Àwọn eré-ìdárayá
1- Àwọn eré-ìdárayá, s. Desportos. Àwọn eléré-ìdárayá ará Amẹ́ríkà - Desportistas dos Estados Unidos.
2 - Bọ́ọ̀lù-alápẹ̀rẹ̀, básíkẹ́tbọlù, s. Basquetebol. Àwọn agbábọ́ọ̀lù alápẹ̀rẹ̀ ará Amẹ́ríkà - Basquetebolistas dos Estados Unidos
3 - Bọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀, s. Futebol. Àwọn agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ - Futebolistas.
4 - Àwọn Ìdíje Òlímpíkì, s. Jogos Olímpicos. Àwọn Ìdíje Òlímpíkì Ìgbà Oru - Jogos Olímpicos de Verão.
5 - Tẹ́nìs, s. Ténis.
Àwọn agbá tẹ́nìs, s. Tenistas. Àtòjọ àwọn onítẹ́nìs ATP ẹnìkan onípò kínní - Lista de tenistas número 1 no ranking da ATP.
Àwọn ìdíje tẹ́nìs, s. Competições de ténis. Àtòjọ àwọn onítẹ́nìs WTA onípò kínní - Lista de tenistas número 1 no ranking da WTA.
6 - Eléré orí pápá, s. Atleta. Àwọn eléré orí pápá ará Amẹ́ríkà - Atletas dos Estados Unidos.
7 - Àwọn ìdíje mọ́tò, s. Automobilismos.
8 - Ife-ẹ̀yẹ Àgbáyé Bọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀, s. Copa do Mundo de Futebol. Ẹgbẹ́ Ìpapọ̀ Káríayé Àjọṣe Bọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ - Federação Internacional de Futebol, FIFA.
Nenhum comentário:
Postar um comentário