quinta-feira, 1 de novembro de 2018

Marcos Cesar Pontes

Arìnlófurufú kan (láìsí Ọkọ̀ òfurufú) fún Ẹ̀ka Ilé Iṣẹ́ Ètò Ìmọ̀ Sáyẹ́ǹsì àti Ìmọ̀ Iṣẹ́ Ẹ̀rọ.
Um astronauta (sem nave espacial) para o Ministério da Ciência e Tecnologia.

Lançamento de Marcos Pontes Rumo à ISS na Soyus TMA-8



.
Marcos Cesar Pontes é um tenente-coronel da Força Aérea Brasileira, atualmente na reserva. Foi o primeiro astronauta brasileiro, sul-americano e lusófono a ir ao espaço, na missão batizada "Missão Centenário", em referência à comemoração dos cem anos do voo de Santos Dumont no avião 14 Bis, realizado em 1906.


Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).


Ẹ̀ka Ilé Iṣẹ́ Ètò Ẹ̀kọ́, s. Departamento do Ministério da Educação.
Iléeṣẹ́ Ètò Ìdájọ́, s. Ministério da justiça.
Arìnlófurufú, arìnrìn-àjò ní ojúde òfuurufú, arìnrìn-àjò ní gbalasa òfuurufú, s. Astronauta.
Àwọn tó ń fi ọkọ̀ àgbéresánmà rìnrìn àjò lọ sínú gbalasa òfuurufú, s. Astronautas na orientação de naves espaciais.
Ẹ̀ka Ìmọ̀ Sáyẹ́ǹsì àti Ìmọ̀ Iṣẹ́ Ẹ̀rọ, s.  Divisão de Ciência e Tecnologia. Ṣé Ìmọ̀ Sáyẹ́ǹsì àti Ìmọ̀ Iṣẹ́ Ẹ̀rọ Lè Kó Wa Yọ? - A ciência e a tecnologia podem nos salvar?
Àìrílégbé, s. Sem-abrigo, sem teto.
Aláìrílégbé, s. Desabrigado, pessoa sem teto.
Àwọn èèyàn tí kò rílé, s.  Pessoas desabrigadas.
Tí ò rílé gbé, adj. Sem teto.
Tí kò ní ilẹ̀, adj. Sem terra.
Ìrìnkánkán, s. Movimento.
Àwọn alátìlẹyìn òmìnira fáwọn obìnrin, s.  Feminismo.
Àjọ tó ń jà fẹ́tọ̀ọ́ obìnrin, s. Movimento feminista. 

Ìrìnkánkán àwọn Ẹ̀tọ́ Aráàlú ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà, s. Movimento dos direitos civis dos negros nos Estados Unidos.
Ìrìnkánkán ti àwọn òṣìṣẹ́ tí ò rílé gbé, s. Movimento dos Trabalhadores Sem Teto.
Ìrìnkánkán ti àwọn òṣìṣẹ́ tí kò ní ilẹ̀, s. Movimento dos Trabalhadores Rurais Sem Terra.
Ẹgbẹ́ tó ń ta ko ìlànà ìwà rere àti àjọṣe ẹgbẹ́-òun-ọ̀gbà, s. Movimento hippie. Ẹgbẹ́ ọ̀dọ́ kan tó dìde nílẹ̀ Yúróòpù àti Amẹ́ríkà láwọn ọdún 1960 jẹ́ ẹgbẹ́ tó ń ta ko ìlànà ìwà rere àti àjọṣe ẹgbẹ́-òun-ọ̀gbà - No mundo ocidental, o movimento hippie na década de 60 era uma rebelião contra os tradicionais valores morais e sociais.
Ẹgbẹ́ òṣèlú àtàwọn tó ń jà fún ẹ̀tọ́ aráàlú kó lè gbèjà àwọn mẹ̀kúnnù, s. Movimento social.
Láìsí òjò, adj. Sem chuva.
Tí kò ti ní sí ìwà àìṣòdodo, adj. Sem injustiças.
Tí kò lópin lórí ilẹ̀ ayé, adj.  Sem fim na terra.
Láìsí pé wọ́n ń ṣá igbó sí i mọ́, adj. Sem precisarem derrubar mais floresta.
Láìkùnà, adj. Sem falha, sem falta, sem fracassar, sem perder.
Tí kì yóò kú rárá, adj. Que nunca morrerá, que não vai morrer, sem precisar passar pela morte.
Láìsí ẹnikẹ́ni tí ó sá àsálà, adj.  Sem que ninguém escapasse, sem que alguém tivesse escapado.
Tí kò ní sí ìwà ìnìkànjọpọ́n àti ìrẹ́jẹ níbẹ̀, adj. Sem exploração egoísta e injustiças.
Láìsí alátakò kankan, adj. Sem oposição , sem oponente.
Kò ní omi kankan, adj. Sem água.
Láìsí ọwọ́ Jèhófà níbẹ̀, adj. Sem depender de Jeová, sem a mão de Jeová ali.
Láìsí ẹni tó máa ta kò ó, adj.  Sem nenhuma oposião,  sem que ninguém se oponha a isso.
Aláìlẹ́gbẹ́m, s. Sem paralelo, único, incomparável, sem par, singular, um, uno.
Títí lọ láìsí pé wọ́n darúgbó, adj. Sem sua idade avançada, sem envelhecer.
Láìsí olùgbé - Sem gente, sem habitante.
Láìsí èèyàn kankan tí ń gbébẹ̀, adj.  Sem qualquer população humana, sem habitantes, sem quem morasse lá, sem gente.
Tí kò tíì ṣẹlẹ̀ rí, adj. Sem precedentes, que nunca ocorreu antes.
Tí kò sí irú ẹ̀ rí, adj.  Nunca visto, sem precedentes.

