹ̀sìn àti ìgbàgbọ́ (religião e fé)
Ẹ̀sìn Yorùbá = religião yorubá
Kandomblé = candomblé
Santería = santeria
Baháí = fé bahá'í
Ìṣehíndù = hinduísmo
Shinto = xintoísmo
Ìmàle = islamismo
Ẹ̀sìn Krístì = cristianismo
Ìṣebúddhà = budismo
7 - Tẹknọ́lọ́jì (tecnologia)
Iṣẹ́ẹ̀rọ = engenharia
Internet = internet
Àfigbébánisọ̀rọ̀ = telecomunicação
Kọ̀mpútà = computador
8 - Sáyẹ́nsì (ciência)
Ìtòràwọ̀ = Astronomia Físíksì = física
Òfurufú = espaço
Ọ̀gbìn = Planta
Sáyẹ́nsì kọ̀mpútà = ciência da computação
Ìwòsàn = medicina
Àdánidá = natureza
Kẹ́místrì = química
Bàíọ́lọ́jì = biologia
9 - Jẹ́ọ́gráfì (geografia)
Ayé = terra Adágún = lago Orílẹ̀-èdè = país Òkun = oceano Orílẹ̀ = continente Ìlú = Cidade Áfríkà = África Ásíà = Ásia Europe = Europa Gúúsù Amẹ́ríkà = América do Sul Àríwá Amẹ́ríkà = América do Norte
Oṣéáníà = Oceania
Antárktìkà = Antártida, Antártica
10 - Ìgbésíayé (biografia)
Olórí orílẹ̀-èdè = chefes de Estado Oníṣọ̀nà = artista Òṣeré = Ator Onímọ̀sáyẹ́nsì = cientista Amòye = filósofo Olóṣèlú = político Olùkọ̀wé = escritor Oníṣòwò = Empresário