Ẹgbẹ́ àwọn amòye ilẹ̀ Áfíríkà (iluminismo africano)
Os africanos que propuseram ideias iluministas antes de Locke e Kant
Tó o bá fẹ́ mọ̀ sí i lórí ẹṣin ọ̀rọ̀ náà ( Se você quiser saber mais sobre o tema):
https://paginadoenock.com.br/idade-da-razao-precisa-ser-reescrita-os-filosofos-africanos-zera-yacob-e-anton-amo-propuseram-ideais-iluministas-antes-de-locke-e-kant/
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário).
Èrò àwọn onílàákàyè, s. O pensamento dos racionalistas.
Ọ̀rúndún kejìdínlógún, s. Século 18
Ẹgbẹ́ àwọn amòye, ọ̀làjú, s. Iluminismo.
Àwọn onímọ̀ ọgbọ́n Ìlanilóye, s. Filósofos iluministas.
Ìgbòkègbodò àjọ àwọn onílàákàyè ilẹ̀ Áfíríkà, s. Movimento intelectual africano.
Ẹgbẹ́ àwọn amòye ilẹ̀ Áfíríkà, s. Iluminismo africano.
Nenhum comentário:
Postar um comentário