Ìsọdibiàmúsìn (colonialismo):
1. Ìmúgbòòrò, s. Expansão.
2. Ìkógun, s. Expropriação
3. Ìpakúpa, s. Extermínio.
4. Ìfiniṣẹrú, s. Escravidão.
5. Ìyọkúrò, ìmújáde, s. Extração.
6. Iṣẹ́ wíwàásù ìhìn rere, iṣẹ́ ìjíhìnrere, s. Evangelização.
Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.
Nenhum comentário:
Postar um comentário