quinta-feira, 21 de junho de 2018

A seleção brasileira

Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ ti àwọn òmùgọ̀ òkúùgbẹ́  ti orílẹ̀ èdè Bràsíl!                            
A seleção dos vira-latas brasileiros!






Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).


Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀, s. Seleção, time de futebol.
Agbábọ́ọ̀lù, agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀, s.  Jogador de futebol.
Òmùgọ̀ òkúùgbẹ́, s. Tolo desprezível.
Òmùgọ̀, s. Cabeça oca, tolo.
Ohun ìtẹ́ńbẹ́lú, s.  Algo desprezível.
Ohun aláìníláárí, s. Algo sem valor. 
Ẹnikẹ́ni tí kò ní láárí, s. Alguém sem valor.
Ẹni tí kò wúlò fún nǹkan kan lonítọ̀hún, s. Pessoa que é moralmente desprezível, pessoa que não tem utilidade para alguma coisa.
Ẹnì tó jẹ́ àjèjì, s. Pessoa alienada.
Tó jẹ́ àjèjì, adj. Alienado.
Àwọn tí kò ní làákàyè, s.  Pessoas sem consciência crítica.
Àwọn arìndìn, s. Estúpidos. 
Àwọn aláìmọ̀kan, s. Ignorantes.
Aláìmòye, aláìmọ̀kan, s. Ignorante.
Àwọn tó ń gbé nínú àwọn ilé hẹ́gẹhẹ̀gẹ, s. Favelados.
Aláìníṣẹ́, s. Desempregado.
Láìka ẹ̀yà, s. Sem distinção de raça.
Játijàti, adj. Avarento, mesquinho, imprestável, inútil, desprezível.
Tí kò ní láárí, adj. Que não tem valor.
Láìníláárí, adj. Sem importância, insignificante, vira-lata.
Láì ẹ̀yà pàtó, adj. Vira-lata, sem raça definida.
Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ ọmọorílẹ̀-èdè Bràsíl, s. Seleção Brasileira de Futebol.
Orílẹ̀-èdè BràsílIlẹ̀ Bràsíl, Bràsíl, s. Brasil, Pindorama.
Orílẹ̀-èdè Olómìnira Aparapọ̀ ilẹ̀ Bràsíl, s. República Federativa do Brasil.
Orílẹ̀-èdè, s. Nação, país.
Orílẹ̀, s. Grupo de origem ou clã.
Èdè, s. Língua, idioma, dialeto, linguagem.
Olómìnira, adj. Independente.
Àpapọ̀, s. Soma, total, combinação, ato de unir, de juntar
Aparapọ̀, adj. Federativa.
Ọmọorílẹ̀-èdè Bràsíl, ọmọ ilẹ̀ Bràsíl, ọmọkùnrin ilẹ̀ Bràsíl, s. Brasileiro.
Ọmọkùnrin ilẹ̀ Bràsíl, s. Brasileiro do sexo masculino.
Ọmọbìnrin ilẹ̀ Bràsíl, s. Brasileira.

Ní ti Bràsíl, ti orílẹ̀ èdè Bràsíl, adj. Brasileiro.

Mi, pron. oblíquo. Me, mim, comigo.
Èmi, mo, mi, n, ng, pron. pess. Eu.

Ìwọ, o, pron. pess. Você. Ìwọ yíò rí mi nínú àwọn ìjì líle - Você me encontrará nas tempestades.
Òun, ó, pron. pess. Ele, ela.
Àwa, a, pron. pess. Nós.
Ẹ̀yin, , pron. pess. Vocês.
Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; nente caso, é posicionado antes do substantivo.
Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.
Wọn, pron. poss. Deles, delas.
Ó, pron. pess. Ele, ela.
O, pron. pess. Você. 
, pron. Você. É usado dessa forma depois de verbo ou preposição.
O, ò, pref. Adicionado ao verbo para formar substantivos que indicam alguém que faz.

O, òo, part. adv. 1. Forma frases exclamativas para ênfase. Ó ti dé o! - Ele já chegou! 2. A forma òo é usada para responder a uma saudação, caso não exista outra estabelecida, ou para concordância diante de uma outra expressão. Ẹ káalẹ́ o - Boa-noite; Òo (respondendo).
Ti lọ, adj. Desaparecido.
, pron. rel. Que, o qual, do qual, cujo.
, conj. Se. Enquanto, ao mesmo tempo que.
, prep. Desde que.
, v. Bater com a mão ou com algo na mão, acertar o alvo.
, adv. Onde, quando.
Ti, prep. de ( indicando posse). Quando usado entre dois substantivos, usualmente é omitido. Ilé ti bàbá mi = ilé bàbá mi ( A casa do meu pai).
Ti, ti...ti, adj. Ambos... e. Ti èmi ti ìyàwó mi - ambos, eu e minha esposa.
Ti, v. Ter (verb. aux.). Arranhar. Pular.
Ti, v. interrog. Como. Ó ti jẹ́? - Como ele está.
Ti, adv. pré-v. Já. Indica uma ação realizada.
Ti, àti, conj. E.
Ti, part. pré-v. 1. Usada para indicar o tempo passado dos verbos. Èmi ti máa rìn lálé - Eu costumava caminhar à noite. 2. É usada com báwo ni - como - quando se deseja expressar sentimento e posicionada antes do verbo principal. Báwo ni àwọn ti rí? - Como eles estão?.
Tìti, adv. Tremendamente, violentamente.
Títí, adv. Continuamente, constantemente.
Títí, prep. Até.
Tìtì, adv. Tremulamente, balançadamente.
Títì, adj. Trancado, que deve ser empurrado, fechado.
Títì, ọ̀nà, s. Via pública, rua, passagem.
Ti... ti, adj. Ambos... e. Ti èmi ti ìyàwó mi - Ambos, eu e minha esposa.
Títi-àiyé, adv. Eternamente.
Títí dé, prep. Até. (referindo-se a um local ou espaço).
Títí di, prep. Até. (referindo-se a período de tempo).
Títí  láé, títí láí, adv. Perpetuamente, para sempre, definitivamente.

Títilọ, adv. Continuadamente, assim por diante.


quarta-feira, 20 de junho de 2018

Renato Noguera

Ohùn àfetígbọ́ lórí ìmọ̀ ọgbọ́n orí àwọn ọmọ ilẹ̀ Áfíríkà.
Áudio sobre filosofia africana.
                                                          



Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).

