Ìjídìde Dẹmọkrátíkì ti àwọn Èèyàn Índíà.
A Revolução Democrática do Povo Indiano.
Mapa mostrando os distritos onde o movimento naxalita está ativo (2007)
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário).
Àwọn èèyàn tí à ń wá ìyípadà nínú ìṣèlú, s. Militantes políticos.
Ajàjàgbara, adógunsílẹ̀, s. Militante, revolucionário.
Ẹgbẹ́ ajàjàgbara, s. Grupo militante, grupo ativista.
Àwọn ẹgbẹ́ ajàjàgbara kọ́múnístì tó ń ṣiṣẹ́ nínú Orílẹ̀-èdè Índíà, s. Naxal, Naxalita, Naksalvadi. É um termo genérico usado para se referir a grupos de militantes comunistas que operam em diferentes partes da Índia.
Ìṣemarksi, àbá èrò orí marksi, s. Marxismo.
Ìṣemarksi-ìṣelenin, àbá èrò orí Marksi àti Lenin, s. Marxismo-leninismo. Marxismo-leninismo, termo resultante da justaposição das palavras marxismo e leninismo, designa a doutrina oficial da tendência majoritária do movimento comunista - isto é, dos partidos e dos estados alinhados à antiga URSS ou à República Popular da China - durante a maior parte do século X
Ìṣemao, s. Maoismo. Doutrina do político Mao Tse-tung (1893-1976) e líder máximo da revolução socialista chinesa e primeiro presidente da República Popular da China.
Ìjídìde, s. Revolução.
Ìjídìde Fránsì, s. Revolução francesa.
Ìjídìde proletárì, s. Revolução proletária.
Jídìde, s. Revolucionar.
Adógunsílẹ̀, s. Revolucionário. Aquele que faz uma guerra, distúrbios ou revolução
Ogun abẹ́lé, ogun ajàjàgbara jà, ẹgbẹ́ onísùnmọ̀mí , s. Guerrilha.
Ogun ajàjàgbara jà, s. Forças guerrilheiras.
Àwọn ọmọ ogun kọ́múníìsì, s. Guerrilhas. comunistas.
Àwọn ọmọ ogun ọlọ̀tẹ̀, s. Tropas rebeldes.
Ẹgbẹ́ ọmọ ogun àwọn ọlọ̀tẹ̀, s. Exército de rebeldes.
Òléwájú, s. Líder, capataz.
Ìdáǹdè, s. Redenção, libertação, emancipação.
Òmìnira, ònnira, s. Liberdade.
Ilómínira, s. Independência.
Iwájú, s. Frente.
Àgbájọ, s. Organização.
Ẹgbẹ́, s. Sociedade, associação, clube, partido. Companheiro, par. Posição, classe.
Àwùjọ apániláyà, ẹgbẹ́ àwọn apániláyà, àwùjọ àwọn apániláyà , s. Grupo terrorista, organização terrorista.
Apániláyà, s. Terrorista.
Ìpániláyà, s. Terrorismo.
Ìwà ìpániláyà tó kárí ayé lọ, s. Terrorismo internacional, terrorismo global.
Ìṣòro ìwà ìpániláyà, s. Problema de terrorismo.
Ohun tó gbàfiyèsí nínú ọ̀ràn ìpániláyà jákèjádò ayé, s. Atos espetaculares de terrorismo no mundo inteiro.
Àìráragba-nǹkan-sí, s. Intolerância.
Ìjà ẹ̀yà, s. Violência étnica.
Ìpẹ̀yàrun, ìpakúpa, s. Genocídio, holocausto.
Tòṣèlúaráìlú, adj. Democrática, democrático.
Ẹgbẹ́ Dẹmọkrátíkì, s.Partido Democrata.
Ìjọba àjùmọ̀ṣe, s.Governo de ação conjunta, governo de parceria.
Ìjọba tí ó fi àyè gba ará ìlú láti ní ìpín nínú ètò ìlú, s. Governo que permite e necessita que os cidadãos tenham parte na organização da cidade ou do país.
Òṣèlúaráìlú òṣèlú aṣojú, s. Democracia representativa.
Orílẹ̀-èdè olómìnira, s. República.
