Ẹ kú ọdún Kérésìmesì! Ẹ kú iyedún! Ṣùgbọ́n, ní orúkọ Elédùmarè. . . jọ̀wọ́, má gbàgbé láti fún àwọn adúláwọ̀ lókun o.
Feliz Natal! Feliz Ano Novo! Mas, em nome do Todo-Poderoso Deus. . . por favor, não se esqueça de fortalecer o povo preto.
Ẹ kú àlàjá ọdún, o̩dún àṣeyọrí àtí àláfíà ni yíò jẹ́! - Feliz Ano Novo, será um ano de sucesso e paz!
Ẹ kú ọdún ẹ kú ìyèdún, ọ̀pọ̀ọ rẹ̀ lẹ ó ṣe láyé ! - Feliz Ano Novo, você fará muitas coisas boas na terra!
Ẹ kú ọdún titun! - Feliz ano novo!
Nenhum comentário:
Postar um comentário