Ìmọ̀lára (sensação, emoção, percepção).
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário).
Ìmọ̀lára pé nǹkan kanni lára lọ́nà tó gbádùn mọ́ni, s. Sensação tátil de forma agradável, sensação de prazer. Wọ́n ṣàkíyèsí pé, ohun tó ń fa irú ìmọ̀lára pé nǹkan kanni lára lọ́nà tó gbádùn mọ́ni yìí ni àkójọpọ̀ iṣan oríṣi kejì tó wà nínú awọ ara wa, èyí tí àwọn fọ́nrán iṣan àkànṣe kan wà nínú rẹ̀ - Essa sensação de prazer, segundo eles, era causada por uma segunda rede de nervos na pele, que consiste de fibras de lenta condução chamadas fibras C táteis.
Èrò pé ‘kò sóhun tó lè ṣe mi, s. Sensação de invulnerabilidade. Èrò pé ‘kò sóhun tó lè ṣe mi’ yìí wọ́pọ̀ láàárín àwọn èwe gan-an - Essa sensação de ‘invulnerabilidade’ é muito comum nos adolescentes.
Àròdùn ọ̀hún ò lọ, s. Sensação de mal-estar. Mo wá bẹ̀rẹ̀ sí fi taratara kópa nínú iṣẹ́ ìwàásù, àmọ́ àròdùn ọ̀hún ò lọ - Aumentei meus esforços na pregação, mas a sensação de mal-estar continuou.
Ọkàn mi balẹ̀ ní gbogbo ìgbà, s. Sensação de segurança. Ìyẹn sì máa ń jẹ́ kí ọkàn mi balẹ̀ ní gbogbo ìgbà - Isso me dava uma sensação de segurança.
Ìbàlẹ̀-ọkàn, Ìbàlẹ̀-àyà, s. Paz de espírito, paz da mente, sensação de paz, serenidade.
Ìwà ẹ̀dá mu pé kó o banú jẹ́, kó o sì ní ẹ̀dùn ọkàn, s. Comportamento natural que faz você se sentir magoado e deprimido. Báwọn òbí ẹ bá kọra wọn sílẹ̀ tàbí tí ọ̀kan lára wọn bá ṣàìsí, ó bá ìwà ẹ̀dá mu pé kó o banú jẹ́, kó o sì ní ẹ̀dùn ọkàn - É natural ficar triste ou ter a sensação de perda caso seus pais tenham se divorciado ou um deles tenha morrido.
Àárẹ̀ tẹ̀mí, s. Sensação de fadiga emocional ou espiritual. Bákan náà ni ṣíṣe àwọn ìgbòkègbodò tẹ̀mí déédéé lè ṣèrànwọ́ láti dín àárẹ̀ tẹ̀mí kù -De modo similar, atividades espirituais regulares podem ajudar a reduzir qualquer sensação de fadiga emocional ou espiritual.