Òṣèlú aláwùjọ, s. Social-democracia.
Àjọṣepọ̀, s. Federação.
Ìṣeolómìnira ijọ́hun, s. Republicanismo clássico.
Ọ̀làjú, s. Iluminismo, civilização.
Ẹgbẹ́ Òṣèlú, s. Partido político.

Ìṣèlú, s. Política.
Òṣèlú, aṣèlú, s. Político.
Ààrẹ, s. Presidente.
Òṣèlúaráìlú, ìjọba tiwa-n-tiwa, ìjọba àjùmọ̀ṣe, ìjọba tí ó fi àyè gba ará ìlú láti ní ìpín nínú ètò ìlú, s. Democracia.
Ẹgbẹ́ Òṣèlú ti Ìjídìde Tòṣèlúaráìlú, s. Partido da Revolução Democrática.
Àwọn oníṣòwò ará ilẹ̀ Íńdíà àti Arébíà, s. Comerciantes indianos e árabes, mercadores indianos e árabes.
Àwọn ará Íńdíà, s. Indianos.
Ọmọ orílẹ̀-èdè, s. Cidadão.
Ti ènìà, adj. Humano.
Ẹ̀dà èèyàn, s. Homem, ser humano. O indivíduo que pertence à espécie humana.
Èèyàn, s. Povo, gente, pessoas.
Ajọ̀bọ, irúọmọnìyàn, àwọn irúọmọnìyàn, s. Hominoidea. A superfamília de mamíferos, incluindo macacos antropóides e os seres humanos.
Ọmọnìyàn, ọmọ ènìyàn, s. Homo sapiens.
Ènìà, ènìyàn, s. Pessoa. É também usado de forma impessoal para significar povo, seres humanos, alguém.
Aráàlú, s. Povo do lugar, da cidade, da região.
Ará, ènìyàn, s. Povo.
Iye ènìyàn inú ìlú, s. População.
Ọ̀pọ̀ ènìà aláìníláárí, àwọn "ọmọ ìta", s. Plebe, populacho, povo, ralé, populaça.
Àwọn èèyàn Júù, s. Povo judeu, judeus.
Àwọn ará Fránsì, s. Os franceses, povo francês.
Àwọn ènìyàn ará Fránsì, s. As pessoas da França.
Olómìnira ilẹ̀ Índíà, s. República da Índia.
Índíà, ilẹ̀ Índíà, Orílẹ̀-èdè Índíà, s. Índia.
Àwọn ará Índíà, s. Indianos, povo indiano.
Àwọn èèyàn Gíríìkì, s. Povo grego.
Ìjọba àjùmọ̀ṣe, s. Democracia.
Ìjọba ológun, s. Ditadura militar, governo militar.
Ìṣeàìlólórí, s. Anarquismo.
Ìṣekápítálístì, ìṣeòwòèlé, kapitálísíìmù, s. Capitalismo.
Aṣekápítálístì, s. Capitalista.
Ìsọ-lẹ́tà-di-ńlá, s. Capitalização.
Kó ọrọ̀ jọ, kó owó jọ, s. Capitalizar.
Ìṣesósíálístì, s. Socialismo.
Ìṣekọ́múnístì, s. Comunismo.
Ìsọ̀kan àwọn Orílẹ̀-èdè Olómìnira Sófíẹ́tì Sósíálístì, s. União das Repúblicas Socialistas Soviéticas
Ìsọ̀kan Sófìẹ̀tì, s. União Soviética.

Ìṣesósíálístì ti ọ̀rọ̀ lásán àròsọ, s. Socialismo utópico.
Ìṣesósíálístì ti sáyẹ́nsì, s. Socialismo científico.
Ìṣeohunayé ti ìtàn, s. Materialismo histórico.

Ṣiṣẹ́, s. Trabalhar, agir, atuar.
Nínú, prep. Dentro, no interior de.
Inú, s. Estômago, ventre, interior, interno, no íntimo de.
Kọnfukiọsi, s. Confúcio.
Táò, ìsìn Táò, s. Tao, taoísmo.
Ìṣe Búdà, ẹ̀sìn Búdà, s. Budismo.
Ìṣe kọnfukiọsi, s. Confucionismo.
