Ìhùmọ̀ ti filọ́sọ́fi (Reflexão filosófica).
1. Àwọn ìbéèrè táwọn èèyàn ń béèrè nípa àwà ẹlẹ́ṣìn Òrìṣà.
Perguntas frequentes sobre os devotos de Oríxá.
2. Ní apá yìí, wàá rí ìdáhùn sí àwọn ìbéèrè táwọn èèyàn ń béèrè nípa àwa ẹlẹ́ṣìn Òrìṣà.
Nesta seção, você encontrará respostas a algumas das perguntas mais frequentes sobre os seguidores de Orixá.
3. Ṣé àwọn ẹlẹ́sìn Pùròtẹ́sítáǹtì gbà pé ẹ̀sìn yín nìkan lẹ̀sìn tòótọ́?
Os protestantes acreditam que a sua religião é a única verdadeira?
4. Ṣé àwọn ẹlẹ́sìn Pùròtẹ́sítáǹtì rò pé ẹ̀yin nìkan ló máa rí ìgbàlà?
Os protestantes acham que só eles serão salvos?
5. Ṣé Kristẹni Ni Yín?
Será que vocês são cristãos?
6. Ǹjẹ́ ẹ ní ìgbàgbọ́ nínú Òrìṣà?
Será que vocês acreditam em Orixá?
7. Máàpù àwọn ẹ̀sìn Áfríkà Bràsíl.
Mapa das religiões afro-brasileiras

Nenhum comentário:
Postar um comentário