Ẹ̀kọ́ nípa àròsọ (mitologia)
A Mitologia estuda mitos, deuses e lendas.
Agbára Abàmì (sobrenatural)
1. Ẹ̀mí àìrí (fantasma).
2. Èèyàn tó di ìkookò (lobisomem)
3. Àǹjọ̀nnú, fanpaya (vampiro)
4. Àjẹ́ (bruxa, feiticeira).
5. Ọ̀rọ̀ (tipo de espírito e fadas que vivem em certas árvores), iwin (espírito, fantasma, fada), kúrékùré, kúékùé (fada, gnomo).
6. Kúrékùré, kúékùé (fada, gnomo).
7. Ańgẹ́lì, màlékà, mọ̀láíkà (anjo).
8. Sátánì (diabo, capeta, satã, demônio), bìlísì (mal, demônio).
Nenhum comentário:
Postar um comentário