Ètò ẹ̀sọ ara - O sistema nervoso.
.
Ẹ̀sọ (nervo), ètò ẹ̀sọ t’ogangan (sistema nervoso central), pádi ẹ̀sọ (célula nervosa , neurônio ), ètò ẹ̀sọ t’àgbèègbè (sistema nervoso periférico), ìṣù ẹ̀sọ (cordão do nervo), ọ̀ran ẹ̀sọ (fibra nervosa), ọ̀pá ẹhìn (coluna vertebral), irìn ẹ̀sọ (raiz nervosa), ẹ̀kọ́ ẹ̀sọ (neurologia), ihò ọ̀pá-ẹhìn (canal espinhal), oníṣègùn ẹ̀sọ-ara (neurologista), ọ̀pọlọ (cérebro), irun ẹ̀sọ (dendritos do neurônio), ẹ̀sọ ọ̀pá-ẹhìn (medula espinhal), ẹ̀sọ ìmira (nervo motor), ẹ̀sọ atọ̀páyọ (nervo espinhal), àwọn ẹ̀sọ-iyè (nervos sensoriais), pádi ẹ̀sọ-ìmira (neurônio motor), ẹ̀sọ adáṣiṣẹ́ (nervo autônomo, neurônio), pádi ẹ̀sọ-ìmira (neurônio motor), ẹ̀sọ iyè-ìríran (nervo óptico), ẹ̀sọ iyè (nervo sensitivo), ẹ̀sọ ìgbọrọ (nervo acústico), ẹ̀sọ atọ̀páyọ (nervo espinhal), ẹ̀sọ akọkàn (fibra nervosa aferente, nervo aferente), ẹ̀sọ afún-ìṣọ̀n (nervo vasoconstritor), ẹ̀sọ atoríyọ (nervo craniano), ẹ̀sọ aṣọ-ìṣọ̀n (nervo vasodilatador), ẹ̀sọ ìmira (fibra nervosa eferente, nervo eferente), ẹ̀sọ ìmira-ìṣọ̀n (nervo vasomotor), ẹ̀sọ iyè-òórùn (nervo olfatório), ẹ̀sọ ìmira-ojú (nervo oftálmico), ẹ̀sọ ẹṣẹ́-ara (nervo secretor), pádi ẹ̀sọ-ìmira (neurônio motor).

Nenhum comentário:
Postar um comentário