sexta-feira, 12 de outubro de 2018

Democracia

Òṣèlúaráìlú (democracia)
                                                       
A filósofa marilena chaui e a democracia brasileira




Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).


Òṣèlúaráìlú, ìjọba àjùmọ̀ṣe, ìjọba tí ó fi àyè gba ará ìlú láti ní ìpín nínú ètò ìlú, s. Democracia.
Ẹni tí ó fẹ́ kí gbogbo ará ìlú jẹ́ alábàápín nínú ètò àti àṣẹ ìlú, s. Pessoa que quer a participação de todos os cidadãos no governo da cidade ou do país. 
Ẹni tí ó ní ìgbàgbọ́ sí ìjọba àjùmọ̀ṣe, s.  Pessoa que acredita no governo com participação popular.
Tòṣèlúaráìlú, dẹmọkrátíkì, adj. Relativo a democracia, forma de governo em que os cidadãos exercem o poder de governo através do sufrágio universal.
Tìwàtìwà, adv. Com dignidade, com prioridade.
Tiwájú, adj. Prioritário.
Àwọn èèyàn tí à ń wá ìyípadà nínú ìṣèlú, s. Militantes políticos. 
Ajàjàgbara, adógunsílẹ̀, s. Militante, revolucionário.
Ẹgbẹ́ ajàjàgbara, s.  Grupo militante, grupo ativista.

Tẹlifíṣàn lédè yorùbá, s. Tv no idioma yorubá
Tẹlifíṣàn wa lédè yorùbá, s. Nossa tv em yorubá.
Tẹlifíṣàn ti àwọn ọmọ Odùduwà, s. Tv dos filhos de Oduduwa.
Ètò ìdánilẹ́kọ̀ọ́ èdè yorùbá, s. Curso de idioma yorubá.
Tẹlifíṣọ̀n lédè yorùbá àti Potogí, s. Tv yorubá-português.
Tẹlifíṣọ̀n ti àwọn yorùbá tó wà lájò, s. Tv dos yorubás da diáspora.

Nenhum comentário:

Postar um comentário