Fídíò, fídéò, s. Vídeo.
Ohùn àfetígbọ́, s. Áudio. Bákan náà, wọ́n kọ́ yàrá ìgbóhùn sílẹ̀ fún ẹ̀ka tó ń gba ohùn àti àwòrán sílẹ̀ àti ẹ̀ka tó ń bójú tó Èdè Adití, wọ́n sì dá ẹ̀ka tó ń ṣe ìwé àwọn afọ́jú sílẹ̀ - Além disso, o Áudio e Vídeo e a Língua de Sinais ganharam novos estúdios, e foi iniciada a transcrição para o braile.
Ìtẹ̀jáde tá a gbohùn, s. Publicação de Áudio 
Àwọn ìtẹ̀jáde tá a gbohùn wọn sílẹ̀, s. Publicações em áudio.
Fífi ariwo rédíò ọkọ̀ díje, s. Rachas” de áudio.
Pípo ohùn pọ̀, s. Mixagem de áudio.
Ohùn tá a gbà sílẹ̀ sórí kásẹ́ẹ̀tì, s. Gravação de áudio. Lára wọn ni àwọn ìwé, ìwé ìròyìn, ìwé pẹlẹbẹ, ìwé ìléwọ́, ìwé àṣàrò kúkúrú, ohùn tá a gbà sílẹ̀ sórí kásẹ́ẹ̀tì àti fídíò - Essas incluem livros, revistas, brochuras, convites, tratados e gravações de áudio e vídeo.
Mílíọ̀nù méjìlélógún, num. 22 milhões.  Mílíọ̀nù méjìlélógún ohun àtẹ́tígbọ́ - 22 milhões de faixas de áudio.
Filọ́sọ́fi ti Áfríkà, ìmọ̀ ọgbọ́n orí àwọn ọmọ ilẹ̀ Áfíríkà, s. Filosofia africana.
Ìmọ̀ ọgbọ́n orí àwọn Gíríìkì, s. Filosofia grega.
 Ìwé àpókírífà, s. Livro apócrifo.
Ẹ̀kọ́ ojoojúmọ́, s. Ensino diário.
Ẹsẹ Ìwé Mímọ́, s. Texto bíblico.
Ìjíròrò ẹ̀kọ́ ojoojúmọ́, s. Considerações do texto diário, discussão do texto, discussão diária.
Ìwé tó kọ, s. Escrito.
Nípa, nípasẹ̀, adv. Sobre, acerca de, concernente a.
Kọjá, prep. Sobre, além de. 
Ní orí, lórí, lérí, prep. Sobre, em cima de, cerca de, acerca de, a respeito de. Níbi Àpérò Ìjọba Lórí Híhùwà Ipá sí Àwọn Obìnrin, èyí tó wáyé ní orílẹ̀-èdè Sípéènì ní ìbẹ̀rẹ̀ ọdún 2002 -  No Congresso Ministerial sobre a Violência contra as Mulheres, realizado na Espanha no início do ano de2002
Lórísórí, prep. Em, por, ao. sobre. 
Sórí, prep. Para cima de. 
Nípati, prep. Conforme. 
Lókè, ní òkè, prep. Acima, no alto de.
Áfríkà, Áfíríkà, s. África.

Ọgbọ́n, s. Sabedoria, senso, arte.
Ìmọ̀, s. cultura, saber. conhecimento.
Ìjìnlẹ̀, s. Profundidade, intensidade.

Sáyẹ́nsì, ìmọ̀ ìjìnlẹ̀, s. Ciência.
Orí, s. Cabeça.
Àwọn, wọ́n, pron. pess. Eles, elas. Indicador de plural.
Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.
Wọn, pron. poss. Deles, delas.

Ọmọorílẹ̀-èdè Bràsíl, ọmọ ilẹ̀ Bràsíl, ọmọkùnrin ilẹ̀ Bràsíl, s. Brasileiro.
Ọmọkùnrin ilẹ̀ Bràsíl, s. Brasileiro do sexo masculino.
Ọmọbìnrin ilẹ̀ Bràsíl, s. Brasileira.
Ní ti Bràsíl, ti orílẹ̀ èdè Bràsíl, adj. Brasileiro.

Àwọn ará, s. Parentes, irmãos, habitantes de uma região (irmandade, popular). Orílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ará ilẹ̀ Ṣáínà - República Popular da China.

Àwọn adúláwọ̀ ti ẹgbẹ́ aláṣẹ bóofẹ́bóokọ̀ ní'lẹ̀ Bràsíl, s. Negros de extrema direita no Brasil.
Ọmọ Áfíríkà Bòlífíà, s. Afroboliviano.
Ọmọkùnrin Áfíríkà Bòlífíà, s. Homem afroboliviano.
Ọmọbìnrin Áfíríkà Bòlífíà, s. Mulher afroboliviana.

Ní ti Áfríkà, ti orílẹ̀ èdè Áfríkà, adj. Africano.
Ọmọ ilẹ̀ Áfríkà, s. Africano.
Ọmọ kùnrin ilẹ̀ Áfríkà, s. Africano.
Ọmọbìnrin ilẹ̀ Áfríkà, s. Africana.
Ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà, aláwọ̀dúdú Ará Amẹ́ríkà, adúláwọ̀ ará Amẹ́ríkà, s. Afro-americano.
Ọmọ Áfríkà Ásíà, s. Afro-asiático.
Ọmọ Áfríkà Bràsíl, aláwọ̀dúdú ará Bràsíl, adúláwọ̀ ará Bràsíl, s. Afro-brasileiro.
Ọmọ Áfríkà Kàríbẹ́ánì, aláwọ̀dúdú ará Kàríbẹ́ánì, adúláwọ̀ ará Kàríbẹ́ánì, s. Afro-caribenho.
Ọmọ Áfríkà Kúbà, aláwọ̀dúdú ará Kúbà, adúláwọ̀ ará Kúbà, s. Afro-cubano.
Melanésíà, s. Melanésia.
Papua, s. Papua.
mọorílẹ̀-èdè papua, s. Papuásio. Natural de Papua-Nova Guiné.
Ní ti papua, adj. Papuásio. Relativo a Papua-Nova Guiné.
Ní ti Melanésia, adj. Melanésio.
Ọmọ ilẹ̀ Melanésia, s. Melanésio.
Ẹ̀yà ènìyàn tàmil, s. Etnia tâmil.
Ní ti tàmil, adj. Tâmil.
Ọmọ ilẹ̀ Tàmil Nadu, s. Tâmil.
Ọmọ ilẹ̀ Éṣíà dúdú, s. Asiático negro.
Ọmọorílẹ̀-èdè Íńdíà dúdú, s. Indiano negro.

