Ọ̀rọ̀ arọ́pò orúkọ ti ara ẹni.
Pronome pessoal.
1. Ti ènìyàn kan (singular)
Mo, mi, ng = eu
O = você
Ó = ele, ela
2. Ti ènìyàn púpọ̀ (plural)
A = nós
Ẹ = vocês
Wọn = eles, elas
O lè Kẹ́kọ̀ọ́ èdè yorùbá pẹ̀lú Olùkọ́ Orlandes o sì, síwájú sí i, jẹ́ kí àwọn òrìṣà darí ẹ padà sí ìlú ìbílẹ̀ rẹ. Kí èrò inú rẹ lílágbára ṣẹ, òmìnira, yan ohun tí ó tọ́ o sì di olórí rere - Aprenda yorubá com o professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.
Nenhum comentário:
Postar um comentário