Láìsí pé wọ́n ń sá kúrò nínú ilé wọn, adj. Sem ter que fugir de suas casas, sem terem de abandonar a sua terra.
Láìsí àní-àní, adj. Sem dúvida.
Láìsí ohun alààyè , adj. Sem vida.
Kò ní ṣiṣẹ́ lórí ilẹ̀ náà, adj.  Sem cultivo.
Láìsí pé Ọlọ́run, adj. Sem Deus, sem interferência divina. 
Kò sì sí pé àwọn ẹranko ń halẹ̀ mọ́ wọn , adj. Sem temer os animais.
Kò sí òṣùpá, adj.  Sem lua. 
Láìní kú, adj.  Sem morrer.
Láìfọhùn, adj. Sem falar nada, sem voz.
Tí kò mọ̀wé, adj.  Sem instrução. 
Tí kò mọ̀wé, adj. Sem instrução, iletrado. Ìwádìí tí wọ́n ṣe fi hàn pé àwọn aṣáájú ìlú àtàwọn aṣáájú ẹ̀sìn máa ń pe àwọn tí kò mọ̀wé ní ʽam-ha·ʼaʹrets, tàbí “àwọn èèyàn ilẹ̀ náà”- Fontes seculares mostram que as classes privilegiadas menosprezavam as pessoas sem instrução, chamando-as de ʽam ha·ʼaʹrets, ou “povo da terra”.

Láì bí ọmọkùnrin kankan, adj. Sem ter um filho homem.
Tí kò ti ní sí ìwà ìbàjẹ́, adj. Que nunca será corrompido, sem corrupção.
Láìjẹ́ pé ẹ̀ṣẹ̀ tí wọ́n jogún tàbí ayé burúkú yìí dí wọn lọ́wọ́, adj.  Sem a interferência do pecado herdado ou do ambiente perverso.

