Ọjọ́ Ìṣègùn Ìbílẹ̀ Áfíríkà Lágbàáyé.
Dia Mundial da Medicina Tradicional Africana.
Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações:
https://www.afro.who.int/pt/regional-director/speeches-messages/dia-da-medicina-tradicional-africana-2021#:~:text=No%20dia%2031%20de%20Agosto,do%20bem%2Destar%20no%20continente.
https://www.youtube.com/watch?v=yvqDDEZL2qE
Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò (vocabulário), àwọn ọ̀rọ̀ tá a sábà máa ń sọ (palavras comuns), àwọn ọ̀rọ̀ tá a sábà máa ń lò (palavras que usamos frequentemente), àkójọ ọ̀rọ̀ tá à ń lò lójoojúmọ́ (vocabulário do dia a dia), àlàyé ọ̀rọ̀, àlàyé àwọn ọ̀rọ̀ (glossário), àkójọ ọ̀rọ̀ (glossário, lista de palavras), àkójọ ọ̀rọ̀ púpọ̀ lágbárí (uma grande lista de palavras na cabeça), àkópọ̀ wóróhùn ọ̀rọ̀ dídára tí o mọ̀ (uma coleção de boas palavras que você conhece).
Nwọ́n, pron. pess. Eles, elas. Expressa uma ação que não é creditada a nenhuma pessoa em particular.
Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; neste caso, é posicionado antes do substantivo.
Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.
Wọn, pron. poss. Deles, delas.
Àjọ̀dún, s. Festival.
Ọjọ́, ijọ́, s. Dia.
Àyájọ́ Ọjọ́ Mọ̀ọ́kọ-Mọ̀ọ́kà Lágbàáyé, s. Dia Internacional da Alfabetização.
Àyájọ́ Ọjọ́ Àwọn Òṣìṣẹ́ Lágbàáyé, s. Dia Internacional dos Trabalhadores.
Ayẹyẹ Ọjọ́ Àwọn Òṣìṣẹ́ ọlọ́dọọdún, s. Comemoração anual do Dia do Trabalho.
Ọjọ́ Àwọn Ọ̀dọ́ Lágbàáyé, s. Dia Mundial dos Jovens.
Ìṣègùn Ìbílẹ̀ Áfíríkà, s. Medicina tradicional africana.
Ilẹ̀, s. Terra, solo, chão.
Ayé àtijọ́, ayéijọ́un, s. Mundo antigo.
Àdánidá, s. Natureza.
Ayé, gbogbo ẹ̀dá, àgbáyé, s. Universo. Èrò wọn ni pé sáyẹ́ǹsì ní tirẹ̀ ń ṣàlàyé nípa bí ìwàláàyè, ayé àti ọ̀run ṣe bẹ̀rẹ̀, nígbà tí ìsìn ń ṣàlàyé ìdí tá a fi dá àwọn nǹkan wọ̀nyí - Para elas, cabe à ciência explicar como a vida e o cosmos vieram à existência, ao passo que a religião deve explicar principalmente o porquê.
Ilẹ̀-ayé, ayé, ilé-ayé, s. Terra (planeta terra).
Plánẹ̀tì ilẹ̀-ayé, s. Planeta terra.
Àwòrán ẹlẹya mẹ́ta, s. Holograma.
Àgbáyé ti àwòrán ẹlẹya mẹ́ta, s. Universo holográfico.
Wíwò ayé, wiwò nípa ayé, wiwò nípa ayé náà, s. Cosmovisão.
Gbogbo, adj. Todo, toda, todos, todas.
Nenhum comentário:
Postar um comentário