Ìṣẹ̀lẹ̀ ìdánilóró ti àwọn olóko lòdì sí ẹ̀yà ènìyàn guaraní Kaiowá.
Atentado terrorista de ruralistas contra etnia guarani Kaiowá.
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário)
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ọ̀gbìn, s. Planta, plantador.
Àgbẹ̀, s. Fazendeiro, agricultor.
Olóko, s. Ruralista, fazendeiro, latifundiário.
Iṣẹ́ Àgbẹ̀, oko-ríro, s. Agicultura.
Oko, s. Orixá da agricultura. Fazenda, roça, plantação.
Okoṣowó, s. Agronegócio.
Iṣẹ́, òwò, ìṣowó, nkan ti o kan ni, ẹjọ́ tó kan ni, s. Negócio.
Ìṣẹ̀lẹ̀ ìdánilóró, s. Atentado terrorista.
Ti, prep. De (indicando posse). Quando usado entre dois substantivos, usualmente é omitido. Ilé ti bàbá mi = ilé bàbá mi ( A casa do meu pai).
Àwọn, wọn, pron. Eles, elas. Indicador de plural.
Lòdì sí, prep. Contra.
Mọ́, prep. Contra.
Ẹ̀yà ènìyàn, s. Etnia.
Guaraní Kaiowá, s. Guarani Kaiowá.
Entidades e pessoas que apoiam genocídio e atentados terroristas contra indígenas.
Àwọn ààrẹ, s. Presidentes.
Igbákejì Ààrẹ, s. Vice-presidente.
Ilé-ẹjọ́ Gígajùlọ, s. Supremo Tribunal Federal (STF).
Aṣàkóso ìdájọ́, s. Ministro da Justiça.
Àwọn onídàájọ́, s. Juízes.
Ìbùjókó aṣòfin ti olóko ní Kọ́ngrésì Onítọmọorílẹ̀-èdè (Ilé Aṣòfin Àgbà àti Ilé Aṣòfin Kéreré), s. Bancada ruralista no congresso nacional (Senado e Câmara dos Deputados).
Àwọn amúnisìn tipátipá, s. Totalitários (facistas, nazistas, neonazistas, hitleristas).
Ẹgbẹ́ ọmọ-ogun ti oko aṣòdì sí ọmọ-ìbílẹ̀, s. Milícia rural anti-indígena.
Ọlọ́pàá, s. Polícia.
Àwọn ológun, s. Militares.
Ọ̀dáràn, apànìà, apani, s. Criminoso, assassino, malfeitor, culpado, matador.

Àwọn bálẹ̀, s. Prefeitos.
Àwọn aṣòfin ìlú, s. Vereadores.
Àwọn gómìnà, s. Governadores.