Máàkù Fẹ́líìsì gbà ẹ̀kọ́ ìtàn lórí Áfríkà.
Marco Feliciano recebe aula de História sobre África.
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário)
Oníwàásù, àlùfáà, olùsọ́ àgùntàn, s. Pastor.
Máàkù, s. Marcos.
Fẹ́líìsì, s. Félix, Feliciano e Felício. O título Feliciano faz alusão ao nome bíblico Félix, que está presente no Novo Testamento.
Rí gbà, rígbà, v. Receber, obter.
Gbà, v. Receber, tomar, pegar. Remover, resgatar, privar. Aceitar, acolher, admitir, concordar. Envolver, amarrartapar. Fugir. Ajudar, socorrer, acudir. Ser dirigido junto, ser conduzido. Conseguir.
Gbà á, v. Recebê-lo.
Àpèjọ, s. Assembleia, encontro, comício.
Àpérò, s. Consulta, conferência, comparação, confrontação, verificação, confronto.
Ìjùmọ̀sọ, s. Concordância.
Ìjọsọ̀rọ̀, àjọsọ̀rọ̀, ìsọ̀rọ̀, s. Conversação.
Ìdánilẹ́kọ̀ọ́, ọ̀rọ̀ sísọ, ìsọ̀rọ̀, s. Palestra, conferência, aula.
Àròyé, s. Debate, discussão, controvérsia.
Ẹ̀kọ́. s. Aula, educação, instrução.
Yàrá ìkẹ́kọ̀ọ́, s. Aula.
Nípa, nípasẹ̀, adv. Sobre, acerca de, concernente a.
Kọjá, prep. Sobre, além de.
Ní orí, lórí, lérí, prep. Sobre, em cima de, cerca de, acerca de, a respeito de.
Lórísórí, prep. Em, por, ao. sobre.
Sórí, prep. Para cima de.
Nípati, prep. Conforme.
Lókè, ní òkè, prep. Acima, no alto de.
Ìtàn, s. História, mito.
Áfríkà, Áfíríkà, s. África.
Ní ti Áfríkà, ti orílẹ̀ èdè Áfríkà, adj. Africano.
Ọmọ ilẹ̀ Áfríkà, s. Africano.
Ọmọ kùnrin ilẹ̀ Áfríkà, s. Africano.
Ọmọbìnrin ilẹ̀ Áfríkà, s. Africana.
Ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà, aláwọ̀dúdú Ará Amẹ́ríkà, adúláwọ̀ ará Amẹ́ríkà, s. Afro-americano.
Ọmọ Áfríkà Ásíà, s. Afro-asiático.
Ọmọ Áfríkà Bràsíl, aláwọ̀dúdú ará Bràsíl, adúláwọ̀ ará Bràsíl, s. Afro-brasileiro.
Ọmọ Áfríkà Kàríbẹ́ánì, aláwọ̀dúdú ará Kàríbẹ́ánì, adúláwọ̀ ará Kàríbẹ́ánì, s. Afro-caribenho.
Ọmọ Áfríkà Kúbà, aláwọ̀dúdú ará Kúbà, adúláwọ̀ ará Kúbà, s. Afro-cubano.

Nenhum comentário:
Postar um comentário