Híńdù, Ìṣehíndù, ẹ̀sìn-ìn Híndù, s. Hinduísmo
Ìsìláàmù, ìmàle, s. Islamismo.
Ìṣekèfèrí titun, s. Neopaganismo, wicca.
Jaini, s. Jainismo.
Ìsìn àwọn Júù, s. Judaísmo
Ìsìn Sikh, s. Siquismo.
Ṣintó, ẹ̀sìn ìbílẹ̀ Jèpánù, ẹ̀sìn ṣintó, s. Xintoísmo.
Ṣọ́ọ̀ṣì ti pẹ́ńtíkọ́sì, ìjọ ti pẹ́ńtíkọ́sì, ilé Ọlọ́run ti pẹ́ńtíkọ́sì, s. Igreja pentecostal.
Ìjọ Ajíhìnrere, s. Igreja evangélica.
Ìjọ Kátólìkì, Ṣọ́ọ̀ṣì Kátólíìkì, s Igreja católica.
Ẹ̀sìn Kristi, ìsìn Kristi, ẹ̀sìn onígbàgbọ́, kirisẹ́ńdọ̀mù, s. Cristianismo.
Ìṣeìjọánglíkánì, s. Anglicanismo.
Ìjọ ilẹ̀ Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì, s. Igreja anglicana.
Ìṣepurẹsibiteriani, s. Presbiterianismo.
Ṣọ́ọ̀ṣì Mẹ́tọ́díìsì, s Igreja metodista.
Ìjọ onígbàgbọ́, s. Congregação cristã.
Ṣọ́ọ̀ṣì Pùròtẹ́sítáǹtì, s. Igreja protestante.
Ìjọ Jéésù Lótìítọ́, s. Verdadeira Igreja de Jesus.
Ṣọ́ọ̀ṣì Ọ́tọ́dọ́ọ̀sì ti Ìlà Oòrùn, s. Igreja ortodoxa oriental.
Baháí, s. Fé bahá'í
Ẹ̀sìn òrìṣà, s. Religião de orixá.
Kandomblé, s. Candomblé.
Santería, s. Santeria.
Fúdù, s Vodum, vodun, voodoo ou vodu.
Ìgbàgbọ́ pé ẹ̀mí wà nínú ohun gbogbo, s. Animismo.
Ìjọsìn Sátánì, s. Satanismo.
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà, s. Testemunhas de Jeová.
Ìjọ Jésù Krístì ti àwọn Ènìyàn Mímọ́ Ọjọ́-ìkẹ́hìn, s. Igreja de Jesus Cristo dos Santos dos Últimos Dias.
Ẹ̀sìn àgbọn, s. Religião do coco.
Àìgbọlọ́rungbọ́, àìgbà-pọ́lọ́run-wà, s. Ateísmo.
Agbátẹrù ìgbàgbọ́ Ọlọ́run-kò-ṣeé-mọ̀, s. Agnosticismo.
Iṣẹ́ àjẹ́, iṣẹ́ oṣó, iṣẹ́ òkùnkùn, s. Feitiçaria.
Oògùn, idán pípa, iṣẹ́ àjẹ́, s. Magia.
Ẹ̀sìn ìbílẹ̀, iṣe gba àwọn ẹ̀mí àìrí gbọ́, s. Xamanismo.
Ìbẹmìílò, ìbẹmìílò ká, s. Espiritismo.
UMBANDA, s. Umbanda. Ó ju àádọ́rin mílíọ̀nù ọmọ ilẹ̀ Bràsíl tí wọ́n sọ pé ó ń lọ́wọ́ nínú ẹ̀sìn kandomblé, Umbanda, Ṣàngó, àtàwọn ẹ̀sìn míì táwọn Adúláwọ̀ mú wọ orílẹ̀-èdè náà - Diz-se que mais de 70 milhões de brasileiros, direta ou indiretamente, estão ligados ao candomblé, umbanda, xangô e outras religiões afro-brasileiras.
Ṣọ́ọ̀ṣì lágbàáyé, ṣọ́ọ̀ṣì pátápátá, s. Igreja Universal.
Ilẹ̀ọba, ìjọba, s. Reino.
Gómìnà, s. Governo.
Ọba, s. Rei.

