Ohun tó máa ń fi ògo àti ipò-ọba àwọn ọ̀tọ̀kùlú hàn.
Algo que mostra glória e realeza da nobreza.
Àwọn ajẹtífù tó tan mọ́ ọn - Adjetivos relacionados: tó máa ń fi ìwà ọmọlúwàbí hàn ( que mostra bons modos), tó máa ń fi ìwà akin tàbí ìwà rere hàn (que mostra nobreza ou bondade), tó máa ń fi ògo àti iyì hàn (que mostra glória e dignidade), tó máa ń fi ògo àti ipò-ọba àwọn ọ̀tọ̀kùlú hàn (que mostra glória e realeza da nobreza), tó ní ìrísí ọlọ́lá ńlá (que tem aparência nobre, que tem uma aparência majestosa), tó jẹ́ ọlọ́yàyà, onínúure àti aláàánú ( que é cordial, magnânimo e compassivo), tó jẹ́ onínúure, tó láàánú tó sì ń gba tàwọn ẹlòmíràn rò (que é gentil, compassivo e atencioso com os outros), tó máa ń fi ọ̀pọ̀ yanturu, ọrọ̀ àti ògo hàn (que mostra abundância, riqueza e glória), tí ó pinminrin (requintado), tó jẹ́ onínúure (que é gentil), tó jẹ́ onínúure nígbà gbogbo (que é sempre gentil), tó lẹ́wà gan-na (muito bonito), tó yani lẹ́nu (surpreendente), tó ní ànímọ́ títayọ lọ́lá kan (que tem uma qualidade excepcional), tó ní àwọn ànímọ́ títayọ lọ́lá tí ìwọ kò ní (que tem qualidades extraordinárias que você não tem), tó jẹ́ àrímáleèlọ (que é magnífico), ṣèranwò (admirável, maravilhoso), tó yàtọ̀ pátápátá (completamente diferente), tó yàtọ̀ (diferente), tó ní ìtumọ̀ míì (que tem outro significado), alámì (notável, marcante), pẹtẹrí (notável, extraordinário), abàmi (extraordinário, notável, famoso, raro, marcante), alásakí (afortunado, famoso), títayọ, títayọlọ́lá (excelente, elevado), lókìkí (famoso, notório), gígalọ́lá (imenso, elevado, glamoroso), tó bùáyà, bùáyà, bùwáyà (incrível, extraordinário, inusitado, espantoso, admirável, inimaginável, inacreditável, maravilhoso, indizível), tó jẹ́ gbajúmọ̀ (que é popular), tó kàmàmà (incomum, maravilhoso), tí ó jọni lójú (notável), yọyẹ́ (extraordinário, incomum), àyinlógo (louvável, elogiável, glorioso, honroso), mímọ́ (limpo, puro, íntegro, sagrado), àtàtà (importante, poderoso, fino), dára jùlọ, dárajù (melhor, superior), tí ó ní ìrísí fífanimọ́ra kan (que tem uma aparência atraente), tí ìrísí rẹ̀ fani mọ́ra (cuja aparência é atraente, que sua aparência é atraente), tó pabanbarì (impressionante), tó wúni lórí (interessante), tó kàmàmà (incrível, lindo, maravilhoso), tó ń gbógo Ọlọ́run yọ (que reflete a glória de Deus), gíga (alto), gàgàrà, gagara (alto, comprido. Não é usado para pessoas), ńlá, tóbi (grande), tó jẹ́ alágbára (que é poderoso), ràbàtà, rabata (enorme, imenso), tó lẹ́wà (bonito, belo), dídára (bom, bonito), dáradára, dáadáa (bom, bonito), tó rẹwà (bonito), tí ó lẹ́wà ní Ìrísí (bela na aparência, vistosa), tí a ṣe lọ́ṣọ̀ọ́ (adornado). Àwọn ọ̀rọ̀-ìṣe tó tan mọ́ ọn - Verbos relacionados: tóbi (ser grande), lẹ́wà (ter beleza), rẹwà (ser ou estar bonita).
Nenhum comentário:
Postar um comentário