sexta-feira, 19 de outubro de 2018

Nazismo no Brasil

Ọ̀pọ̀ àwọn ará Bràsíl fẹ́ Ìjọba Násì kan 
Muitos brasileiros querem um governo nazista.



A imagem pode conter: comida



Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).



Ọ̀pọ̀, s. Plenitude, grande quantidade, multidão.
Ọ̀pọ̀lọ́pọ̀, adj. Numeroso, abundante.

Onírúurú, adj. Vários, diferentes.
Púpọ̀, adj. Muito.
Púpọ̀-púpọ̀, adv. Abundantemente.

Àwọn, wọ́n, pron. pess. Eles, elas. Indicador de plural.
Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.
Wọn, pron. poss. Deles, delas.

Àwọn ará Bràsíl, s. Brasileiros.

Ọmọ orílẹ̀-èdè Bràsíl, ọmọ ilẹ̀ Bràsíl, s. Brasileiro, brasileira.

Ti orílẹ̀ èdè Bràsíl, adj. Do Brasil; 

Tó jẹ́ ọmọ bíbí ilẹ̀ Bìràsílì, tó jẹ́ ọmọ bíbí ilẹ̀ Bràsíl, tí a bí ní ilẹ̀ Bràsíl, adj. Brasileiro, brasileira.

Obìnrin ọmọ Bràsíl, obìnrin ọmọ ilẹ̀ Bràsíl, obìnrin ará Bràsíl, obìnrin tó jẹ́ ọmọ bíbí ilẹ̀ Bràsíl, s. Brasileira.

Ọkùnrin ọmọ Bràsíl, ọkùnrin ilẹ̀ Bràsíl, 

ọkùnrin ará Bràsíl, ọkùnrin tó jẹ́ ọmọ bíbí ilẹ̀ Bràsíls. Homem Brasileiro.

Ẹlẹ́yàpúpọ̀, s. Indivíduo mestiço, colorido ou multirracial.
Adúláwọ̀, s. Negro.

Ènìyàn dúdú, s. Negro.
Dúdú, v. Ser preto.
Dúdú, adj. Negro.

Ará, s. Parente, habitante de um lugar, um conhecido, irmandade. Orílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ará ilẹ̀ Ṣáínà - República Popular da China.
Ará, s. Parente, habitante de um lugar, um conhecido, irmandade. Orílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ará ilẹ̀ Ṣáínà - República Popular da China.
Èèpo, s. Palha, casca, pele, vagem, concha.
Awọ ara, s. Pele.
Awọ, s. Pele humana ou de animal, pelo.

Ẹnì, s. Pessoa.
Ẹní, s. Esteira, capacho.

Fẹ́, v. Querer, desejar.  
Ìtàn lásan, s. História em vão, mito. 
Àròsọ, s. Rumor, boato, hipótese, mito. 
Àlọ́, s. Mito ( enigma, adivinhação). 
Ìtàn àròsọ ayé, s. Mito. 
Ìtàn, s. Mitos, histórias, episódio. 
Èrò tí kò tọ́, s. Idéia equivocada, ideia errada, mito.
Tó wà nínú wa, adj. Que está em nós.
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Kúbà, s. República de Cuba.
Orílẹ̀-èdè Olómìnira Aparapọ̀ ilẹ̀ Bràsíl, s. República Federativa do Brasil. Ìwé ìròyìn kan tí wọ́n ń tẹ̀ lórílẹ̀-èdè Bràsíl sọ pé irú ìwàásù bí èyí làwọn ìsìn kan lórílẹ̀-èdè Bràsíl sábà máa ń ṣe - Essa é a mensagem difundida por certos grupos religiosos no Brasil, segundo um jornal desse país.
Orílẹ̀-èdè Bràsil, ilẹ̀ Bràsíl, s. Brasil, Pindorama.
Ìpínlẹ̀ Ogunlọ́gọ̀ Orílẹ̀-èdè ilẹ̀ Bòlífíà, s. Estado Plurinacional da Bolívia
Orílẹ̀-èdè Olómìnira Bòlífárì ilẹ̀ Fẹnẹsúélà, s. República Bolivariana da Venezuela.
Orílẹ̀-èdè Fẹnẹsúélà, ilẹ̀ Fẹnẹsúélà, s. Venezuela.
Ìmúnisìn tipátipá, ìjọba ìmúnisìn tipátipá, s. Totalitarismo (hitlerismo, fascismo, nazismo, nacional-socialismo).
Ìjọba Aláṣẹ Oníkùmọ̀, s. Facismo.

