sábado, 18 de novembro de 2017

Sem


Àwọn ẹlẹ́kọ̀ọ́ ẹfolúṣọ̀n ṣàlàyé bí ìwàláàyè ṣe bẹ̀rẹ̀ lórí ilẹ̀ ayé, àmọ́ wọn ò gbà pé Ọlọ́run ló ṣẹ̀dá ohun gbogbo.
A teoria da evolução tenta explicar que a vida na Terra surgiu sem a necessidade de intervenção divina.

Resultado de imagem para Evolução da vida


 Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).


Àwọn, wọ́n - Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; nente caso, é posicionado antes do substantivo.
Wọn - A eles, a elas.
Wọn - Deles, delas.
Àwọn ẹlẹ́kọ̀ọ́ ẹfolúṣọ̀n - Evolucionistas.
Ṣàlàyé - Explicar.
Bí ìwàláàyè - Como a vida.
Ṣe - Fazer, causar.
Bẹ̀rẹ̀ - Começar.
Lórí - Sobre.
Ilẹ̀ ayé - Terra. 
Àmọ́ - Mas. 
Kò, ò - Não.
Gbà - Aceitar, receber.
- Que.
Ọlọ́run - Deus.
Ṣẹ̀dá - Criar.
Ohun gbogbo - Todas as coisas.
- Ser ele.
Àìrílégbé - Sem-teto, sem-abrigo. 
Tí kò ní ilẹ̀ - Sem-terra.
Láìsí òjò - Sem chuva.
Tí kò ti ní sí ìwà àìṣòdodo -Sem injustiças.
Tí kò lópin lórí ilẹ̀ ayé - Sem fim na terra.
Láìsí pé wọ́n ń ṣá igbó sí i mọ́ - Sem precisarem derrubar mais floresta.
Láìkùnà - Sem falha, sem falta, sem fracassar, sem perder.
Tí kì yóò kú rárá - Que nunca morrerá, que não vai morrer, sem precisar passar pela morte.
Láìsí ẹnikẹ́ni tí ó sá àsálà - Sem que ninguém escapasse, sem que alguém tivesse escapado.
Tí kò ní sí ìwà ìnìkànjọpọ́n àti ìrẹ́jẹ níbẹ̀ - Sem exploração egoísta e injustiças.
Láìsí alátakò kankan - Sem oposição , sem oponente.
Kò ní omi kankan - Sem água.
Bọrọgidi, ó sì ṣófo - Sem forma e vazia.
Láìsí ọwọ́ Jèhófà níbẹ̀ - Sem depender de Jeová, sem a mão de Jeová ali.
Láìsí ẹni tó máa ta kò ó - Sem nenhuma oposião,  sem que ninguém se oponha a isso.
Aláìlẹ́gbẹ́m - Sem paralelo, único, incomparável, sempar, singular, um, uno.
Títí lọ láìsí pé wọ́n darúgbó - Sem sua idade avançada, sem envelhecer.
Láìsí olùgbé - Sem gente, sem habitante.
Láìsí èèyàn kankan tí ń gbébẹ̀ - Sem qualquer população humana, sem habitantes, sem quem morasse lá, sem gente.
Tí kò tíì ṣẹlẹ̀ rí - Sem precedentes, que nunca ocorreu antes.
Tí kò sí irú ẹ̀ rí - Nunca visto, sem precedentes.
Kò tíì rírú rẹ̀ rí jáde - Nunca foi atingido, sem precedentes.
Láìsí pé wọ́n ń sá kúrò nínú ilé wọn - Sem ter que fugir de suas casas, sem terem de abandonar a sua terra.
Láìsí àní-àní - Sem dúvida.
Láìsí ohun alààyè  - Sem vida.
Kò ní ṣiṣẹ́ lórí ilẹ̀ náà - Sem cultivo.
Láìsí pé Ọlọ́run - Sem Deus, sem interferência divina. 
Láìsí i, ìwàláàyè kò ní ṣeé ṣe lórí ilẹ̀ ayé - Sem isso, a vida não seria possível na Terra, sem a qual seria impossível haver vida na Terra.
Kò sì sí pé àwọn ẹranko ń halẹ̀ mọ́ wọn - Sem temer os animais.
Kò sí òṣùpá - Sem lua. 
Láìní kú - Sem morrer.
Láìfọhùn - Sem falar nada, sem voz.
Tí kò mọ̀wé - Sem instrução. 
Tí kò mọ̀wé - Sem instrução, iletrado. Ìwádìí tí wọ́n ṣe fi hàn pé àwọn aṣáájú ìlú àtàwọn aṣáájú ẹ̀sìn máa ń pe àwọn tí kò mọ̀wé ní ʽam-ha·ʼaʹrets, tàbí “àwọn èèyàn ilẹ̀ náà”- Fontes seculares mostram que as classes privilegiadas menosprezavam as pessoas sem instrução, chamando-as de ʽam ha·ʼaʹrets, ou “povo da terra”.
