Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário). Ọpa ijó, s. Pole dance, dança do cano, dança do poste. Ọ̀pá, s. Cajado, poste, vareta com que se tocam os atabaques dùndún e bẹ̀mbẹ́. Ọ̀pá aládé, s. Cetro. Ọpa, s. Poste, estaca de bambu. Òpó, s. Poste, pilar. Ijó, s. Dança.
Iṣẹ́ ni oògùn ìṣẹ́, múra si iṣẹ́ rẹ ọ̀rẹ́ mi, iṣẹ́ ni a fi i di ẹni gíga Bí a kò bá rẹ́ni fẹ̀hìn tì, bí ọ̀lẹ là á rí Bí a kò bá rẹ́ni gbẹ́kẹ̀lé, à á tẹra mọ iṣẹ́ ẹni Ìyá rẹ lè lówó lọ́wọ́, Bàbá si lè lẹ́ṣin leekan Bí o bá́ gbójú lé wọn, o tẹ́ tán ni mo sọ fún ọ Ohun ti a kò bá jìyà fún kì í lè tọ́jọ́ Ohun ti á fara ṣiṣẹ́ fún ní í pẹ́ lọ́wọ́ ẹni Apá lará, ìgunpá niyèkan Bí ayé n fẹ́ ọ loni, bí o bá lówó lọ́wọ́, ni wọn má a fẹ́ ọ lọla Tàbí tí o bá wà ní ipò àtàtà, ayé a yẹ́ ọ sí tẹ̀rín-tẹ̀rín Jẹ́ kí o di ẹni n rágó, kí o ri bí ayé ti n yínmú sí ọ Ẹ̀kọ́ sì tún n sọni dọ̀gá, mú́ra kí o kọ dáradára Bí o sì rí ọ̀pọ̀ ènìyàn, tí wọn fi ẹ̀kọ́ ṣe ẹ̀rín rín Dákun má ṣe fara wé wọn Ìyà n bọ̀ fọ́mọ tí kò gbọ́n, ẹkún n bẹ fọ́mọ tó n sá kiri Má fòwúrọ̀ ṣeré, ọ̀rẹ́ mi, múra sí iṣẹ́ ọjọ́ n lọ ENGLISH TRANSLATION Work is the antidote for poverty, work hard, my friend Attaining higher height is largely dependent on hard work If there is no one to depend on, we simply work harder Your mother may be wealthy, your father may have a ranch of horses If you depend on their wealth, you may end up in disgrace, I tell you Gains not earned through hard work, may not last Whatever is earned through hard work, often last in one’s hand The arm is a relative, the elbow remain a sibling The world may love you today, it is only when you are relevant that you will be loved tomorrow Or when you are in a position of authority, the world will honour you with cheers Wait till you are poor and you will see how all will grimace at you Education do contribute to making one relevant, ensure you acquire solid education And if you see people mocking education, Please do not emulate them Suffering is lying in wait for irresponsible children, sorrow lies ahead for truants Do not waste your early years, my friend, work harder, time waits for no one. Tradução (Google Tradutor) O trabalho é o antídoto para a pobreza.
O trabalho é o antídoto para a pobreza, trabalhe duro, meu amigo Alcançar uma altura mais elevada é largamente dependente do trabalho árduo Se não houver ninguém para depender, simplesmente trabalhamos mais Sua mãe pode ser rica, seu pai pode ter uma fazenda de cavalos Se você depende de sua riqueza, você pode acabar em desgraça, eu lhe digo Ganhos não ganhos com o trabalho duro, podem não durar O que é ganho com o trabalho duro, muitas vezes durar na mão O braço é um parente, o cotovelo permanece um irmão O mundo pode te amar hoje, é somente quando você é relevante que você será amado amanhã Ou quando você está em uma posição de autoridade, o mundo vai honrá-lo com aplausos Espere até que você é pobre e você vai ver como todos vão fazer careta para você Educação contribuir para tornar um relevante, garantir que você adquirir uma educação sólida E se você vê pessoas zombando da educação, Por favor, não os imite O sofrimento está à espreita de crianças irresponsáveis, a tristeza está à frente para os verdadeiros Não desperdice seus primeiros anos, meu amigo, trabalhe mais, o tempo não espera por ninguém.
