Aṣa - Ẹyẹ Àdàbà - pẹ̀lú àkọlékè.
Asha - Pomba - Legendada.
Ẹyẹ Àdàbà
Canção de Aṣa
Letra
Ojúmọ́ ti mọ, ojúmọ́ ti mọ mi
Ní ilẹ̀ yí o
Ojúmọ́ ti mọ, mo rí 're o
Ojúmọ́ ti mọ, ojúmọ́ ti mọ mi
Ní ilẹ̀ yí o
Ojúmọ́ ti mọ, mo rí 're o
Ẹyẹ àdàbà, ẹyẹ àdàbà
Ẹyẹ àdàbà tí fò l'ókè l'ókè
Wá a bà lé mi o o
Ojúmọ́ ti mọ, mo rí 're o
Ojúmọ́ ti mọ, ojúmọ́ ti mọ mi
Ní ilẹ̀ yí o
Ojúmọ́ ti mọ, mo rí 're o
Ojúmọ́ ti mọ, ojúmọ́ ti mọ mi
Ní ilẹ̀ yí o
Ojúmọ́ ti mọ, mo rí 're o, ó yá
Ẹyẹ àdàbà, ẹyẹ àdàbà, ẹyẹ e e e
Ẹyẹ àdàbà tí fò l'ókè l'ókè
Wá a bà lé mi o o
Ojúmọ́ ti mọ, mo rí 're o, ó yá
Ẹyẹ àdàbà, ẹyẹ àdàbà, ẹyẹ e e e
Ẹyẹ àdàbà tí fò ó ń fò ń fò
Wá a bà lé mi o o
Ojúmọ́ ti mọ, mo rí 're o
Ẹ wí kí n gbọ́ sẹ́
Ẹyẹ àdàbà, ẹyẹ eee
Ẹyẹ àdàbà tí fò l'ókè l'ókè l'ókè ó dé ọ̀run
Wá bà lé mi o o
Ojúmọ́ ti mọ, mo rí 're o
O o o ó yè e
Ẹyẹ àdàbà, ẹyẹ àdàbà, ẹyẹ o o
Ẹyẹ àdàbà tí fò ó ń fò ń fò
Wá bà lé mi o o
Ojúmọ́ ti mọ, mo rí 're o
O o oo oo ooo
O o oo o
Ẹ wí kí n gbọ́ sẹ́
O o oo o
Aah o o o oo o
Oo mo rí 're o
O o o o ooo o
Mo rí 're o
Ire ire ire ooo
O o o o o
Mo rí 're o
Ẹyẹ àdàbà, ẹyẹ àdàbà
Ẹyẹ tí fò l'ókè l'ókè ó dé ọ̀run
Wá bà lé mi o o
Ojúmọ́ ti mọ, mo rí 're o
Compositores: Bukola Elemide / Cobhams Emmanuel Asuquo
Letra de Eyé Àdabá © Sony/ATV Music Publishing LLC
Asha - Pomba - Legendada.
Ẹyẹ Àdàbà
Canção de Aṣa
Letra
Ojúmọ́ ti mọ, ojúmọ́ ti mọ mi
Ní ilẹ̀ yí o
Ojúmọ́ ti mọ, mo rí 're o
Ojúmọ́ ti mọ, ojúmọ́ ti mọ mi
Ní ilẹ̀ yí o
Ojúmọ́ ti mọ, mo rí 're o
Ẹyẹ àdàbà, ẹyẹ àdàbà
Ẹyẹ àdàbà tí fò l'ókè l'ókè
Wá a bà lé mi o o
Ojúmọ́ ti mọ, mo rí 're o
Ojúmọ́ ti mọ, ojúmọ́ ti mọ mi
Ní ilẹ̀ yí o
Ojúmọ́ ti mọ, mo rí 're o
Ojúmọ́ ti mọ, ojúmọ́ ti mọ mi
Ní ilẹ̀ yí o
Ojúmọ́ ti mọ, mo rí 're o, ó yá
Ẹyẹ àdàbà, ẹyẹ àdàbà, ẹyẹ e e e
Ẹyẹ àdàbà tí fò l'ókè l'ókè
Wá a bà lé mi o o
Ojúmọ́ ti mọ, mo rí 're o, ó yá
Ẹyẹ àdàbà, ẹyẹ àdàbà, ẹyẹ e e e
Ẹyẹ àdàbà tí fò ó ń fò ń fò
Wá a bà lé mi o o
Ojúmọ́ ti mọ, mo rí 're o
Ẹ wí kí n gbọ́ sẹ́
Ẹyẹ àdàbà, ẹyẹ eee
Ẹyẹ àdàbà tí fò l'ókè l'ókè l'ókè ó dé ọ̀run
Wá bà lé mi o o
Ojúmọ́ ti mọ, mo rí 're o
O o o ó yè e
Ẹyẹ àdàbà, ẹyẹ àdàbà, ẹyẹ o o
Ẹyẹ àdàbà tí fò ó ń fò ń fò
Wá bà lé mi o o
Ojúmọ́ ti mọ, mo rí 're o
O o oo oo ooo
O o oo o
Ẹ wí kí n gbọ́ sẹ́
O o oo o
Aah o o o oo o
Oo mo rí 're o
O o o o ooo o
Mo rí 're o
Ire ire ire ooo
O o o o o
Mo rí 're o
Ẹyẹ àdàbà, ẹyẹ àdàbà
Ẹyẹ tí fò l'ókè l'ókè ó dé ọ̀run
Wá bà lé mi o o
Ojúmọ́ ti mọ, mo rí 're o
Compositores: Bukola Elemide / Cobhams Emmanuel Asuquo
Letra de Eyé Àdabá © Sony/ATV Music Publishing LLC