Aláwọ̀funfun, s. Branco.
Òyìnbó, òyìbó, òìbó, s. O homem branco, o europeu.
Funfun, adj. Branco.

Ilẹ̀, s. Terra, solo, chão.
Ilẹ̀ Bràsíl, Bràsíl, s. Brasil, Pindorama.
Orílẹ̀-èdè Olómìnira Aparapọ̀ ilẹ̀ Bràsíl, s. República Federativa do Brasil.
Orílẹ̀-èdè, s. Nação, país.
Orílẹ̀, s. Grupo de origem ou clã.
Èdè, s. Língua, idioma, dialeto, linguagem.
Olómìnira, adj. Independente.
Àpapọ̀, s. Soma, total, combinação, ato de unir, de juntar
Aparapọ̀, adj. Federativa. 

Ẹlẹ́yàpúpọ̀, s. Indivíduo mestiço, colorido ou multirracial.
Adúláwọ̀, s. Negro.

Ènìyàn dúdú, s. Negro.
Dúdú, v. Ser preto.
Dúdú, adj. Negro.
Adúláwọ̀ ọkàn funfun, s. Negro de alma branca, negropeu, negro jabuticaba (preto por fora e branco por dentro).
Ẹ̀mí, s. Alma (vida representada pela respiração).
Yúróòpù, Yúrópù, s. Europa.

Ọ̀mọ̀, s.Uma árvore cuja madeira é utilizada para fazer o tambor bẹ̀mbẹ́. Cordia millenii (Boraginaceae).
Ọmọ, s. Filho, criança, descendência.
Ọmọbìnrin, s. Filha.
Ọmọkùnrin, s. Filho. 
Ọmọ àgbàbọ́, s. Filho adotivo.

Ọmọ àgbo, ọmọ ọwọ́, ọmọ ọmú, s. Bebê, criança.
Ọmọ aládé, s. Príncipe, princesa.
Ọmọ aláìloobiọmọ òkús. Órfão.
Ọmọ àlè, s. Bastardo, o filho da outra.
Ọmọbíbí, s. Nascimento de uma criança.
Ọmọdé, s. Criança.
Ọmọ̀dọ̀, s. Criada, serviçal.
Ọmọdọ́mọ, s. De criança em criança, de tempos em tempos.
Ọmọ ènìà, s. Ser humano, cavalheiro.
Ọmọ ẹ̀hìn, s. Discípulo, seguidor, aprendiz.
Ọmọge, s. Mulher jovem, criada.
Ọmọge ìbílẹ̀, mọ ìlú, s. Nativo da terra.
Ọmọ iléwé, akẹ́kọ̀ọ́, akẹ́kọ́, ọmọ ilé-ẹ̀kọ́, ọmọ-sùkúrùs. Aluno, estudante.
Ọmọ ìlú, s. Nativo da mesma cidade, nativo da mesma região.
Ọmọ jẹ́jẹ́, s. Criança fina, gentil.
Ọmọkọ́mọ, s. Qualquer criança, uma criança má.
Ọmọ làlà, s. O primeiro neto.
Ọmọlé, s. Grupo familiar.
Ọmọlẹ́hìn, s. Seguidor.
Ọmọlójú, s. Neto, menina dos olhos.
Ọmọlúwàbí, s. Pessoa de caráter, cavalheiro e educado.
Ọmọ ọba, s. Filho do rei, príncipe, princesa.
Ọmọnìkéjì, s. Companheiro, vizinho.
Ọmọ mọ, s. Neto.
Ọmọ-ọmú, s. Criança em fase de amamentação.
Ọmọpẹ́, s. Denominação de uma criança que passa dos nove meses de gestação.
Ọmọṣẹ́, s. Aprendiz de trabalho.
Ọmọ tuntun, s. Recém-nascido, bebê.
Ọmọ wáhàrí, s. Filho de uma escrava tomada como esposa.
Ọ̀mọ̀wé, s. Pessoa educada, sábia.
Ọ̀mọwẹ̀, s. Nadador.


Ìlómìnira látọwọ́ Pọ́rtúgàl, s. Independência de Portugal.


Marilena Chaui

 Àwùjọ abàṣẹwàá, ìwàwíwù àti ìwà ipá ní orílẹ̀-èdè Bràsíl.
Sociedade autoritária, ética e violência no Brasil.                                             




Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).

Àròjinlẹ̀ aláyẹ̀wò, s. Teoria crítica da sociedade.
Ìṣeọ̀rọ̀àwùjọ, s. Sociologia.
Abàṣẹwàá, apàṣẹwàá, s. Ditador. Ṣé apàṣẹwàá ni bàbá rẹ̀ tó fi jẹ́ pé ohun tó bá sọ pé kó ṣe ló gbọ́dọ̀ ṣe? - Podia contrariar a vontade do pai autoritário?
Ìjọba bóofẹ́-bóokọ̀, ìṣàkóso abàṣẹwàá, s. Ditadura. 
Òṣèlúaráìlú, ìjọba tiwa-n-tiwa, ìjọba àjùmọ̀ṣe, ìjọba tí ó fi àyè gba ará ìlú láti ní ìpín nínú ètò ìlú, s. Democracia.
Ìjọba àjùmọ̀ṣe, s.Governo de ação conjunta, governo de parceria.
Ìjọba tí ó fi àyè gba ará ìlú láti ní ìpín nínú ètò ìlú, s. Governo que permite e necessita que os cidadãos tenham parte na organização da cidade ou do país. 
Òṣèlúaráìlú òṣèlú aṣojú, s. Democracia representativa.
Orílẹ̀-èdè olómìnira, s. República.
Òṣèlú aláwùjọ, s. Social-democracia.
Àjọṣepọ̀, s. Federação.
Ìṣeolómìnira ijọ́hun, s. Republicanismo clássico.
Ọ̀làjú, s. Iluminismo, civilização.
Àwọn ọ̀tọ̀kùlú, s. Os nobres, aristocracia.
Àwọn sàràkí-sàràkí, àwọn ọ̀tọ̀kùlú, àwọn èèyàn jàǹkànjàǹkàn, s. Aristocracia. Àwọn sàràkí-sàràkí ìlú Jerúsálẹ́mù fẹ̀sùn kàn án pé ńṣe ló fèrú gba ipò, wọ́n sì rọ ìjọba Róòmù láti rọ̀ ọ́ lóyè - A aristocracia de Jerusalém considerava Herodes um usurpador e tentou convencer Roma a destituí-lo.
Àwùjọ, s. Sociedade.
Àwùjọ abàṣẹwàá, s. Sociedade autoritária.
Ìlànà lórí omi lílò, s. Ética da água.
Ọ̀fin, s. Lei, estatuto.
Ìwàwíwù, ìwà, ẹ̀kọ́ ìwà rere, s. Ética.
Ìwà, s.  Conduta, caráter, comportamento.
Ìwàrere, s. Boa conduta, um bom caráter.
Ẹ̀kọ́, s.  Aula, educação, instrução.
Wíwù, ẹwù, s. Prazer, agradabilidade.