Orílẹ̀-èdè Olómìnira, s. Republica.
Ìpínlẹ̀, orílẹ̀-èdè, s. Estado.
Ìpínlẹ̀, orílẹ̀-èdè, s. Estado.
Àgbègbè, s. Território, enclave. Àgbègbè tó kẹ́yìn níbi tí àwọn Mùsùlùmí ń gbé ní orílẹ̀-èdè Sípéènì - Último enclave mouro na Espanha.
Ìpínlẹ̀, s. Fronteira, demarcação, limite entre duas cidades, Estado ( SP, RJ).
Orílẹ̀, s. Nome que denota um grupo de origem ou clã.
Ilẹ̀, s. Terra, solo, chão.
Orílẹ̀-èdè, s. Estado, nação.
Ìlú, s. Cidade, terra, , região, país.
Ìlù, s. Tambor, um tipo de toque de atabaque.
Ìlù, s. Atabaque, tambor.
Ìlu, s. Verruma, perfurante.
Ìlú etí, s. Tímpano.
Èdè, s. Idioma, língua, dialeto.

Ti lọ, adj. Desaparecido.
Tí, pron. rel. Que, o qual, do qual, cujo.
Tí, conj. Se. Enquanto, ao mesmo tempo que.
Tí, prep. Desde que.
Tí, v. Bater com a mão ou com algo na mão, acertar o alvo.
Tí, adv. Onde, quando.
Ti, prep. de ( indicando posse). Quando usado entre dois substantivos, usualmente é omitido. Ilé ti bàbá mi = ilé bàbá mi ( A casa do meu pai).
Ti, ti...ti, adj. Ambos... e. Ti èmi ti ìyàwó mi - ambos, eu e minha esposa.
Ti, v. Ter (verb. aux.). Arranhar. Pular.
Ti, v. interrog. Como. Ó ti jẹ́? - Como ele está.
Ti, adv. pré-v. Já. Indica uma ação realizada.
Ti, àti, conj. E.
Ti, part. pré-v. 1. Usada para indicar o tempo passado dos verbos. Èmi ti máa rìn lálé - Eu costumava caminhar à noite. 2. É usada com báwo ni - como - quando se deseja expressar sentimento e posicionada antes do verbo principal. Báwo ni àwọn ti rí? - Como eles estão?.
Tìti, adv. Tremendamente, violentamente.
Títí, adv. Continuamente, constantemente.
Títí, prep. Até.
Tìtì, adv. Tremulamente, balançadamente.
Títì, adj. Trancado, que deve ser empurrado, fechado.
Títì, ọ̀nà, s. Via pública, rua, passagem.
Ti... ti, adj. Ambos... e. Ti èmi ti ìyàwó mi - Ambos, eu e minha esposa.
Títi-àiyé, adv. Eternamente.
Títí dé, prep. Até. (referindo-se a um local ou espaço).
Títí di, prep. Até. (referindo-se a período de tempo).
Títí láé, títí láí, adv. Perpetuamente, para sempre, definitivamente.
Títilọ, adv. Continuadamente, assim por diante.
Ń, v. Estar. Indicador de gerúndio.
Ń, adv. pré-verbal. O prefixo "ń" no verbo indica não só uma ideia presente como uma ação que esteja ocorrendo, em desenvolvimento (gerúndio). Pela sua função, é equivalente ao verbo auxiliar estar em português.
L', pref. No.
L, pref. Forma modificada da palavra ní quando seguida de palavra iniciada por vogal diferente de i.
Ní, prep. Contração da preposição ní e substantivo. Quando a vogal inicial do substantivo não é i, a consoante n da preposição se transforma em l, e a vogal i toma forma de vogal do substantivo posterior. Mas se a vogal do substantivo é i, ela é eliminada. Ní àná ( l'ánàá ). Ní ilé (ní'lé)
Ní, part. enfática. Usada na construção de frases, quando o verbo tiver dois objetos, o segundo objeto é precedido por " ní".
Ní, prep. No, na, em. Usada para indicar o lugar em que alguma coisa está. Indica uma posição estática.
Ní, v. Ter, possuir, dizer.Transportar carga em um barco ou navio. Ocupar, obter, pegar.
