sexta-feira, 2 de maio de 2025

Transformação

 Àwọn àpẹẹrẹ díẹ̀ (alguns exemplos): 

- Yíyí ọ̀rá padà sí èròjà gúlúkóòsì - Transformação de gordura em glicose. 

Àyípadà nínú apilẹ̀ àbùdá tó ṣàdédé wáyé nínú ara - Mudança genética repentina que ocorre no corpo.

- Àgbáálá ayé gbígbéṣẹ́, tí ń yí pa dà - Universo dinâmico e em constante mutação.

- Fáírọ́ọ̀sì tó ń máa ń tètè sọ ara ẹ̀ di púpọ̀ - Vírus que se multiplica rapidamente.

- Ìsọdimímọ́ orúkọ rẹ̀ - Santificação de seu nome 

 -Yíya orúkọ Ọlọ́run sí mímọ́ - Santificação do nome de Deus.

- Sísọ orúkọ Ọlọ́run di mímọ́ - Santificação do nome de Deus.

- Ìtàn àwọn ènìyàn tí wọ́n pa lára dà di ìkookò panipani lóru - Contos de homens que à noite se transformam em lobisomens assassinos.

- Ìyípadà ológo - Transfiguração.

Nenhum comentário:

Postar um comentário