Àwọn ọmọ tí òbí wọn bá ń fi ìfẹ́ bá wí, s. Filhos de pais que conseguem equilibrar o amor com a disciplina.
Ìwà ipá, s. Violência. Kí ló ń fa ìwà ipá yìí? - O que causa essa violência?
Ilẹ̀, s. Terra, solo, chão.
Orílẹ̀-èdè BràsílIlẹ̀ Bràsíl, Bràsíl, s. Brasil, Pindorama.
Orílẹ̀-èdè Olómìnira Aparapọ̀ ilẹ̀ Bràsíl, s. República Federativa do Brasil.
Orílẹ̀-èdè, s. Nação, país.
Orílẹ̀, s. Grupo de origem ou clã.
Èdè, s. Língua, idioma, dialeto, linguagem.
Olómìnira, adj. Independente.
Àpapọ̀, s. Soma, total, combinação, ato de unir, de juntar
Aparapọ̀, adj. Federativa.
Ọmọorílẹ̀-èdè Bràsíl, ọmọ ilẹ̀ Bràsíl, ọmọkùnrin ilẹ̀ Bràsíl, s. Brasileiro.
Ọmọkùnrin ilẹ̀ Bràsíl, s. Brasileiro do sexo masculino.
Ọmọbìnrin ilẹ̀ Bràsíl, s. Brasileira.

Ní ti Bràsíl, ti orílẹ̀ èdè Bràsíl, adj. Brasileiro. 
Orílẹ̀-Èdè Rússíà, Rọ́síà, s. Rússia.
Ìparapọ̀ Rọ́sìà, s. Federação Russa.

Ń, v. Estar. Indicador de  gerúndio.
Ń, adv. pré-verbal. O prefixo "ń" no verbo indica não só uma ideia presente como uma ação que esteja ocorrendo, em desenvolvimento (gerúndio). Pela sua função, é equivalente ao verbo auxiliar estar em português.
L', pref. No.
L, pref. Forma modificada da palavra ní quando seguida de palavra iniciada por vogal diferente de i.
, prep. Contração da preposição ní e substantivo. Quando a vogal inicial do substantivo não é i, a consoante n da preposição se transforma em l, e a vogal i toma forma de vogal do substantivo posterior. Mas se a vogal do substantivo é i, ela é eliminada. Ní àná ( l'ánàá ). Ní ilé (ní'lé)
, part. enfática. Usada na construção de frases, quando o verbo tiver dois objetos, o segundo objeto é precedido por " ní".
, prep. No, na, em. Usada para indicar o lugar em que alguma coisa está. Indica uma posição estática.
, v. Ter, possuir, dizer.Transportar carga em um barco ou navio. Ocupar, obter, pegar.
Ni, v. Ser, é.
, pron. dem. Aquele, aquela. Requer alongamento da vogal final da palavra que o antecede somente na fala. Ex.: Fìlà ( a ) nì = aquele chapéu.

, ( conj. pré-v.). E, além disso, também. Liga sentenças, porém, não liga substantivos; nesse caso, usar " àti". É posicionado depois do sujeito e antes do verbo.
Ti, àti, conj. E.
Àti, Conj. E. Usada entre dois nomes, mas não liga verbos. 
Pẹ̀lú, conj. E. Liga substantivos, mas não liga verbos.
Pẹ̀lú, prep. Com, junto com.
Pẹ̀lú, adv. Também.
Pẹ̀lú, v. Estar em companhia de, acompanhar.
Òun, ó, pron. pess. Ele, ela.
Òun, on, Conj. E. Geralmente usada com nomes de pessoas. Òjó on Àjàdí - Ojô e Ajadi.
Oun, ohun, s. Coisa, algo.
Oùn, ohùn, s. Voz.


segunda-feira, 18 de junho de 2018

Maria Cristina

Màríà Kristina, ìwọ gbọ́dọ̀ wákiri fún mi nínú àwọn ìjì líle.
Maria Cristina, procure por mim nas Tempestades.





Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).

Màríà, s. Maria. Lẹ́yìn náà ni Màríà di ìyàwó Jósẹ́fù - Depois disso, Maria se casou com José.
Màríà Kristina, s. Maria Cristina. 
Kristine, Kristina, s. Cristina. O nome Cristina é a variante feminina de Cristino, que tem o mesmo sentido que Cristiano. Cristiano tem origem no latim Christianus, derivado de christianu, que quer dizer literalmente “cristão”. ... Cristo, originado a partir do grego Christós, significa literalmente “o ungido”. “Bó bá ti ń di nǹkan bí aago méjì ọ̀sán, ó máa ń rẹ̀ mí gan-an débi pé mo lè sùn lọ níbi tí mo bá ti ń bá ẹnì kan sọ̀rọ̀!”—Kristine, ọmọ ọdún mọ́kàndínlógún [19] - “Por volta das 2 horas da tarde, estou tão cansada que quase chego a dormir no meio de uma conversa!” — Cristina, 19 anos.  Wo àpẹẹrẹ ohun tó ṣẹlẹ̀ sí Kristina - Veja o exemplo de Cristina.

Ìwọ, o, pron. pess. Você.
, pron. pess.Vocês. Forma alternativa de ẹ̀yin. É usado para demonstrar respeito quando se dirige a um senhor ou senhora, em qualquer tipo de expressão.
Ẹ̀yin, ẹ, pron. pess. Vocês.
E, pref. Adicionado ao verbo para formar substantivos que indicam ação e movimento. Rò - pensar; èrò - imaginação.
E, é, pron. da 3ª pessoa do singuar representado pela repetição da vogal final do verbo. Este procedimento é conhecido como o caso objetivo da 3ª pessoa Ò gé - Ele cortou; Ò gé e - Ele a cortou.