Ni, v. Ser, é.
Nì, pron. dem. Aquele, aquela. Requer alongamento da vogal final da palavra que o antecede somente na fala. Ex.: Fìlà ( a ) nì = aquele chapéu.
Tó, v. Bastar, ser o bastante, ser o suficiente. Ser igual a, equivaler.
Tó, adj. Suficiente, bastante.
Tó, pron. rel. Que. Contração de tí ó. A partícula ó é sempre usada se tí for seguida por um verbo. Antes de pronome e substantivo, ela não é usada. Ọkùnrin tó pè mí ẹ̀gbọ́n mi - O homem que me chamou é meu irmão.
Tó, tóó, adv. pré-v. Antes de. É antecedido por kí. Kí òun tó lọ, ó sọ̀rọ̀ pẹ̀lú mi - Antes de ele ir, eu conversei com ele.

O, ò, pref. Adicionado ao verbo para formar substantivos que indicam alguém que faz.
O, òo, part. adv. 1. Forma frases exlamativas para ênfase. Ó ti dé o! - Ele já chegou! 2. A forma òo é usada para responder a uma saudação, caso não exista outra estabelecida, ou para concordância diante de uma outra expressão. Ẹ káalẹ́ o - Boa-noite; Òo (respondendo).
Òun, ó, pron. pess. Ele, ela.
O, pron. pess. Você
Ọ, pron. Você. É usado dessa forma depois de verbo ou preposição.
Ọ, pref. Adicionado ao verbo para formar substantivos que indicam alguém que faz. Ọdẹ (caçador) e dẹ (caçar).
Ọ, ọ́, pron. da 3ª pessoa do singular representado pela repetição da vogal final do verbo de uma sílaba ( caso objetivo 3ª pessoa). Ó ṣọ́ - Ele vigiou, Ó ṣọ́ ọ - Ele a vigiou.
Ọ, ẹ, pron. oblíquo. Você.
Kò, ò, adv. Não. Faz a negativa dos verbos regulares.
Ìjọba Kọ́múníìsì, s. Governo comunista.O, òo, part. adv. 1. Forma frases exlamativas para ênfase. Ó ti dé o! - Ele já chegou! 2. A forma òo é usada para responder a uma saudação, caso não exista outra estabelecida, ou para concordância diante de uma outra expressão. Ẹ káalẹ́ o - Boa-noite; Òo (respondendo).
Òun, ó, pron. pess. Ele, ela.
O, pron. pess. Você
Ọ, pron. Você. É usado dessa forma depois de verbo ou preposição.
Ọ, pref. Adicionado ao verbo para formar substantivos que indicam alguém que faz. Ọdẹ (caçador) e dẹ (caçar).
Ọ, ọ́, pron. da 3ª pessoa do singular representado pela repetição da vogal final do verbo de uma sílaba ( caso objetivo 3ª pessoa). Ó ṣọ́ - Ele vigiou, Ó ṣọ́ ọ - Ele a vigiou.
Ọ, ẹ, pron. oblíquo. Você.
Kò, ò, adv. Não. Faz a negativa dos verbos regulares.
Ìjọba àjùmọ̀ṣe, s. Democracia.
Ìjọba ológun, s. Ditadura militar, governo militar.
Ìṣeàìlólórí, s. Anarquismo.
Ìṣekápítálístì, ìṣeòwòèlé, kapitálísíìmù, s. Capitalismo.
Aṣekápítálístì, s. Capitalista.
Ìsọ-lẹ́tà-di-ńlá, s. Capitalização.
Kó ọrọ̀ jọ, kó owó jọ, s. Capitalizar.
Ìṣesósíálístì, s. Socialismo.
Ìṣekọ́múnístì, s. Comunismo.
Ìsọ̀kan àwọn Orílẹ̀-èdè Olómìnira Sófíẹ́tì Sósíálístì, s. União das Repúblicas Socialistas Soviéticas
Ìsọ̀kan Sófìẹ̀tì, s. União Soviética.
Ìjídìde proletárì, s. Revolução proletária.
Ẹgbẹ́ kọ́múnístì, s. Partido comunista.
Aṣekọ́múnístì, s. Comunista.Ìṣeàìlólórí, s. Anarquismo.