Lítíréṣọ̀, iṣẹ́ọnàmọ̀ọ́kọmọ̀ọ́kà (literatura)
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário).
Ewì, s. Poesia.
Olùkọ̀wé, s. Escritor.
Òṣeré, s. Ator.
Àwòrán kíkùn, akun àwòrán, s. Pintura.
Ìgbésíayé, s. Biografia.
Tíátà, s. Teatro.
Aláwàdà, s. Comediante.
Orin, s. Música.
Orin jùjú, jùjú, s. Juju. É um estilo de música popular nigeriana, derivada da tradicional Música yorubá de percussão.
Orin fújì, s. Fuji. É um gênero musical popular nigeriano.
Oníṣọ̀nà, s. Artista.