, pron. pess.Vocês. Forma alternativa de ẹ̀yin. É usado para demonstrar respeito quando se dirige a um senhor ou senhora, em qualquer tipo de expressão.
, pron. Você, com sentido formal e respeitoso. Usado depois de verbo e preposição.
Ẹ, ọ, pron. oblíquo. Você.
Ẹ kú, Exp. Inicia uma forma de cumprimento, desejando tudo de bom a uma ou várias pessoas. Ẹ kúu fàájì òpin ọ̀sẹ̀ o! - Bom final de semana!

, pref. Adicionado ao verbo para formar substantivos que indicam ação, movimento e sentimento. kọ́ (ensinar), Ẹ̀kọ́ (aula).
Ẹ́, pron. da 3ª pessoa do singular representado pela repetição da vogal final do do verbo. Este procedimento é conhecido como o caso objetivo da  3ª pessoa. Ó kẹ́ ẹ - Ele a acariciou. Ó gbẹ ẹ́ - Ele a secou.
Ẹ̀, ẹ, pron. poss. São formas opcionais de rẹ (seu, sua, de você) e rẹ̀ (dele, dela).
Ẹ̀ẹ̀, pref. Forma reduzida de ẹ́rìn ou ẹ̀rẹ̀ (vez), adicionada aos numerais para indicar o  número de vezes. Ẹ̀ẹ̀mẹ́ta (três vezes).
Ẹ ṣé!, expr. Obrigado! “Ẹ ṣé gan-an pé ẹ fara balẹ̀ gbọ́ mi.”- “OBRIGADO por ter me ouvido.”
Ẹ ṣe modupẹ oo!, expr. Obrigado!.
Ẹ ṣe é o!, expr. Cumprimento de agradecimento, obrigado.
Ẹ ṣeun!, expr. Obrigado! 
Ẹ ṣeun púpọ̀! expr. Muito obrigado! 

, v. Alcançar, ultrapassar, perseguir. Ajudar. Encontrar.
, prep. pré-v. Com, em companhia de.
, prep. Contra.
, adv. Nunca, absolutamente.

, v. Ver.  Achar, encontrar, descobrir, perceber. Tornar-se, obter, conseguir, adquirir. Ser, parecer. 
, adv. Nunca, anteriormente, em qualquer época atrás, antes de.
, part. Usada no fim da frase para dar ênfase.

, v. Afundar, submergir, encobrir. Esconder, ocultar, escavar dentro.

Yíò, yóò, part. pré-v. É uma das alternativas para formar o tempo futuro dos verbos.
Yóò, adv. pré. v. Indicador de futuro numa frase afirmativa. Em outras palavras, emprega-se o futuro do presente para expressar uma ação que será executada no futuro. Outros indicadores de futuro: yóó, ó, á, máa, fẹ́.
Máa, part. v. Usada como outra opção para marcar o tempo futuro do verbo, admitindo o pronome pessoal de uma sílaba.
Máa, v. aux. Indica uma ação habitual, costumeira.
Máa ń, a máa, adv. pré v. Ter costume de, estar acostumado, ter maneira de (fazer algo). Emprega-se o presente do indicativo para expressar uma ação constante ou habitual.
Máa, maa, obs. : Colocado antes do verbo, dá um sentido polido a uma ordem.

Gbọ́dọ̀, v. aux. Dever, arriscar, precisar, ousar.
Wákiri, v. Procurar, solicitar. 
Fún, prep. Para, em nome de (indica uma intenção pretendida para alguém).
Fún, v. Dar. Espremer, apertar, extrair. Espalhar, desperdiçar, empurrar para os outros. Espirrar, assoar.
Fun, v. Ser branco. Soprar, ventar.

Mi, pron. oblíquo. Me, mim, comigo.
Èmi, mo, mi, n, ng, pron. pess. Eu.
Ìwọ, o, pron. pess. Você. Ìwọ yíò rí mi nínú àwọn ìjì líle - Você me encontrará nas tempestades.
Òun, ó, pron. pess. Ele, ela.
Àwa, a, pron. pess. Nós.
Ẹ̀yin, , pron. pess. Vocês.
Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; nente caso, é posicionado antes do substantivo.
Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.
Wọn, pron. poss. Deles, delas.
Ó, pron. pess. Ele, ela.
O, pron. pess. Você. 
, pron. Você. É usado dessa forma depois de verbo ou preposição.
O, ò, pref. Adicionado ao verbo para formar substantivos que indicam alguém que faz.
O, òo, part. adv. 1. Forma frases exlamativas para ênfase. Ó ti dé o! - Ele já chegou! 2. A forma òo é usada para responder a uma saudação, caso não exista outra estabelecida, ou para concordância diante de uma outra expressão. Ẹ káalẹ́ o - Boa-noite; Òo (respondendo).

Nínú, prep. Dentro, no interior de.
Inú, s. Estômago, ventre, interior, interno, no íntimo de.

Ń, v. Estar. Indicador de  gerúndio.
Ń, adv. pré-verbal. O prefixo "ń" no verbo indica não só uma ideia presente como uma ação que esteja ocorrendo, em desenvolvimento (gerúndio). Pela sua função, é equivalente ao verbo auxiliar estar em português.
L', pref. No.
L, pref. Forma modificada da palavra ní quando seguida de palavra iniciada por vogal diferente de i.
, prep. Contração da preposição ní e substantivo. Quando a vogal inicial do substantivo não é i, a consoante n da preposição se transforma em l, e a vogal i toma forma de vogal do substantivo posterior. Mas se a vogal do substantivo é i, ela é eliminada. Ní àná ( l'ánàá ). Ní ilé (ní'lé)
, part. enfática. Usada na construção de frases, quando o verbo tiver dois objetos, o segundo objeto é precedido por " ní".
, prep. No, na, em. Usada para indicar o lugar em que alguma coisa está. Indica uma posição estática.
, v. Ter, possuir, dizer.Transportar carga em um barco ou navio. Ocupar, obter, pegar.
Ni, v. Ser, é.
, pron. dem. Aquele, aquela. Requer alongamento da vogal final da palavra que o antecede somente na fala. Ex.: Fìlà ( a ) nì = aquele chapéu.

Ìjì, s. Ventania marítima, tempestade marítima.
Ẹ̀fúùfù líle, ẹ̀fúùfù ńlá, ìjì, s. Tempestade.

