quarta-feira, 8 de novembro de 2023

Antissemitismo

Inúnibíni sí àwọn ará Sémítì (àwọn ará palẹ́sìnì) tí wọ́n ń bá ìpakúpa àwọn ènìyàn wọn jà.

Perseguição aos semitas (palestinos) que lutam contra o extermínio de seu povo.

Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações:

https://www.correiodopovo.com.br/not%C3%ADcias/pol%C3%ADcia/pol%C3%ADcia-federal-prende-dois-suspeitos-de-planejar-atos-terroristas-no-brasil-1.1415729

https://g1.globo.com/mundo/noticia/2023/10/17/brasileiros-convocados-pelo-exercito-de-israel-quem-pode-ir-a-guerra-e-quem-nao-pode-ser-chamado-veja-perguntas-e-respostas.ghtml


Àwọn ọ̀rọ̀-orúkọ tó tan mọ́ ọn - Substantivos relacionados: Orílẹ̀-èdè Palẹstínì, Orílẹ̀-èdè Palẹ́sìnì (Estado da Palestina), Bèbè Ìlàòrùn (Cisjordânia, West Banki), Àgbègbè Gásà (faixa de Gaza), Ìlà Oòrùn Jerúsálẹ́mù (Jerusalém Oriental), ọmọorílẹ̀-èdè Palẹstínì, ọmọ ilẹ̀ Palẹstínì (palestino), ọkùnrin ará Palẹstínì, ọkùnrin ilẹ̀ Palẹstínì (homem da Palestina, palestino do sexo masculino, homem palestino), obìnrin ará Palẹstínì (mulher da Palestina, mulher palestina), Àwọn ará Palẹstínì (palestinos), ìkórìíra ẹ̀yà Sémítì (antissemitismo), àwọn ará árábù (árabes), inúnibíni tí wọ́n ń ṣe kárí ayé (perseguição internacional, perseguição que estão fazendo em todo o mundo), inúnibíni sí àwọn ará Sémítì (perseguição aos semitas), inúnibíni sí àwọn ará Sémítì tí ń gbé ní Àgbègbè Gásà (perseguição aos Semitas que vivem na Faixa de Gaza), àwọn Júù (judeus), àwọn ènìyàn Sémí (povo semita), ètò ìjọba Násì ti ‘Bẹ́ńjámínì Nétáníyà (o regime nazista de Benjamin Netanyahu), Orílẹ̀-èdè Ísírẹ́lì (Nação de Israel). Àwọn ajẹtífù tó tan mọ́ ọn - Adjetivos relacionados: ti orílẹ̀ èdè Palẹstínì, tí a bí ní ilẹ̀ Palẹstínì (da Palestina, que nasceu na Palestina, palestino), tí wọ́n ń bá ìpakúpa àwọn ènìyàn wọn jà (que lutam contra o massacre do seu povo).

Nenhum comentário:

Postar um comentário