A pecuária é a gestão e o cuidado dos animais de exploração pelos seres humanos, em que as qualidades genéticas e comportamento, considerado como vantajoso para os seres humanos, são mais desenvolvidos. O termo pode referir-se à prática de criação selectiva e criação de gado para promover características desejáveis em animais para utilidade, desporto, prazer ou investigação.
Especialização produtiva na criação animal:
- Ẹ̀kọ́ ìroko ẹran ọ̀sìn-pípa - Pecuária de corte (criação de bovinos destinados à produção de carne). - Ẹ̀kọ́ Ìroko ẹran-ọsìn ti wàrà - Pecuária de leite (criação de bovinos e outros animais destinados à produção de leite). - Ẹ̀kọ́ ìroko ẹran-ọsìn ti irun àgùtàn - Pecuária de lã (criação de ovinos ou caprinos que fornecem lã). - Ẹ̀kọ́ ìroko ẹṣin - Equinocultura (criação de cavalos). - Ẹ̀kọ́ ìroko ẹran ẹlẹ́dẹ̀ - Suinocultura (criação de porcos). - Ẹ̀kọ́ ìroko abìyẹ́ - Avicultura (criação de aves). - Ẹ̀kọ́ ìroko ehoro - Cunicultura (criação de coelhos). - Ẹ̀kọ́ ìroko oyin - Apicultura (criação de abelhas). - Ẹ̀kọ́ ìroko ẹja - Piscicultura (criação de peixes).
Ìmọtótó (limpeza) Ìmọtótó ló le ṣẹ́gun àrun o. A limpeza pode vencer a doença. Ìmọtótó ilé ( Limpeza da casa). Ìmọtótó ara ( Limpeza do corpo). Ìmọtótó aṣọ ( Limpeza da roupa). Ìmọtóto ouńjẹ (Limpeza da comida). Ìmọtótó ló le ṣẹ́gun àrun o.
Ìmọtótó, s. Limpeza. Ló, v. + pron. Ser ela, ser ele. Ló, v. Tranquilizar-se. Lè, v. aux. Poder físico ou inteectual. Tendência para uma ocorrência. Dever, precisar. Ṣẹ́gun, v. Vencer. Àrùn, s. Doença. O, part. adv. Forma frases excamativas para ênfase. Ó ti dé o! - Ela já chegou!
Ìbálòpọ̀ pẹ̀lú yèyé ìṣẹ̀dá tàbí àràmàǹdà obìnrin náà.
Ecossexualidade (relação sexual com a mãe natureza).
Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò, àkójọ ọ̀rọ̀ tí ò ń lò lójoojúmọ́, àwọn àkànlò ọ̀rọ̀, àwọn àkànlò èdè, ọ̀rọ̀ tó máa ń sọ, àkànlò èdè lọ́nà tó gún régé (vocabulário).
Àbáṣe, ìbáṣe (cooperação, apoio, assistência, relação sexual com uma mulher), ìfẹ́ ìbálòpọ̀ sókè (excitação sexual), ẹni tó nífẹ̀ẹ́ sí bíbá ọkùnrin àti obìnrin lò pọ̀ (aquele que tem atração ou interesse sexual pelos dois sexos), ìbálòpọ̀, ẹ̀yà abo àti akọ, ẹ̀ya obìnrin àti ọkùnrin, ìbádàpọ̀, takọtabo, ìbálòpọ̀ takọtabo (sexo), iṣẹ́ aṣẹ́wó mímọ́ (prostituição sagrada), ìwà bíbá ọmọdé ṣèṣekúṣe (pedofilia), yíyan ọmọdé láàyò fún ìbálòpọ̀ (interesse mórbido pelas crianças), ìgbégbòdì ìbálòpọ̀ nínú èyí tí ó jẹ́ pé àwọn ọmọdé ni a yàn láàyò (perversão sexual em relação às crianças), ìwà bíbá ẹranko ṣèṣekúṣe (zoofilia), ìwà bíbá adìyẹ ṣèṣekúṣe (zoofilia com galinhas), ẹni tó máa ń bá yèyé ìṣẹ̀dá tàbí àràmàǹdà obìnrin náà lò pọ̀ (ecossexual, aquele que faz sexo com a mãe natureza).