Òbí, oobi, s. Família biológica, os parentes carnais, pai e mãe, pais. Nítorí pé o ń bẹ̀rù pé àwọn òbí rẹ lè fẹ́ wá mú ọ padà sílé, o lè máa lọ́ tìkọ̀ láti jẹ́ kí wọ́n mọ nǹkan tó ń ṣẹlẹ̀ - Temendo que seus pais venham buscá-lo para levá-lo de volta para casa, você talvez hesite em contar-lhes a verdade. 

Ilé ìwòsàn, s. Hospital. Ìṣòro Joel burú sí i, a sì ní láti tètè dá a pa dà sílé ìwòsàn - O estado de saúde de Joel piorou e tivemos de levá-lo de volta para o hospital.

Rússia

 Tí o bá wá mi dé'lé t'ẹ́ ò rí mi, mo rọ́ọ̀ṣì lọ sí Orílẹ̀-Èdè Rússíà ni.

Se você me procurar em casa e não me encontrar, eu fui à Rússia.

Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).

Ti lọ, adj. Desaparecido.
, pron. rel. Que, o qual, do qual, cujo.
, conj. Se. Enquanto, ao mesmo tempo que.
, prep. Desde que.
, v. Bater com a mão ou com algo na mão, acertar o alvo.
, adv. Onde, quando.
Ti, prep. de ( indicando posse). Quando usado entre dois substantivos, usualmente é omitido. Ilé ti bàbá mi = ilé bàbá mi ( A casa do meu pai).
Ti, ti...ti, adj. Ambos... e. Ti èmi ti ìyàwó mi - ambos, eu e minha esposa.
Ti, v. Ter (verb. aux.). Arranhar. Pular.
Ti, v. interrog. Como. Ó ti jẹ́? - Como ele está.
Ti, adv. pré-v. Já. Indica uma ação realizada.
Ti, àti, conj. E.
Ti, part. pré-v. 1. Usada para indicar o tempo passado dos verbos. Èmi ti máa rìn lálé - Eu costumava caminhar à noite. 2. É usada com báwo ni - como - quando se deseja expressar sentimento e posicionada antes do verbo principal. Báwo ni àwọn ti rí? - Como eles estão?.
Tìti, adv. Tremendamente, violentamente.
Títí, adv. Continuamente, constantemente.
Títí, prep. Até.
Tìtì, adv. Tremulamente, balançadamente.
Títì, adj. Trancado, que deve ser empurrado, fechado.
Títì, ọ̀nà, s. Via pública, rua, passagem.
Ti... ti, adj. Ambos... e. Ti èmi ti ìyàwó mi - Ambos, eu e minha esposa.
Títi-àiyé, adv. Eternamente.
Títí dé, prep. Até. (referindo-se a um local ou espaço).
Títí di, prep. Até. (referindo-se a período de tempo).
Títí  láé, títí láí, adv. Perpetuamente, para sempre, definitivamente.
Títilọ, adv. Continuadamente, assim por diante.

Ìwọ, o, pron. pess. Você.
, pron. pess.Vocês. Forma alternativa de ẹ̀yin. É usado para demonstrar respeito quando se dirige a um senhor ou senhora, em qualquer tipo de expressão.
Ẹ̀yin, ẹ, pron. pess. Vocês.
E, pref. Adicionado ao verbo para formar substantivos que indicam ação e movimento. Rò - pensar; èrò - imaginação.
E, é, pron. da 3ª pessoa do singuar representado pela repetição da vogal final do verbo. Este procedimento é conhecido como o caso objetivo da 3ª pessoa Ò gé - Ele cortou; Ò gé e - Ele a cortou.

, pron. pess.Vocês. Forma alternativa de ẹ̀yin. É usado para demonstrar respeito quando se dirige a um senhor ou senhora, em qualquer tipo de expressão.
, pron. Você, com sentido formal e respeitoso. Usado depois de verbo e preposição.
Ẹ, ọ, pron. oblíquo. Você.
Ẹ kú, Exp. Inicia uma forma de cumprimento, desejando tudo de bom a uma ou várias pessoas. Ẹ kúu fàájì òpin ọ̀sẹ̀ o! - Bom final de semana!

, pref. Adicionado ao verbo para formar substantivos que indicam ação, movimento e sentimento. kọ́ (ensinar), Ẹ̀kọ́ (aula).
Ẹ́, pron. da 3ª pessoa do singular representado pela repetição da vogal final do do verbo. Este procedimento é conhecido como o caso objetivo da  3ª pessoa. Ó kẹ́ ẹ - Ele a acariciou. Ó gbẹ ẹ́ - Ele a secou.
Ẹ̀, ẹ, pron. poss. São formas opcionais de rẹ (seu, sua, de você) e rẹ̀ (dele, dela).
Ẹ̀ẹ̀, pref. Forma reduzida de ẹ́rìn ou ẹ̀rẹ̀ (vez), adicionada aos numerais para indicar o  número de vezes. Ẹ̀ẹ̀mẹ́ta (três vezes).
Ẹ ṣé!, expr. Obrigado! “Ẹ ṣé gan-an pé ẹ fara balẹ̀ gbọ́ mi.”- “OBRIGADO por ter me ouvido.”
Ẹ ṣe modupẹ oo!, expr. Obrigado!.
Ẹ ṣe é o!, expr. Cumprimento de agradecimento, obrigado.
Ẹ ṣeun!, expr. Obrigado! 
Ẹ ṣeun púpọ̀! expr. Muito obrigado! 

, v. Alcançar, ultrapassar, perseguir. Ajudar. Encontrar.
, prep. pré-v. Com, em companhia de.
, prep. Contra.
, adv. Nunca, absolutamente.

, v. Vir. Procurar por, buscar, vasculhar. Tremer de nervoso. Dividir, partir em pequenos pedaços.
, v. Ser, haver, existir, estar.
, V. Cavar. Remar, dirigir. Abraçar, prender, apertar . Monopolizar.
Wà, àwa, pron. pess. Você.
Wa, pron. oblíquo. Nos, conosco. Possui função reflexiva e é posicionado depois de verbo e preposição.
Wa, pron. poss. Nosso, nossa.

Mi, pron. oblíquo. Me, mim, comigo.
, v. Chegar. 
, prep. Até. Quando indicar um local,  é antecedido por títí. Mo rìn títí dé ilé mi - Eu andei até minha casa.
, part.É usada entre duas palavras repetidas para dar o sentido de vir, de chegar. Ìran - geração > Ìradéran - de geração em geração.
, v. Unir, ligar, apertar.
, prep. Por.