Tí wọn ò ti mọ̀ ọ́n, adj. Sem nenhum destaque, desconhecido para eles.
Tí kò sì sí ohun tó lè ṣe sí i, adj. Sem poder fazer nada a respeito.
Láìṣe ìwádìí kankan ní tìtorí ẹ̀rí-ọkàn yín - Sem fazer indagação por causa da vossa consciência.
Àìríná-àìrílò á sì di ohun ìgbàgbé -  Sem nenhum sinal de pobreza.
Kò sì ní ṣàníyàn mọ́ - Sem ansiedade.
Láìsí kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà - Sem discriminação, sem nenhuma barreira racial.
Àgbègbè tí kò mọ̀ rí, s. Território desconhecido, área desconhecida. Èyí ló máa ń mú káwọn ọ̀dọ́langba dà bí arìnrìn àjò afẹ́ kan tó ń wá ọ̀nà tó máa gbà ní àgbègbè tí kò mọ̀ rí, ńṣe ni gbogbo nǹkan máa ń dàrú mọ́ wọn lójú, ọ̀pọ̀ ìgbà ni wọn kì í sì í fẹ́ béèrè pé kí ẹnì kan ràn wọ́n lọ́wọ́ - De modo que muitas vezes eles se sentem como turistas em uma terra desconhecida: assustados com o que os rodeia e, em muitos casos, sem vontade de pedir ajuda.
Tí kò lẹ́mìí, adj. Sem vida.
Láìsí pé ó jìnnà sí i jù tí kò sì sún mọ́ ọn jù, adj. Sem se afastar ou se aproximar.
Láìbímọ, adj.  Sem ter filhos.
Nígbà tí kò sówó mọ́ lọ́wọ́ - Quando já não havia mais dinheiro, sem mais dinheiro.
Tí kò ní okun alágbára gíga, adj. Que não têm força, sem energia dinâmica.
Ọ̀run, s.  Céu. Èmi kò wá láti pa run, bí kò ṣe láti mú ṣẹ; nítorí lóòótọ́ ni mo wí fún yín pé ọ̀run àti ilẹ̀ ayé yóò tètè kọjá lọ jù kí lẹ́tà kan tí ó kéré jù lọ tàbí kí gínńgín kan lára lẹ́tà kan kọjá lọ kúrò nínú Òfin lọ́nàkọnà kí ohun gbogbo má sì ṣẹlẹ̀.”—Mátíù 5:17, 18 - Não vim destruir, mas cumprir; pois, deveras, eu vos digo que antes passariam o céu e a terra, do que passaria uma só letra menor ou uma só partícula duma letra da Lei sem que tudo se cumprisse.” — Mateus 5:17, 18.
Tí kò tíì sírú rẹ̀ rí nínú ìtàn ọmọ aráyé, adj.  Sem comparação em toda a história da humanidade.
Tí kò sí ẹnikẹ́ni tí yóò kó wọn jọpọ̀, adj. Sem alguém que os reúna. 
Láìsí ìdájọ́ òdodo, adj. Sem justiça, sem qualquer justiça.
Tí kò ní ìyọlẹ́nu, adj. Que não há perturbação, sem perturbação.
Láìsí ará ayé, adj. Sem ninguém,  sem homem terreno.
Ìwákiri lófurufú, s. Exploração espacial. 
Mísàílì àntí-èlò, s. Foguete de antimatéria. 
Ọkọ̀ òfurufú, s. Nave espacial.
Ọkọ̀-òfurufú, s. Sonda espacial. 
Ọkọ̀-àlọbọ̀ Òfurufú, Ọkọ̀-ayára Òfurufú, s.  Ônibus espacial.
Ilé-iṣẹ́ Ìmójútó Ìrìnlófurufú àti Òfurufú Orílẹ̀-èdè Amẹ́rííà, s. NASA (National Aeronautics and Space Administration), Administração Nacional da Aeronáutica e Espaço).
Ilé-iṣẹ́, s. Empresa.
Ìṣàgbéṣe òfurufú, s. Agência espacial. 
Arìnlófurufú, s. Astronauta.
Ìrìnlófurufú, s. Aeronáutica.
Ìwákiri lófurufú, s. Exploração espacial.
Òfurufú, ojú òfurufú, inú òfurufú, s. Espaço sideral.
Àwọn kan, pron. Alguns. Ó lè ṣòro fún àwọn kan láti gba ìbáwí - Para alguns, isso pode ser um verdadeiro desafio.
Àwọn kan lára àwọn, pron. Alguns dos.  
Àwọn lẹ́rìí kan, s.  Algumas testemunhas.   Àmọ́ o, àwọn kan ò lè lo gbogbo àkókò wọn lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn báyìí torí ipò tó yí wọn ká -  É claro que alguns não podem servir no tempo integral no momento por causa de suas circunstâncias. 
Àwọn Kristẹni kan, s. Alguns cristãos. Àwọn kan ti nígbàgbọ́ rí, àmọ́ wọn ò dúró sínú ìfẹ́ Ọlọ́run - Alguns que tinham fé não permaneceram no amor de Deus. Àwọn onímọ̀ sáyẹ́ǹsì kan ronú pé, níwọ̀n bó ti jẹ́ pé kò tíì pẹ́ tí ọ̀rọ̀ yíyí àbùdá irè oko padà bẹ̀rẹ̀, ó yẹ kí àyẹ̀wò ṣì máa lọ lórí rẹ̀ nípa àwọn ewu tó lè ṣe fún àwọn tó ń jẹ ẹ́ - Alguns cientistas acham que é muito cedo para avaliar os alimentos GM e que seriam necessários mais testes para detectar possíveis riscos para os consumidores.
Àwọn akéde kan, s. Alguns publicadores. 

