Ẹgbẹ́ ọ̀daràn (organização criminosa)
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário).
Ẹgbẹ́ ọ̀daràn, àjọ ọ̀daràn, àjọ arúfin, s. Organização criminosa.
Ẹgbẹ́ ológun, s. Milícia.
Ẹgbẹ́ ọlọ̀tẹ̀, s. Grupo revolucionário.
Àwùjọ àwọn apániláyà, s. Organizações terroristas
Ẹgbẹ́ àwọn apániláyà, s. Organização terrorista.
Àwọn ọmọ ìta oníjàgídíjàgan, s. Gangues.
Ẹgbẹ́ ọ̀daràn, s. Máfia.
Ẹgbẹ́ olè, s. Quadrilha.
Nenhum comentário:
Postar um comentário