Àwọn ìbéèrè pàtàkì (questões fundamentais)
Kéèyàn tó lè ní ojúlówó ìbàlẹ̀ ọkàn, èèyàn ní láti rí ìdáhùn sáwọn ìbéèrè pàtàkì yìí - Se você quiser ter verdadeira paz mental, precisa obter respostas para estas perguntas fundamentais:
1. Ta ni àwọn èèyàn mi, ta sì ni èmi? - Quem é o meu povo e quem sou eu?
2. Ibo làwọn èèyàn mi ti wá? - De onde veio o meu povo? Níbo ni mo ti wá? - De onde eu vim? Báwo ni mo ṣe dáyé? - De onde eu vim?
3. Ibo ni àwọn ènìyàn mi ń lọ? - Para onde meu povo está indo? Níbo ni mo ń lọ? - Para onde estou indo?
4. Kí làwọn èèyàn mi ń ṣe nínú ayé yìí? - O que meu povo está fazendo neste mundo? Kí ni mò ń ṣe nínú ayé yìí? O que estou fazendo neste mundo?
Nenhum comentário:
Postar um comentário