Kàn án mọ́gi!, v. imper. Crucifica-o!, Para a estaca com ele!  Bẹ̀rẹ̀ sí fẹ̀sùn kàn án - Começou a acusá-lo.
Ìkan, ọ̀kan, num.  Um.
Kan, v. Tornar azedo.
Kan, adj. Amargo, ácido, azedo. Longe, ao largo.
Kan, num. e art. Um, uma.
Kàn, adv. pré. v. Somente, simplesmente.
Kàn, v. Atingir, tocar, alcançar. Pregar com um martelo. Bater na porta, bater com a cabeça como um carneiro. Girar, retornar, fazer um rodízio. Referir-se a, aludir, recorrer. Devolver, interessar alguém.
Kán, v. Pingar, gotejar ( a chuva ou qualquer líquido). Quebrar, partir, estalar algo sólido.
Mọ́gi, s. Estaca. 
Ìmọ̀, s. Conhecimento.
Sáyẹ́ǹsì, s. Ciência.
Ìmọ̀ Iṣẹ́ Ẹ̀rọ, s. Tecnologia.
Àti, Conj. E. Usada entre dois nomes, mas não liga verbos.
, ( conj. pré-v.). E, além disso, também. Liga sentenças, porém, não liga substantivos; nesse caso, usar " àti". É posicionado depois do sujeito e antes do verbo.

Ti, àti, conj. E.
Pẹ̀lú, Conj. E.
Òun, on, conj. E. Geralmente usada com nomes de pessoas.
Ètò, s. Ordem, sistema.
Ètò-ètò, s. Matriz, molde.
Ètò èèkà, s. Sistema numérico.
Ṣètò, adj. Organizado.
Iṣẹ́, s. Trabalho, serviço, ocupação. Mensagem.
Ilé, s. Casa.
Ẹ̀ka, s. Galho, ramo, parte, seção.
Fún, prep. Para, em nome de (indica uma intenção pretendida para alguém).
Fún, v. Dar. Espremer, apertar, extrair. Espalhar, desperdiçar, empurrar para os outros. Espirrar, assoar.
Fun, v. Ser branco. Soprar, ventar.
Láìsí, adj. Inexistência, nulo, sem.
Ọkọ̀ òfurufú, ọkọ̀ òfúrufú, pléènì, bààlúù, s. Avião, aeronave. 
Eropílénì, s. aeroplano, aeronave, avião.
Ọkọ̀ òfurufú olùsọ́, s. Aeronave de patrulha.
Pápá ọkọ̀ òfurufú, pápá bàlúù, ibùdó ọkọ-òfúrufú, s. Aeroporto. 
Pápá Ọkọ̀ Òfurufú Káríayé Múrítàlá Mùhammẹ̀d, s. Aeroporto Internacional Murtala Muhammed.
Pápá Ọkọ̀ Òfurufú Káríayé, s. Aeroporto internacional.
Òfurufú, òfuurufú, s. Espaço sideral, ar, firmamento, céu.
Ọkọ̀, s. Canoa, veículo, carro.
 
Àwọn gbólóhùn kúkúrú (frases curtas)

Kò tíì rírú rẹ̀ rí jáde -  Nunca foi atingido, sem precedentes.
Bọrọgidi, ó sì ṣófo - Sem forma e vazia.

Nenhum comentário:

Postar um comentário