Ilé, s. Casa.
Kò sí, v. Forma negativa do verbo wà (estar, existir, haver). Kò sí owó kò sí orò - sem dinheiro não há obrigação.
Kò, ò, adv. Não. Faz a negativa dos verbos regulares. 

Bẹ́ẹ̀ni, adv. Sim, assim é. Inicia uma resposta afirmativa.
Rárá, adv. Não, nunca, absolutamente.
Ràrá, aràrá, s. Anão, pigmeu.
Rárà, s. Canção, elegia, poesia.
Rara, v. Esfregar o corpo.
Rara, adv. Ruidosamente. 

, v. Ver.  Achar, encontrar, descobrir, perceber. Tornar-se, obter, conseguir, adquirir. Ser, parecer. 
, adv. Nunca, anteriormente, em qualquer época atrás, antes de.
, part. Usada no fim da frase para dar ênfase.

, v. Afundar, submergir, encobrir. Esconder, ocultar, escavar dentro.
Orílẹ̀-èdè tó ṣẹ̀ṣẹ̀ ń gòkè àgbà, s. País em desenvolvimento.
Kò ń, ò ń, kì í, kò kì í, ò kì í, kò kì ń, ò kì ń, adv. pré. v. Não ter o costume de, não estar acostumado a, não ter maneira de fazer algo. Estes advérbios pré-verbais negam à ação habitual no presente do indicativo do tempo negativo. Em outra palavras, revelam uma ação que não será executada no futuro.
Bí ...bá ti, adv. Tanto tempo quanto, como, quando.
Bí... bá, v. aux. Expressa uma condição indefinida.
, prep. Como, da mesma forma que.
, v. 1. Perguntar, indagar de alguém, comunicar. Também usado para formar frases interrogativas; nesse caso, é posicionado no fim da frase. 2. Entregar, distribuir. 3. Gerar, dar nascimento a. 4. Estar zangado, aborrecer.
, conj. v. aux. Se. Indica uma condição.

Ilẹ̀, s. Terra, solo, chão.
Ilẹ̀ Bràsíl, Bràsíl, s. Brasil, Pindorama.
Orílẹ̀-èdè Olómìnira Aparapọ̀ ilẹ̀ Bràsíl, s. República Federativa do Brasil.
Orílẹ̀-èdè, s. Nação, país.
Orílẹ̀, s. Grupo de origem ou clã.
Èdè, s. Língua, idioma, dialeto, linguagem.
Olómìnira, adj. Independente.
Àpapọ̀, s. Soma, total, combinação, ato de unir, de juntar
Aparapọ̀, adj. Federativa.

Ọmọorílẹ̀-èdè Bràsíl, ọmọ ilẹ̀ Bràsíl, ọmọkùnrin ilẹ̀ Bràsíl, s. Brasileiro.
Ọmọkùnrin ilẹ̀ Bràsíl, s. Brasileiro do sexo masculino.
Ọmọbìnrin ilẹ̀ Bràsíl, s. Brasileira.

Ní ti Bràsíl, ti orílẹ̀ èdè Bràsíl, adj. Brasileiro. 
Orílẹ̀-Èdè Rússíà, Rọ́síà, s. Rússia.
Ìparapọ̀ Rọ́sìà, s. Federação Russa.
Màríà, s. Maria. Lẹ́yìn náà ni Màríà di ìyàwó Jósẹ́fù - Depois disso, Maria se casou com José.
Màríà Kristina, s. Maria Cristina. 
Kristine, Kristina, s. Cristina. O nome Cristina é a variante feminina de Cristino, que tem o mesmo sentido que Cristiano. Cristiano tem origem no latim Christianus, derivado de christianu, que quer dizer literalmente “cristão”. ... Cristo, originado a partir do grego Christós, significa literalmente “o ungido”. “Bó bá ti ń di nǹkan bí aago méjì ọ̀sán, ó máa ń rẹ̀ mí gan-an débi pé mo lè sùn lọ níbi tí mo bá ti ń bá ẹnì kan sọ̀rọ̀!”—Kristine, ọmọ ọdún mọ́kàndínlógún [19] - “Por volta das 2 horas da tarde, estou tão cansada que quase chego a dormir no meio de uma conversa!” — Cristina, 19 anos.  Wo àpẹẹrẹ ohun tó ṣẹlẹ̀ sí Kristina - Veja o exemplo de Cristina.
Ṣọ́ọ̀ṣì, s. Igreja.
Rọ́, v. Fazer um barulho, fazer um estrondo. Narrar, relatar. Agrupar, congregar. Deslocar , ser elástico.
Èmi, mo, mi, n, ng, pron. pess. Eu.
Ìwọ, o, pron. pess. Você.
Òun, ó, pron. pess. Ele, ela.
Àwa, a, pron. pess. Nós.
Ẹ̀yin, , pron. pess. Vocês.

Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; nente caso, é posicionado antes do substantivo.
Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.
Wọn, pron. poss. Deles, delas.

Ó, pron. pess. Ele, ela.
O, pron. pess. Você. 
, pron. Você. É usado dessa forma depois de verbo ou preposição.
O, ò, pref. Adicionado ao verbo para formar substantivos que indicam alguém que faz.
O, òo, part. adv. 1. Forma frases exlamativas para ênfase. Ó ti dé o! - Ele já chegou! 2. A forma òo é usada para responder a uma saudação, caso não exista outra estabelecida, ou para concordância diante de uma outra expressão. Ẹ káalẹ́ o - Boa-noite; Òo (respondendo).

Ṣì, v. adv. pré.v. Ainda, até o presente, durante algum tempo.
Ṣì, v. Perder, errar. Ser pálido.
Ṣí, v. Abrir, descobrir, destampar. Movimentar. Calcular.
Ṣii, adv. Durante algum tempo.
, prep. Para, em direção a. Indica movimento direcional.
, adv. Exatamente, indica uma situação exata e pontual.
, adv. Usado no fim de uma frase afirmativa a fim de indicar adição um pouco mais da conta. Mo fẹ́ jẹun sí - Eu quero comer mais.
, part. Usada entre duas palavras repetidas para dar o sentido de lá e cá. Ìlúsílú - de cidade em cidade.
, v. Forma negativa do verbo wà (existir, haver, estar). É precedido por kò. Kò sí ewu - Não há perigo.