Ti ìpilẹ̀ṣẹ̀, ti ìpilẹ̀ṣẹ̀pàtàkì, adj. Substancial, medular, crucial, relevante, primeiro, primordial, mestre, principal, necessário, importante, básico, capital, essencial, imprescindível, indispensável, vital, elementar.
Ìṣekápítálístì, ìṣeòwòèlé, kapitálísíìmù, s. Capitalismo.
Aṣekápítálístì, s. Capitalista.
Ìsọ-lẹ́tà-di-ńlá, s. Capitalização.
Kó ọrọ̀ jọ,  kó owó jọ, s. Capitalizar.
Ìṣesósíálístì, s. Socialismo.
Ìṣekọ́múnístì, s. Comunismo.
Ìjọba Násì, s. Nazismo.
Ìjọba Kọ́múníìsì, s. Governo comunista.
Ìsọ̀kan àwọn Orílẹ̀-èdè Olómìnira Sófíẹ́tì Sósíálístì, s. União das Repúblicas Socialistas Soviéticas
Ìsọ̀kan Sófìẹ̀tì, s. União Soviética.
Lòdì sí òṣèlúaráìlú, adj. Antidemocrático.

Ìjọba àjùmọ̀ṣe, s. Democracia.
Ìjọba ológun, s. Ditadura militar, governo militar.
Ìjídìde proletárì, s. Revolução proletária.

Ẹgbẹ́ kọ́múnístì, s. Partido comunista.
Aṣekọ́múnístì, s. Comunista.
Ìṣeàìlólórí, s. Anarquismo.
Ìṣesósíálístì ti ọ̀rọ̀ lásán àròsọ, s. Socialismo utópico.
Ìṣesósíálístì ti sáyẹ́nsì, s. Socialismo científico.
Ìṣeohunayé ti ìtàn, s. Materialismo histórico.
Ìjídìde proletárì, s. Revolução proletária.

Àwọn kan, pron. Alguns. Ó lè ṣòro fún àwọn kan láti gba ìbáwí - Para alguns, isso pode ser um verdadeiro desafio.
Àwọn kan lára àwọn, pron. Alguns dos.  
Àwọn lẹ́rìí kan, s.  Algumas testemunhas.   Àmọ́ o, àwọn kan ò lè lo gbogbo àkókò wọn lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn báyìí torí ipò tó yí wọn ká -  É claro que alguns não podem servir no tempo integral no momento por causa de suas circunstâncias. 
Àwọn Kristẹni kan, s. Alguns cristãos. Àwọn kan ti nígbàgbọ́ rí, àmọ́ wọn ò dúró sínú ìfẹ́ Ọlọ́run - Alguns que tinham fé não permaneceram no amor de Deus. Àwọn onímọ̀ sáyẹ́ǹsì kan ronú pé, níwọ̀n bó ti jẹ́ pé kò tíì pẹ́ tí ọ̀rọ̀ yíyí àbùdá irè oko padà bẹ̀rẹ̀, ó yẹ kí àyẹ̀wò ṣì máa lọ lórí rẹ̀ nípa àwọn ewu tó lè ṣe fún àwọn tó ń jẹ ẹ́ - Alguns cientistas acham que é muito cedo para avaliar os alimentos GM e que seriam necessários mais testes para detectar possíveis riscos para os consumidores.
Àwọn akéde kan, s. Alguns publicadores. 

Kàn án mọ́gi!, v. imper. Crucifica-o!, Para a estaca com ele!  Bẹ̀rẹ̀ sí fẹ̀sùn kàn án - Começou a acusá-lo.
Ìkan, ọ̀kan, num.  Um.
Kan, v. Tornar azedo.
Kan, adj. Amargo, ácido, azedo. Longe, ao largo.
Kan, num. e art. Um, uma. 

Kàn, adv. pré. v. Somente, simplesmente.
Kàn, v. Atingir, tocar, alcançar. Pregar com um martelo. Bater na porta, bater com a cabeça como um carneiro. Girar, retornar, fazer um rodízio. Referir-se a, aludir, recorrer. Devolver, interessar alguém.
Kán, v. Pingar, gotejar ( a chuva ou qualquer líquido). Quebrar, partir, estalar algo sólido.
Mọ́gi, s. Estaca. 

