Ìbèèrè ti ọmọ-ìbílẹ̀ ní'lẹ̀ Bràsíl ní ìṣẹ́jú mẹ́rin.
A questão indígena no Brasil em quatro minutos.
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário).
Ìbèèrè, àbèèrè, s. Pergunta, questão, requisição.
Ìṣòro, s. Dificuldade, problema.
Ọmọ-ìbílẹ̀, ẹ̀yà abínibí, onílẹ̀, ìbílẹ̀, s. Índio, nativo, aborígine, indígena.
Ti ìbílẹ̀, ti ilẹ̀, ti ìlú, ti ọmọ-ìbílẹ̀, adj. Indígena, nativo, aborígene.
Ilẹ̀, s. Terra, solo, chão.
Bràsíl, s. Pindorama, Brasil.
Mẹ́rin, num. Total de quatro.
Ìṣẹ́jú, s. Minuto.
Iṣoṣó, s. Gentileza, encantamento.