, v. Descolorir, desbotar. Verbo com sentido de descer, descambar, e usado em certas composições. Ara rẹ̀  silẹ̀ - O corpo dele esfriou (depois da febre). Ó sì í délẹ̀ - Ele destruiu isto.
Sì, ṣì, adv. pré.v. Ainda, além disso. Má sìlọ - Não vá ainda.
Sii, adv. Por algum tempo.
Síi, adv. Mais do que, aumentar. Usado como complemento de verbo. Owó mi wú síi - Meu dinheiro aumentou mais do que antes.
Sìì, adv. Vagarosamente, forçadamente. Ó nrìn sìì - Ele correu vagarosamente.

Ń, v. Estar. Indicador de  gerúndio.
Ń, adv. pré-verbal. O prefixo "ń" no verbo indica não só uma ideia presente como uma ação que esteja ocorrendo, em desenvolvimento (gerúndio). Pela sua função, é equivalente ao verbo auxiliar estar em português.
L', pref. No.
L, pref. Forma modificada da palavra ní quando seguida de palavra iniciada por vogal diferente de i.
, prep. Contração da preposição ní e substantivo. Quando a vogal inicial do substantivo não é i, a consoante n da preposição se transforma em l, e a vogal i toma forma de vogal do substantivo posterior. Mas se a vogal do substantivo é i, ela é eliminada. Ní àná ( l'ánàá ). Ní ilé (ní'lé)
, part. enfática. Usada na construção de frases, quando o verbo tiver dois objetos, o segundo objeto é precedido por " ní".
, prep. No, na, em. Usada para indicar o lugar em que alguma coisa está. Indica uma posição estática.
, v. Ter, possuir, dizer.Transportar carga em um barco ou navio. Ocupar, obter, pegar.
Ni, v. Ser, é.
, pron. dem. Aquele, aquela. Requer alongamento da vogal final da palavra que o antecede somente na fala. Ex.: Fìlà ( a ) nì = aquele chapéu.

Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; nente caso, é posicionado antes do substantivo.
Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.
Wọn, pron. poss. Deles, delas.

Bẹ̀rẹ̀, v. Começar, iniciar.
Bẹ̀rẹ̀ sí, v.  Iniciar a, começar a. Tẹ́túlọ́sì bẹ̀rẹ̀ sí fẹ̀sùn kàn án - Tértulo começou a acusá-lo.

Ọ̀rọ̀, s. Palavra, texto, assunto, expressão. Kí Ni Ìtumọ̀ Ọ̀rọ̀ Náà? - Qual é o significado da palavra?
Àwọn àkámọ́ kọrọdọ, s. Parênteses. A kì í sábà ka àwọn ìtọ́ka kan tó bá wà nínú àwọn àkámọ́ kọrọdọ, bẹ́ẹ̀ pẹ̀lú ni kò sídìí láti yí ohùn padà tí a bá ń ka ọ̀rọ̀ inú àkámọ́ onígun tá a bá fi parí ìtumọ̀ ọ̀rọ̀ inú ìwé tí à ń kà - As fontes de referência entre parênteses não precisam ser lidas, e não há necessidade de mudar o tom da voz ao ler as palavras entre colchetes cuja função é completar o sentido da leitura.
Àmì àyọlò, s. Aspas. Àmì àyọlò (“ “ tàbí ‘ ‘) ó lè fi hàn pé kéèyàn dánu dúró díẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀ àti ìparí ọ̀rọ̀ tí a bá fi yà sọ́tọ̀ (ìdánudúró díẹ̀ ṣíún ni o, tó bá wà láàárín ọ̀rọ̀; àmọ́ tó bá wà ní ìparí ọ̀rọ̀, a óò túbọ̀ dánu dúró pẹ́ díẹ̀) - Aspas (“ ” ou ‘ ’) podem indicar que as palavras delimitadas por elas devem ser lidas com pausas antes e depois do trecho (pausas bem breves se as palavras fizerem parte de um texto; mais longas no caso de uma declaração completa).
Lédè Gẹ̀ẹ́sì, prep. + s. Em inglês.
Dojúkọ, v. Confrontar, abordar.
Àtakò, ìtakò, s. Oposião, resistência.
Irú, s. tipo, espécie, gênero, raça.
Yìí, yí, pron. dem. Este, esse, esta, essa, isto, isso. Forma reduzida de èyí.
Ìwọ̀ Oòrùn Yúróòpù, Apáìwọ̀òrùn Yúróòpù, s. Europa Ocidental.
Ìlà Oòrùn Yúróòpù, Apáìlàoòrùn Yúróòpù, s.  Europa Oriental. 
Ìwọ̀ Oòrùn, s. Oeste, Ocidente.
Ìlà Oòrùn, s. Leste, Oriente.
Yúróòpù, s. Europa.
Ìjọba Násì, s. Nazismo.
Ìjọba Kọ́múníìsì, s. Governo comunista.
Ìsọ̀kan àwọn Orílẹ̀-èdè Olómìnira Sófíẹ́tì Sósíálístì, s. União das Repúblicas Socialistas Soviéticas
Ìsọ̀kan Sófìẹ̀tì, s. União Soviética.
Lòdì sí òṣèlúaráìlú, adj. Antidemocrático.
Ìṣekọ́múnístì, s. Comunismo.
Ìjọba àjùmọ̀ṣe, s. Democracia. 
Ìṣekápítálístì, ìṣeòwòèlé, s. Capitalismo.
Ìṣesósíálístì, s. Socialismo.
Ìjọba ológun, s. Ditadura militar, governo militar.
Ẹgbẹ́ kọ́múnístì, s. Partido comunista.
Aṣekọ́múnístì, s. Comunista.
Ìṣeàìlólórí, s. Anarquismo.
Ìṣesósíálístì ti ọ̀rọ̀ lásán àròsọ, s. Socialismo utópico.
Ìṣesósíálístì ti sáyẹ́nsì, s. Socialismo científico.
Ìṣeohunayé ti ìtàn, s. Materialismo histórico.
Ìjídìde proletárì, s. Revolução proletária.
Ìmúnisìn tipátipá, ìjọba ìmúnisìn tipátipá, s. Totalitarismo (hitlerismo, fascismo, nazismo, nacional-socialismo).
Ìjọba Aláṣẹ Oníkùmọ̀, s. Facismo.
Nípa ará ìlúdídi ará ìlú, àyèọmọìlú, s. Cidadania.
Ọmọ ìlú, ará ìlú, ọlọ̀tọ̀, onílú, s.  Cidadão.