Ilẹ̀, s. Terra, solo, chão.
Ilẹ̀ Bràsíl, Bràsíl, s. Brasil, Pindorama.
Orílẹ̀-èdè, s. Nação, país.
Orílẹ̀, s. Grupo de origem ou clã.
Èdè, s. Língua, idioma, dialeto, linguagem.
Olómìnira, adj. Independente.
Àpapọ̀, s. Soma, total, combinação, ato de unir, de juntar
Aparapọ̀, adj. Federativa.

Ààrẹ, s. Presidente.
Ìjọba, s. Governo, reino.
Gómìnà, s. Governo. 
Àkóso, àkóso ìlú, s. Restrição, controle, governo, administração. Àkóso lọ́wọ́: Regulado por. Àkójọ àwọn gómìnà ìpínlẹ̀ Nàìjíríà - Lista de governadores dos estados da Nigéria. 
Ìtọ́nà, s. Governo, tutela. 
Ìfọ̀nàhàn, s. Direção, guia.
Ìjọba-araẹni, s. Governo autônimo.
Ìjọba kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà, s. Apartheid, governo do apartheid. Lẹ́yìn tó fi ilé ìwé sílẹ̀, ó ṣiṣẹ́ sójà ìjọba kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà tẹ́lẹ̀ rí ti Gúúsù Áfíríkà - Depois de deixar a escola, serviu no exército da África do Sul no anterior governo do apartheid. Lákòókò tá à ń sọ yìí, Gúúsù Ìwọ̀ Oòrùn Áfíríkà wà lábẹ́ àkóso ìjọba kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà ti Gúúsù Áfíríkà - Naquela época, a África do Sudoeste estava sob o regime do apartheid (segregação racial), da África do Sul.
Ráíkì, s. Reich, reinado, região, rico, um império, reino, nação. Ìtúká Ráíkì Kẹta - Dissolução do Terceiro Reich.
Ti mú, adj. Preso, detido. “Wọ́n ti mú mi, wọn ò sì gbọ́ ẹjọ́ mi tí wọ́n fi dájọ́ ikú fún mi -  “Fui detido e sentenciado à morte — sem ter tido um julgamento.
Sí ọgbà ẹ̀wọ̀n, prep.+ s. Para a prisão.
Lọ́gbà ẹ̀wọ̀n, prep. + s. Na prisão. 
Láwọn àgọ́ ìṣẹ́niníṣẹ̀ẹ́, prep. + s.  Nos campos de concentração.
Tó wà ní àwọn àgọ́ ìṣẹ́niníṣẹ̀ẹ́, adj. Que estão nos campos de concentração.
Àgọ́ ìṣẹ́niníṣẹ̀ẹ́, s. Campo de concentração. 
Ọmọ ogun adàlúrú, s. Guerrilheiro.

Àwọn gbólóhùn (frases)


Ẹni tí ó jẹ́ ìtàn àròsọ -Aquele que é mito.
Ẹni tí ó jẹ́ ìtàn lásanAquele que é mito.
Ilẹ̀  Bràsíl ló jẹ wá lógún jù lọ - Brasil acima de tudo.
Ilẹ̀ Bràsíl ju ohunkóhun mìíràn - Brasil acima de tudo.
Ọlọ́run ló jẹ wá lógún jù lọ - Deus acima de tudo.
gbẹ́ òṣèlú mi ni Orílẹ̀-èdè Bràsíl - Meu partido é o Brasil.
Jọ̀wọ́, lọ sí Orílẹ̀-èdè Kúbà - Jọ̀wọ́, lọ sí Orílẹ̀-èdè Kúbà - Por favor, vá para Cuba.
Mú ìṣekọ́múnístì kúrò lórí wa -  Afasta o comunsmo de nós, fora comunismo. 
Ilẹ̀ Bràsíl kì yóò run bi Orílẹ̀-èdè Fẹnẹsúélà - Brasil não será destruído como a nação da Venezuela.
Ilẹ̀ Bràsíl kì yóò di Fẹnẹsúélà kan - O Brasil não vai se tornar uma Venezuela.



Nenhum comentário:

Postar um comentário