Àwọn onímọ̀sáyẹ́nsì ti orílẹ̀ èdè Ṣáínà ṣẹ̀dá Òòrùn tí a fi ọgbọ́n ṣe.
Cientistas chineses criam sol artificial.
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário).
Àwọn, wọn, pron. Eles elas. Indicador de plural.
Onímọ̀sáyẹ́nsì, s. Cientista.
Ọmọorílẹ̀-èdè Ṣáínà, ọmọ ilẹ̀ Ṣáínà, ọmọ kùnrin ilẹ̀ Ṣáínà, s. Chinês.
Ọmọ kùnrin ilẹ̀ Ṣáínà, s. Chinês (masculino).
Ọmọbìnrin ilẹ̀ Ṣáínà, s. Chinesa.
Ní ti Ṣáínà, ti orílẹ̀ èdè Ṣáínà, adj. Chinês.
Orílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ará ilẹ̀ Ṣáínà, s. República Popular da China
Dá, v. Fazer, fabricar. Cessar a chuva, parar, interromper, ser raro, escasso. Atingir, acertar, bater. Abandonar, desertar. Estar bem. Derrubar em uma luta. Quebrar o que é compacto, rachar. Arrancar o inhame. Causar. Contribuir. Confiar. Estar inativo. Consultar.
Ṣe, v. Fazer, causar, desempenhar. Ser.
Mú jáde, mújáde, v. Produzir, realizar.
Mọ, v. Construir, modelar. Ser restrito, limitado.
Ṣẹ̀dá, v. Criar.
Òòrùn, òrùn, s. Sol.
Ìfi-ọgbọ́n-ṣe, tí a fi ọgbọ́n ṣe, tí kì íṣe ti ẹ̀dá, adj. Artificial.

Nenhum comentário:
Postar um comentário