Àgùntàn - Ovelha. Tí kò bá sí ìrànlọ́wọ́ látọ̀dọ̀ àwọn àgùntàn mìíràn tó jẹ́ alábàákẹ́gbẹ́ wọn - sem a ajuda de seus companheiros das outras ovelhas.
Láì bí ọmọkùnrin kankan -Sem ter um filho homem.
Tí kò ti ní sí ìwà ìbàjẹ́ - Que nunca será corrompido, sem corrupção.
Láìjẹ́ pé ẹ̀ṣẹ̀ tí wọ́n jogún tàbí ayé burúkú yìí dí wọn lọ́wọ́ - Sem a interferência do pecado herdado ou do ambiente perverso.
Tí wọn ò ti mọ̀ ọ́n - Sem nenhum destaque, desconhecido para eles.
Tí kò sì sí ohun tó lè ṣe sí i- Sem poder fazer nada a respeito.
Láìṣe ìwádìí kankan ní tìtorí ẹ̀rí-ọkàn yín - Sem fazer indagação por causa da vossa consciência.
Àìríná-àìrílò á sì di ohun ìgbàgbé -  Sem nenhum sinal de pobreza.
Jésù Kristi - Jesus Cristo. Nígbà tí Jésù Kristi wà lórí ilẹ̀ ayé, nígbà míì ó máa ń lọ síbi àdádó láti lọ gbàdúrà níbi tí ẹnikẹ́ni kò ti ní yọ ọ́ lẹ́nu - Quando Jesus Cristo estava na Terra, às vezes ele ia sozinho a um lugar isolado para orar sem ser interrompido.
Kò sì ní ṣàníyàn mọ́ - Sem ansiedade.
Láìsí kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà - Sem discriminação, sem nenhuma barreira racial.
Àgbègbè tí kò mọ̀ rí - Território desconhecido, área desconhecida. Èyí ló máa ń mú káwọn ọ̀dọ́langba dà bí arìnrìn àjò afẹ́ kan tó ń wá ọ̀nà tó máa gbà ní àgbègbè tí kò mọ̀ rí, ńṣe ni gbogbo nǹkan máa ń dàrú mọ́ wọn lójú, ọ̀pọ̀ ìgbà ni wọn kì í sì í fẹ́ béèrè pé kí ẹnì kan ràn wọ́n lọ́wọ́ - De modo que muitas vezes eles se sentem como turistas em uma terra desconhecida: assustados com o que os rodeia e, em muitos casos, sem vontade de pedir ajuda.
Tí kò lẹ́mìí - Sem vida.
Láìsí pé ó jìnnà sí i jù tí kò sì sún mọ́ ọn jù - Sem se afastar ou se aproximar.
Láìbímọ - Sem ter filhos.
Nígbà tí kò sówó mọ́ lọ́wọ́ - Quando já não havia mais dinheiro, sem mais dinheiro.
Tí kò ní okun alágbára gíga - Que não têm força, sem energia dinâmica.
Ọ̀run àti ilẹ̀ ayé - Céu e Terra. Èmi kò wá láti pa run, bí kò ṣe láti mú ṣẹ; nítorí lóòótọ́ ni mo wí fún yín pé ọ̀run àti ilẹ̀ ayé yóò tètè kọjá lọ jù kí lẹ́tà kan tí ó kéré jù lọ tàbí kí gínńgín kan lára lẹ́tà kan kọjá lọ kúrò nínú Òfin lọ́nàkọnà kí ohun gbogbo má sì ṣẹlẹ̀.”—Mátíù 5:17, 18 - Não vim destruir, mas cumprir; pois, deveras, eu vos digo que antes passariam o céu e a terra, do que passaria uma só letra menor ou uma só partícula duma letra da Lei sem que tudo se cumprisse.” — Mateus 5:17, 18.
Tí kò tíì sírú rẹ̀ rí nínú ìtàn ọmọ aráyé - Sem comparação em toda a história da humanidade.
Tí kò sí ẹnikẹ́ni tí yóò kó wọn jọpọ̀ - Sem alguém que os reúna. 
Láìsí ìdájọ́ òdodo - Sem justia, sem qualquer justiça.
Tí kò ní ìyọlẹ́nu - Não há perturbação, sem perturbação.
Láìsí ará ayé - Sem ninguém,  sem homem terreno. 




Nenhum comentário:

Postar um comentário