Àwọn àjọ àgbáyé tí wọ́n fi Áfíríkà ṣe ibùjókòó. Organizações internacionais sediadas em África.
1. Ìmùlẹ̀ Àwọn Orílẹ̀-Èdè Arébíà - Liga Árabe.
2. Ẹgbẹ́ àwọn Ará Mùsùlùmí - Irmandade Muçulmana.
3. Ṣọ́ọ̀ṣì Ọ́tọ́dọ́ọ̀sì Ilẹ̀ Etiópíà - Igreja Ortodoxa Etíope.
4. Ṣọ́ọ̀ṣì Kimbanguist - Igreja Kimbanguista.
5. Ṣọ́ọ̀ṣì Coptic - Igreja Copta.
Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò (vocabulário), àwọn ọ̀rọ̀ tá a sábà máa ń sọ ( palavras comuns), àwọn ọ̀rọ̀ tá a sábà máa ń lò (palavras que usamos frequentemente), àkójọ ọ̀rọ̀ tá à ń lò lójoojúmọ́ (vocabulário do dia a dia), àlàyé ọ̀rọ̀, àlàyé àwọn ọ̀rọ̀ (glossário), àkójọ ọ̀rọ̀ (glossário, lista de palavras), àkójọ ọ̀rọ̀ púpọ̀ lágbárí (uma grande lista de palavras na cabeça), àkópọ̀ wóróhùn ọ̀rọ̀ dídára tí o mọ̀ (uma coleção de boas palavras que você conhece).
Nwọ́n, pron. pess. Eles, elas. Expressa uma ação que não é creditada a nenhuma pessoa em particular.
Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; neste caso, é posicionado antes do substantivo.
Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.
Wọn, pron. poss. Deles, delas.
Àwọn àjọ àgbáyé tí wọ́n wà ní Áfíríkà, Àwọn àjọ àgbáyé tí wọ́n fi Áfíríkà ṣe ibùjókòó, s. Organizações internacionais sediadas em África.
Tó wà ní Áfíríkà, tó fi Áfíríkà ṣe ibùjókòó, adj. Sediada em África.
Bàbá Alẹkisáńdíríà, aṣáájú Ṣọ́ọ̀ṣì Ọ́tọ́dọ́ọ̀sì ti Coptic, s. Patriarca de Alexandria, líder da Igreja Ortodoxa Copta.
Ṣọ́ọ̀ṣì Coptic nílẹ̀ Íjíbítì, s. Igreja Copta no Egito.
Kín ni ẹ lè sọ nípa àkòrí yìí? - O que dizer sobre este tema?
ResponderExcluirẸ jẹ́ ká mọ̀ ní ìsàlẹ̀👇... Diga-nos abaixo 👇. . .